Jacob Zuma: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 56 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q57282 (translate me)
page fixing and expansion
Ìlà 35:
}}
 
'''Jacob Zuma''' jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Gúúsù Áfíríkà tẹ́lẹ́.<ref name=dismiss>{{cite news |last=Zigomo |first=Muchena |newspaper=The China Post | url=http://www.chinapost.com.tw/international/africa/2008/09/13/174479/S.-African.htm |title=S. African judge dismisses Zuma corruption case |agency=Reuters |date=13 September 2008 |accessdate=27 November 2013}}</ref><ref>{{cite news|url=http://news.bbc.co.uk/2/hi/africa/7612233.stm |title=news.bbc.co.uk, SA court rejects Zuma graft case |publisher=BBC News |date=12 September 2008 |accessdate=15 September 2010}}</ref><ref>{{cite news|author=James Orr and agencies |url=http://www.guardian.co.uk/world/2008/sep/12/southafrica |title=South African court clears way for Zuma presidential run |work=The Guardian |location=UK |date= 12 September 2008|accessdate=15 September 2010 }}</ref> Ó wolé ní osù kejìlá odún 2006 gégé bí alága fún egbé [[African National Congress]] (ANC) ní [[Guusu Afrika]].<ref name=head-anc>{{cite news|last=Conway-Smith|first=Erin|title=Jacob Zuma re-elected as head of ANC|url=http://www.telegraph.co.uk/news/worldnews/africaandindianocean/southafrica/9753579/Jacob-Zuma-re-elected-as-head-of-ANC.html|accessdate=27 November 2013|newspaper=The Telegraph|date=18 December 2012}}</ref> Olóyè ni ó jé ní àárín àwọn Zulu. Ní ọjọ́ karùn-ún osù kìíní odún 2007, ó fé Nompumeledo Ntuli, ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí ìyàwó rẹ̀ karin lẹ́yìn ìgbà tí ó ti bí ọmọ méjì fún un. 1943 ni wọ́n bí Jacob Zuma. Ìyàwó rẹ̀ kan tí orúkọ rẹ̀ ní jẹ́ Kate pa ara rẹ̀ ní ọdúin 2000 nítorí pé ó ní ìgbéyàwó tí àwọn ti ṣe fún ọfún mẹ́rìnlélógún kò rọgbọ. Ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógójì ni Kate nígbà náà: Ní ọdún 2005 ni President thabo Mbaki yọ Zuma kúrò ní ipò igbákejì àrẹ nítorí ìwà ìbàjẹ́.<ref>{{cite news|url=http://news.iafrica.com/specialreport/armsdeal_focus/265106.htm|title=Ngcuka accused of 'derailing justice'|date=24 August 2003|accessdate=7 April 2009}}</ref> Ní ọdún 2006 ni wón fi ẹ̀sùn kan Zuma pé ó fi ipá bá obìnrin kan tí ó ní HIV lo pò. Kò jẹ̀bi ẹ̀sùn náà.
'''Jacob Zuma'''
Òun ó wolé ní osù kejìlá odún 2006 gégé bí alága fún egbé [[African National Congress]] (ANC) ní [[Guusu Afrika]]. Olóyè ni ó jé ní àárín àwon Zulu. Ní ojó karùn-ún osù kìíní odún 2007, ó fé Nompumeledo Ntuli, omo odún métàlélógbòn gégé bí ìyàwó rè krin léyìn ìgbà tí ó ti bí omo méjì fún un. 1943 ni wón bí Jacob Zuma. Ìyàwó rè kan tí orúko rè n jé Kate pa ara rè ní odúin 2000 nítorí pé ó ní ìgbéyàwó tí àwon ti se fún ofún mérìnlélógún kò rogbo. Omo odún mérìnlélógójì ni Kate nígbà náà: Ní odún 2005 ni President thabo Mbaki yo Zuma kúrò ní ipò igbákejì àre nítorí ìwà ìbàjé. Ní odún 2006 ni wón fi èsùn kan Zuma pé ó fi ipá bá obìnrin kan tí ó ní HIV lo pò. Kò jèbi èsùn náà.
 
==àwọn ìtọ́kasí==
 
{{ekunrere}}
==Itokasi==
{{reflist}}
{{SAPresidents}}
 
 
{{ekunrere}}
{{BD|1942||Zuma Jacob}}
[[Ẹ̀ka:àwọn ọjọ́ìbí ní 1942]]
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Jacob_Zuma"