Paul Émile Chabas: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 14:
| training =
| movement =
| works = September Morn (1912)}}
 
'''Paul Émile Chabas''' (Ọjọ́ keje Oṣù kẹta Ọdún 1869 – Ọjọ́ kẹwá Oṣù karún Ọdún1937) jẹ́ olùyàwòrán ará Faransé àti ọmọ ẹgbẹ́  Académie des Beaux-Arts.
Ìlà 20:
== Ìgbésíayé ==
 
[[Fáìlì:Paul_Chabas_September_Morn_The_Metropolitan_Museum_of_Art.jpg|thumb|288x288px240px|Paul Chabas's ''September Morn'', 1912, epo lórí igbokun, Metropolitan Museum of Art, [[New York]] ]]
Wọ́n bíi ní Nantes, ó sì kọ iṣẹ́ ọnà lábẹ́ William-Adolphe àti Tony Robert-Fleury.
Ó kọ́kọ́ ṣe àfihàn iṣẹ́ rẹ̀ ní Salon ní ọdún 1890. Chabas gba ẹbùn Prix National ní ọdún 1899 ní Paris Salon pẹ̀lú ''Joyeux Ébats'' rẹ̀.<ref name="obit"><cite class="citation news">[https://www.newspapers.com/clip/1024689/paul_chabas_obituary_1937/? ""September Morn" Creator Dies After Long Illness"]. </cite></ref> Wọ́n fún ní ẹ̀bùn góòlú ní Exposition Universelle of 1900 àti ní ọdun 1912 tí ó gba Médaille d’honneur.<ref name="minibio"><cite class="citation news">[https://www.newspapers.com/clip/1036318/paul_chabas_thumbnail_bio_1937/ "Paul Chabas bio"]. </cite></ref> Àwọn ẹka ọnà tí ó fẹ́ràn ni yíya ọoṃdébìrin tí ó wà ní ìhòho. Wọ́n gbàá ní ọ̀gá ní yiya ìhòhò ní gbogbo ilẹ̀ Yúróòpù.<ref name="obit"><cite class="citation news">[https://www.newspapers.com/clip/1024689/paul_chabas_obituary_1937/? ""September Morn" Creator Dies After Long Illness"]. </cite></ref>