Springbok: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
kNo edit summary
No edit summary
Ìlà 40:
'''springbok''' jẹ́ alábọ́dé [[Ẹtu|ẹtu]] tí wọ́n ń rí ní gúúsù áfríkà àti gúúsù-wọ̀orùn áfríkà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ ''Antidorcas'', Jẹ́mánì onímọ̀ ẹranko [[Eberhard August Wilhelm von Zimmermann]] ló kọ́kọ́ ṣe àpèjuwe ọmọ ẹbí Bovidae yìí ní ọdún 1780. Ẹ̀yà méta ẹranko yìí tí di mímọ̀. Ẹtu èyí tẹ́ẹ́rẹ́ tẹ́sẹrẹ̀ gùn, springbok gùn tó 71 sí 86 cm (28 to 34 in) ní ìwọ̀n èjìká àti ìwúwosí láti 27 sí 42 kg (60 sí 93 lb). Akọ àti abo rẹ̀ ní ìho méjì tí ó yípo sẹ́yìn. Springbok yìí ma ń ní ojú funfun, ìlà dúdú láti ojú dé ẹnu, àwọ̀ pako fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ tí ó pupa díẹ̀ láti apá iwájú dé íbubu ìha ìdí rẹ̀.
 
Ara rẹ̀ ma ń yá gágá ní àfẹ̀mọ́jú àti àṣàalẹ́, springbok fọ́ọ̀mù àdàlù ìbálòpọ̀. Ní ìgàkan sẹ́yìn, springbok ti aṣálẹ Kalahari àti ti Karoo ma ń kóra wonwọn kọjá ní igbóẹgàn, lèyí tí à ń pè ní '' trekbokken''
 
 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Springbok"