King's College: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 1:
{{Infobox school
| name = King's College
| image = Kings College, Lagos1.jpg
| alt =
| caption = Kings College, Lagos
| motto = Spero Lucem
| streetaddress = Ojúlé kẹta ní Catholic Mission
Ìlà 34:
| footnotes =
}}
[[File:Kings College, Lagos1.jpg|thumb|left|Kings College, Lagos1]]
'''King's College, Lagos''' jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndìrì ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Wọ́n dáa síle\̣ ní ọjọ́ ogún oṣù kẹsán ọdún 1909 pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ́ mẹ́wá ní Erékùṣù Èkó, lẹ́gbẹ́ Tafawa Balewa Square. Ìlé ẹ̀kọ́ yìí maa ń gba ọkùnrin nìkan, bíótilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn obìnrin díẹ̀díẹ̀ wà lára wọn (A Level) àwọn akẹ́kọ HSC kí wọ́n tó dá  Queen's College Lagos, sílẹ̀ tí a mọ̀ sí kọ́lẹ́jì obìrin. Báyìí, àwọn akẹ́kọ náà maa ń bá àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn ṣe ìdánwò  West African School-Leaving Certificate àti National Examinations Council.