Wọlé Sóyinká: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Legobot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q41488 (translate me)
kNo edit summary
Ìlà 15:
| awards = {{awd|[[Nobel Prize in Literature]]|1986}}
}}
'''Oluwole Soyinka''' (ojoibi 13 July 1934) je ojogbon (Professor) ninu [[Imo Lítíréṣọ̀]] (literature), alakosile ere ori itage (Playwrightplaywright) ati akewi (poet). Omo orile ede Naijiria ni Ṣoyinka je, lati eya Yoruba. Soyinka gba [[Ebun Nobel]] ni odun 1986 fun ise owo re lori igbega imo ikowe.
 
Won bi Soyinka ni ilu [[Abeokuta]], Leyin ti opa ri eko re ni irile ede Nigeria ati UK, o se ise pelu tiata Royal Court ni ilu Londonu (London). O te siwaju lati ko awon ere ni orile ede mejeeji ni tiata ato ori ero asoro magbesi. O ko ipa Pataki ni itan iselu and akitiyan fun ominira lati owo Great Britain.
 
 
Ìlà 25:
{{Nobel Prize in Literature}}
{{igbesiaye|1934||Soyinka, Wole}}
 
 
[[Ẹ̀ka:Àwọn ẹlẹ́bùn Nobel nínú Lítíréṣọ̀]]