Henry McNeal Turner: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "'''Henry McNeal Turner''' (February 1, 1834 – May 8, 1915) je olusoagutan-rere, oloselu, ati bisoobu apaguusu akoko fun African Metho..."
 
No edit summary
Ìlà 1:
[[File:Henry McNeil Turner.jpg|thumb|right|Henry McNeal Turner ninu aso oniwaasu]]
'''Henry McNeal Turner''' (February 1, 1834 – May 8, 1915) je olusoagutan-rere, [[politician|oloselu]], ati [[bishop|bisoobu]] apaguusu akoko fun [[African Methodist Episcopal Church|Ijo Metodisti Olusoagutan-rere ara Afrika]]; o je asiwaju ni ipinle Georgia nipa isakojo awon ijo olominira awon alawodudu ni Amerika leyin opin [[American Civil War|Ogun Abele ara Amerika]].<ref name=amer>{{Cite Americana|wstitle=Turner, Henry McNeal|year=1920}}</ref> O je bibisaye ni ipinle South Carolina, Turner ko lati mooko mooka ko to di oniwaasu ijo Metodisti. O darapo mo Ijo AME ni [[St. Louis, Missouri]] ni odun 1858, nibi to ti di olusoagutan-rere; leyin re o tun se oniwaasu ni [[Baltimore, Maryland]] ati [[Washington, DC.]]