Eucharia Oluchi Nwaichi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
Ìlà 4:
 
==Ìgbésí ayé==
A bí ọ̀mọ̀wé Nwaichi si Ìpínlẹ̀ Ábíá sí idílé Ọ̀gbẹ́ Donatus Nwaichi ti ìlú Ábíá. Ó ní báṣẹ́lọ̀ (B.SC) ati másíta Síáyẹ́nsì (B.Sc) pẹ̀lú dókítọ́réti nínú ìmọ̀ [[Biokẹ́mísìrì]]Biochemistry lati Yunifásítì ìlú Port hacourt níbi tí ó tí padà di olùkọ́ ìmọ̀ Biokẹ́mísìrì . kí ó tó darapọ̀ mọ́ Yunifásítì ìlú Port hacourt, Ó ṣiṣẹ́ ilẹ́ "Shell Oil" fún odún kan péré. Iṣẹ́ rẹ̀ tó dáyatọ̀ nínú ìmọ̀ Síáyẹ́nsì ni ó jẹ́ kì ó gba àmì ẹ̀yẹ ti ''L'Oreal-UNESCO ni odún 2013.<Ref>{{cite web|url=http://www.vanguardngr.com/2013/03/2-nigerian-scientists-bag-unesco-loreal-2013-award/|title=Two Nigerian Scientists bag UNESCO LOreal 2013 award|work=Vanguard News|accessdate=November 13, 2015}}</ref><Ref>{{cite web|url=http://sunnewsonline.com/new/nigerian-women-who-cracked-science/|title=Nigerian Women whocracked science|work=The Sun Newspaper|accessdate=November 13, 2015}}</ref>
 
==Àwọn ìtọ́kasí==
{{Reflist}}