Brasil: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k →‎Itokasi: removed deleted template, removed: {{Link FA|af}} (10) using AWB (11720)
Ìlà 143:
Ori ile ti a mo loni bi Brasil je gbigbesele latowo [[Portugal]] ni April 1500, nigba ti oko-ojuomi lati Portugal ti [[Pedro Álvares Cabral]] dari gunle.<ref name="Boxer, p. 98">Boxer, p.&nbsp;98.</ref> Awon wonyi pade awon are ibe ti ede opo won je ti [[Tupi–Guarani]]. Botilejepe ilu abudo akoko je didasile ni 1532, imusin ko bere titi to fi di 1534, nigbati Oba [[Dom (title)|Dom]] [[John III of Portugal|João&nbsp;3k]] ile Portugal pin ibe si ile basorun ajogun mejila.<ref>Boxer, pp.&nbsp;100–101.</ref><ref name="Skidmore, p.&nbsp;27">Skidmore, p.&nbsp;27.</ref>
 
[[File:Oscar Pereira da Silva - Desembarque de Pedro Álvares Cabral em Porto Seguro em 1500 by Oscar Pereira da Silva (1865–1939).jpg|thumb|left|Ìgúnlẹ̀ [[Pedro Álvares Cabral]] ní [[Porto Seguro]] ní [[1500]]. Àwòrán tí Oscar Pereira da Silva yà (1904).]]
 
Eto yi ko ni yori i rere rara, bosi ti di odun 1549 oba yan [[Governor-General|Gomina Agba]] kan lati samojuto gbogbo ibe.<ref name="Skidmore, p.&nbsp;27"/><ref>Boxer, p.&nbsp;101.</ref> Awon eya abinibi bi melo kan je fifamora,<ref>Boxer, p.&nbsp;108</ref> awon miran je kikoleru tabi piparun ninu ogun tabi pelu awon arun ti awon ara Europe ko ran won ti ara won ko ni ajesara si.<ref name="Boxer, p.&nbsp;102">Boxer, p.&nbsp;102.</ref><ref>Skidmore, pp.&nbsp;30, 32.</ref> Nigba ti yio fi di arin orundun 16k, suga ti di oja okere pataki fun Brasil<ref name="Boxer, p.&nbsp;100"/><ref>Skidmore, p.&nbsp;36.</ref> nitori awon ara Portugal yi ko opo eru wa lati Afrika<ref>Boxer, p.&nbsp;110</ref><ref>Skidmore, p.&nbsp;34.</ref> lati fi won sise fun [[demand (economics)|ibere oja]] suga to unpo si kariaye.<ref name="Boxer, p.&nbsp;102"/><ref>Skidmore, pp.&nbsp;32–33.</ref>
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Brasil"