6,104
edits
(Created by translating the page "Australopithecus africanus") |
(Created by translating the page "Australopithecus africanus") |
||
'''''Australopithecus africanus''''' jẹ́ èya australopithecines ìgbàanìelérò ayé àtijọ́ tí ó jẹ́ àkọ́kọ́ ẹ̀yà
apá gúúsù <nowiki>[[Africa|Áfíríkà]]</nowiki> nìkan: Taung (1924), Sterkfontein (1935), Makapansgat (1948) àti Gladysvale (1992).<ref name="info">{{Àdàkọ:Cite web|url=http://www.archaeologyinfo.com/australopithecusafricanus.htm|title=Australopithecus africanus|work=archaeologyinfo.com}}</ref>
=== Ọmọ Taung ===
[[Fáìlì:Australopithecus_africanus_-_Cast_of_taung_child.jpg|thumb|250x250px| Àgbẹ́dẹ ọmo Taung]]
Ramond Dart, tí ó jẹ́ olórí ẹ̀ka ètò ìpín ara ènìyàn ti University of the Witwatersrand ní Johasnnesburg, gúúsù <nowiki>[[Africa|Áfíríkà]]</nowiki> nifẹ́ sí tàtijọ́ tí wọ́n rí ní bi òkúta ẹfun ní Taung legḅe Kimberley, gúúsù Áfíríkà ní ọdún 1924.<ref>{{Àdàkọ:Cite web|url=http://www.press.uchicago.edu/Misc/Chicago/284158_brain.html|title=Raymond Dart and our African origins|work=uchicago.edu}}</ref>[[#cite_note-3|<span class="mw-reflink-text"><nowiki>[3]</nowiki></span>]]<ref>{{Àdàkọ:Cite web|url=http://www.talkorigins.org/faqs/homs/rdart.html|title=Biographies: Raymond Dart|work=talkorigins.org}}</ref> Èyí tí ó jọni lójú jú ní agbárí bí ti ìnànkí tí ó dàbí ti ènìyàn tí ibi ojú, eyín rẹ̀ àti èyí tí ó ṣe pàtàkì jùlọ ni ihò tí ó wà ní ìsàlẹ̀ agbárí lókè ọ̀pá ẹ̀yín ẹ̀ (tí wọ́n ń pè ní foramen magnum); bí ó ṣe rí dàbí tí ènìyàn bá dúró leyí tófihan wípé ó ṣeésẹ kí homid-si-homid akọ́dièyàn èèyàn yí lẹ́sè méjì fún ìrìn yàtọ̀ sí ẹlẹ́sè́ merin. Dart fún àwòṣe àpẹ̣rẹ ní tí à ń pè ní Australopithecus africanus; ó tún pèé ní "Ọmọ Taung".
Eleyi jẹ́ àkọ́kọ́ tí wọ́n máa pe hominin ní "ìnànkí", fún ìdí èyí wọ́n pe ènìyàn ní ìran ìnànkí.<span class="cx-segment" data-segmentid="131"></span>
== See also ==
|