Akọ ibà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
replaced a word with Yoruba-inexistent letter "ṣ̀" with the closest similar word (hopefully a good guess – feel free to fix if not!)
k fixed erroneous duplicate-accented characters
Ìlà 18:
 
<!--Cause and diagnosis-->
Níwọ́pọ̀, ààrùn yii maa ń múni nípa ìgéjẹ lọ́wọ́ aabo ẹ̀fọn tí ó ní àkóràn ''[[Anọfẹ́lísì]]''.<!-- <ref name=WHO2014/> --> Ìgéjẹ yii maa ń mú àwọn kòkòrò àkóràn láti itọ́ ẹ̀fọn sínu [[ibi ìgbẹ́jẹ̀ kiri ara|ẹ̀jẹ̀]]ènìyàn.<ref name=WHO2014/> Kòkòrò àkóràn yíì yóò rìn kiri lọ inú ẹ̀dọ̀ níbi tí wọn a ti dàgbà láti pọ̀si.<!-- <ref name=EBMED2014/>--> Ẹ̀yà máàrùn ''Kòkòrò àṣòkunfà'' lè ranni kí ènìyàn tán kiri.<ref name=EBMED2014/> Ọ̀̀pọ̀̀Ọ̀pọ̀ ikú ni o ń wáyé nípa ''[[Kòkòrò àṣòkunfà falciparum|P.&nbsp;falciparum]]'' pẹ̀lú ''[[Plasmodium vivax|P.&nbsp;vivax]]'', ''[[Plasmodium ovale|P.&nbsp;ovale]]'', àti ''[[Plasmodium malariae|P.&nbsp;malariae]]'' maa ń sábà fa ibà tí kò lera.<ref name=WHO2014/><ref name=EBMED2014/> Àwọn ẹ̀yà ''[[kòkòrò àṣòkunfà knowlesi|P.&nbsp;knowlesi]]'' kìí sábà fa ààrùn lára àwọn ènìyàn.<ref name=WHO2014/> A sábà maa ń ṣàwarí ibà nípa àyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀ nípa lílo ohun elò awo kòkòrò [[fíìmù ẹ̀jẹ̀]], tàbí pẹ̀lú ìdálórí [[ántígínì]]- [[Àwọn àyẹ̀wò ìṣawarí ántígínì ẹ̀fọn|àyẹ̀wò ìṣawarí kíákíá]].<ref name=EBMED2014/> Àwọn ìlànà lílo [[polymerase ìtàgìjí àṣokunfà]] láti ṣàwarí kòkòrò náà [[DNA]] ti di àgbékalẹ̀, ṣùgbọ́n a kí sábà lò ní àwọn agbègbè tí ibà ti [[Endemic (epidemiology)|wọ́pọ̀]] nítorí ọ̀wọ́n àti ipá gbòòrò líle wọn.<ref name="Nadjm 2012">{{Cite journal |author=Nadjm B, Behrens RH |title=Malaria: An update for physicians |journal=Infectious Disease Clinics of North America |year=2012 |volume=26 |issue=2 |pages=243–59 |pmid=22632637 |doi=10.1016/j.idc.2012.03.010}}</ref>
 
<!--Prevention and treatment-->
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Akọ_ibà"