Eucharia Oluchi Nwaichi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 1:
 
'''Eucharia Oluchi Nwaichi''' jẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ ẹ̀yà [[Biokẹ́mísìrìBiochemistry]], tí ó ní se pẹ̀lú àyíká. Ó tún jẹ́ onímọ̀n [[Tọsikọ́lọ́jì]]Toxicology. Ó gba àmì ẹ̀yẹ
tí àwon olóyìnbó n pè ní ''L'Oreal-UNESCO Awards'' fún àwon obìnrin ní odún 2013 fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí " ìjìnlẹ̀ ṣàyẹnsí ojutú sí àyík á èérí. Ó sì jẹ́ ikeji ọmọ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] lati ẹ̀yà [[ígbò]] lóbìnrin tí ó gba àmì ẹ̀yẹ ''L'Oreal-UNESCO Awards'' fún àwon obìnrin nínú ìmọ̀ [[Science|Síáyẹ́nsì]].<Ref>{{cite web|url=http://saharareporters.com/2013/04/01/nigerian-shines-unesco-science-laureate-wins-100000-nan|title=Nigerian Shines UNESCO Science Laureate wins-$100,000-NAN|work=Sahara Reporters|accessdate=November 13, 2015}}</ref><Ref>{{cite web|url=http://en.starafrica.com/education/eucharia-oluchi-nwaichi-port-harcourt-studies-how-to-remove-arsenic-and-copper-from-polluted-soil.html|title=Eucharia Oluchi Nwaichi Port harcourt studies how to remove arsenic and copper from polluted soil|work=Star Africa|accessdate=November 13, 2015}}</ref>