Anafilasisi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
comments
Ìlà 1:
<!-- {{Alafo-alaye aiṣan
| Orukọ = Anafilasisi
| Awọran = Angioedema2010.JPG
Ìlà 13:
| MeshID = D000707
}}
-->
 
<!--Itumọ, awọn aami aiṣan ati okunfa-->
'''Anafilasisi''' jẹ [[nkan ti ara korira si]] ti o l’ewu kan ti o ma nyara waye ti o si le fa iku.<ref name=Tint10>{{cite book |author=Tintinalli, Judith E. |title=Emergency Medicine: A Comprehensive Study Guide (Emergency Medicine (Tintinalli))|publisher=McGraw-Hill Companies |location=New York |year=2010 |pages=177–182 |isbn=0-07-148480-9 |oclc=|doi= |accessdate=}}</ref> O maa nni awọn abajade aami aiṣan ti o ni ara to njanijẹ gan-an, ọọfun ti o nwu, ati [[riru ẹjẹ]] ti o lọ silẹ ninu. Awọn okunfa ti o wọpọ julọ ni ki kokoro j’ẹni/t’ani, ounjẹ, ati oogun.
 
<!—Ayipada--Ayipada ti aiṣan ṣe ati ẹkọ nipa wọn, ṣiṣe ayẹwo, ati abojuto -->
Lori ipele [[Ayipada ti aiṣan ṣe okunfa ati ẹkọ nipa wọn|nipa ayipada ti aiṣan ṣe okunfa ati ẹkọ nipa wọn]], anafilasisi maa nwaye nipa jijọwọ awọn olulaja kan lati awọn oriṣi [[sẹẹli ẹjẹ funfun]] ti a taji yala nipa [[eto ajẹsara|ajẹsara] tabi awọn eto ti ko nii fiṣe pẹlu ajẹsara. A maa nṣe ayẹwo rẹ nipa awọn aami ti o nfarahan lọwọ lọwọ. Ọna itọju akọkọ ni nipa fi fun ni l’abẹrẹ [[efinifirini]], pẹlu awọn ọna miiran ti o nṣiṣẹ papọ pẹlu rẹ.
 
<!—Ẹko-- Ẹko nipa ajakalẹ arun ati itan -->
Ni gbogbo agbaye, awọn eniyan ti o to 0.05–2% ni o ni anafilasisi ni ipo kan igbe aiye wọn ati pe iye yii jọ wipe o npọ sii. Ọrọ naa wa lati ἀνά ana, [[Ede giriki|Giriki]] ''lodi si'', ati φύλαξις filasi,''idaabobo''.