Anafilasisi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k →‎Awọ-ara: file fmt
Ìlà 85:
 
===Ṣiṣayẹwo nkan ti ara korira===
[[File:Allergy skin testing.JPG|thumb|atanpako|[[Ṣiṣayẹwo nkan ti awọ-ara korira]] ti a nṣe lori apa ọtun]]
[[Ṣiṣayẹwo nkan ti ara korira]] le ṣe iranlọwọ nipa mimọ ohun ti o nfaa. [[Ṣiṣayẹwo nkan ti awọ-ara korira]] (fun apẹẹrẹ [[Patch test (medicine)|patch testing]]) wa fun awọn ounjẹ kan ati oró.<ref name=His11/> Ṣiṣayẹwo ẹjẹ fun IgE ni pato le wulo lati jẹrisi wara-olomi, ẹyin, ẹpa, ẹpa igi ati awọn nkan ti ara korira ninu ẹja.<ref name=His11/> Ṣiṣayẹwo awọ-ara wa lati jẹrisi awọn nkan ti ara korira bii [[pẹnisilini]] ṣugbọn ko si fun awọn itọju miiran.<ref name=His11/> Iru anafilasisi ti ko niiṣe pẹlu ajẹsara ṣee mọ nipa itan ati ikọlu si nkan ti ara korira nikan, ti kii si ṣe nipa ayẹwo awọ-ara ati ayẹwo ẹjẹ.<ref name=His10/>
 
===Ayẹwo Dida aiṣan mọ yatọ ===