Wikipedia:Civility: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created by translating the page "Wikipedia:Civility"
 
No edit summary
 
Ìlà 1:
{{ìpinu|WP:SHORT}}
'''Ìwà ìrẹ̀lẹ̀ '''jẹ́ ara ìṣe wa ní Wikipedia, ó sì wà lára òpó marún tí ó gbé Wikipedia ró. Ètò ìmúlò yìí ṣe àlàyé nípa bí a ṣe fẹ́ kí oníṣẹ́ ṣe máa dojú kọ ìṣòro tí wọ́n bá yọjú. Níwọ̀nba, àwọn olóòtú gbọ́dọ̀ ḿa bọ̀wọ̀ fún ara wọn. Kí wọ́n máa gbìyànjú lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìwé-ìmọ ọ̀fẹ́ kí wọ́n sì máa hu ìwà tó dára, pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀, ìwà tútú, pàápàá jùlọ tí ìtàkùrọ́sọ̀ bá ń gbóná jinjin.
{{shortcut|WP:Ìrẹ̀lẹ̀|WP:I}}
[[Fáìlì:Jimmy_Carter_greets_residents_of_South_Bronx,_New_York_-_NARA_-_176402.tif|rightcenter|thumb|200x200px|Ìrẹ̀lẹ̀, ìbọ̀wọ̀ fún ara wa ṣ pàtàkì]]
 
'''Ìwà ìrẹ̀lẹ̀ '''jẹ́ ara ìṣe wa ní Wikipedia, ó sì wà lára òpó marún tí ó gbé Wikipedia ró. Ètò ìmúlò yìí ṣe àlàyé nípa bí a ṣe fẹ́ kí oníṣẹ́ ṣe máa dojú kọ ìṣòro tí wọ́n bá yọjú. Níwọ̀nba, àwọn olóòtú gbọ́dọ̀ ḿa bọ̀wọ̀ fún ara wọn. Kí wọ́n máa gbìyànjú lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìwé-ìmọ ọ̀fẹ́ kí wọ́n sì máa hu ìwà tó dára, pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀, ìwà tútú, pàápàá jùlọ tí ìtàkùrọ́sọ̀ bá ń gbóná jinjin. Ìwà ìrẹ̀lẹ̀ tí Wikipedia fẹ́ níṣe pẹ̀lú gbogbo àwọn olóòtú nígbà tí wọ́n bá ń bá ara wọn sọ̀rọ̀ ní Wikipedia, pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ní ojú [[ewé ọ̀rọ̀ oníṣẹ́]] àtí [[ojú ewé ọ̀rọ̀ àyọkà]] àti gbogbo ìjíròrò pèlú tàbí nípa àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ tí ó jẹ́ olùkọ Wikipedia.
 
 
Ìwà ìrẹ̀lẹ̀ tí Wikipedia fẹ́ níṣe pẹ̀lú gbogbo àwọn olóòtú nígbà tí wọ́n bá ń bá ara wọn sọ̀rọ̀ ní Wikipedia, pẹ̀lú ọ̀rọ̀ ní ojú [[ewé ọ̀rọ̀ oníṣẹ́]] àtí [[ojú ewé ọ̀rọ̀ àyọkà]] àti gbogbo ìjíròrò pèlú tàbí nípa àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ tí ó jẹ́ olùkọ Wikipedia.
 
 
 
== Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀ ==
[[Fáìlì:Jimmy_Carter_greets_residents_of_South_Bronx,_New_York_-_NARA_-_176402.tif|right|thumb|200x200px|Ìrẹ̀lẹ̀, ìbọ̀wọ̀ fún ara wa ṣ pàtàkì]]
 
 
Differences of opinion are inevitable in a collaborative project. When discussing these differences some editors can seem unnecessarily harsh, while simply trying to be forthright. Other editors may seem oversensitive when their views are challenged. Faceless written words on talk pages and in edit summaries do not fully transmit the nuances of verbal conversation, sometimes leading to misinterpretation of an editor's comments. An uncivil remark can escalate spirited discussion into a personal argument that no longer focuses objectively on the problem at hand. Such exchanges waste our efforts and undermine a positive, productive working environment. Resolve differences of opinion through civil discussion; disagree without being disagreeable. Discussion of other editors should be limited to polite discourse about their actions.
 
[[Ẹ̀ka:Àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ Wikipedia]]