Springbok: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 43:
 
==Àkójọ àti ìtànkálẹ̀==
[[File:Lightmatter gerenuk.jpg|thumb|rightleft| [[gerenuk]], àwọn ẹ̀yà tí springbok lè jọ]]
Springbok jẹ́ ìkangbọ̀n ní ìdílé Antidorcas tí wọ́n sì gbe sí ẹbí Bovidae.<ref name =MSW3>{{MSW3 Artiodactyla | id = 14200530 | page = 678}}</ref> Eberhard August Wilhelm Zimmermann von onímọ̀ ẹranko ọmọ orílẹ̀ èdè Jemaní ni ó kọ́kọ́ ṣe àpèjúwe ẹranko yìí ní ọdún 1780. Zimmermann kó ìdílé Antilope (blackbuck) sí springbok.<ref>{{cite book|last1=von Zimmermann|first1=E.A.W.|authorlink=Eberhard August Wilhelm von Zimmermann|title=Geographische Geschichte des Menschen, und der Allgemein Verbreiteten Vierfüssigen Thiere: Nebst Einer Hieher Gehörigen Zoologischen Weltcharte|date=1780|publisher=In der Weygandschen Buchhandlung|location=Leipzig, Germany|page=427|language=German}} {{open access}}</ref>
Ní ọdún 1845, Carl Jakob Sundevall onímọ̀ ẹranko ọmọ orílẹ̀ èdè Sweden ló kó springbok Antidorcas,ìdílé tiẹ̀..<ref name="Sundevall">{{cite journal|last1=Sundevall|first1=C.J.|authorlink=Carl Jakob Sundevall|title=Melhodisk öfversigt af Idislande djuren, Linnés Pecora|journal=Kungl. Svenska Vetenskapsakademiens Handlingar|year=1844|page=271|url=http://www.biodiversitylibrary.org/item/182326#page/795/mode/1up|series=3|language=Swedish}} {{open access}}</ref>
Ìlà 70:
}}}}
 
==Àwọn ìtọ́kasí==
==Ìtọ́kasí==
{{reflist}}
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Springbok"