Àwọn Ogun Napoleon: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
removed deleted template
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 76:
'''OGUN NAPOLEON'''
 
Ìjàgbara tí a nń pe ní revolution tí ó selèṣẹlẹ̀ ní [[France]] jéjẹ́ kí Fance ní òtáọ̀tá púpòpúpọ̀ ní ìlú Òyìnbó. Èyí ni ó sì fa ogun tí ó selèṣẹlẹ̀ láàrin 1792 sí 1815 tí ó férèfẹ́rẹ̀ máa dáwó dúró.
Ní àsìkò ogun yìí, ilèilẹ̀ [[Faransé]] ní ÒgágunỌ̀gágun kan tí orúkoorúkọ rèrẹ̀ nń jéjẹ́ [[Napoleon Bonaparte]]. ÒpòlopòỌ̀pọ̀lọpọ̀ ogun ni Napoleon séṣẹ́. LéyìnLẹ́yìn ìgbà tí ó ti ségunṣẹ́gun wònyíwọ̀nyí, ó sosọ ara rèrẹ̀ di emperor ní 1804. LéyìnLẹ́yìn ìgbà tí ó ti di olórí ilèilẹ̀ Faransé tán ó tún féfẹ́ di olórí gbogbo ìlú Òyìnbó. Nítorí ìdí èyí, gbogbo ìlú Òyìnbó ni ó wá gbógun tì í kí àbá rèrẹ̀ yìí má baà lè seṣẹ.
ÀwonÀwọn ìlú tó nńilèilẹ̀ Faransé jà nígbà náà ni Austria, Prussia, Russia, Britain àti Spain. ÀwonÀwọn omoọmọ ogun ilèilẹ̀ Faransé pòpọ̀ gan-an ni. WónWọ́n séṣẹ́ òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun. ÀwónÀwọ́n eléyìí tí ó seṣe pàtàkì jù ni ogun Marengo àti Hohenlinden ní 1800 ti Austerlitz ní 1805 àti ti Jena ní 1806. ÌségunÌṣẹ́gun yìí fún Napoleon ní agbara láti máa darí ilèilẹ̀ ìlú Òyìnbó.
SùgbónṢùgbọ́n sá, àwonàwọn ológun ojú omi ilèilẹ̀ GèésìGẹ̀ẹ́sì lágbára gan-an ni. ÒgáỌ̀gá wonwọn ni Lord Nelson. WónWọ́n ségunṣẹ́gun omoọmọ ogun ilèilẹ̀ Faransé ní ogun Nile ní 1798. Èyí ni kò jéjẹ́ilèilẹ̀ Faranse rí ilèilẹ̀ GèésìGẹ̀ẹ́sì gbà.
Inú bí Napoleon, kò jéjẹ́àwonàwọn ojaọja ilèilẹ̀ GèésìGẹ̀ẹ́sì kojákọjáàwonàwọn ilèilẹ̀ ìlú Òyìnbó mìíràn mómọ́. Àìrí ojàọjà ilèilẹ̀ GèésìGẹ̀ẹ́sì yìí dá wàhálà sílèsílẹ̀ fún àwonàwọn ilèilẹ̀ yòókù. Spain yarí. Ó gbógun ti Napoleon. IlèIlẹ̀ GèésìGẹ̀ẹ́sì lolọ ran Spain lówólọ́wọ́. EniẸni tí ó saájúṣaájú omoọmọ ogun ilèilẹ̀ GèésìGẹ̀ẹ́sì lolọ ni Arthur Wellesley tí ó padà wá nń jéjẹ́ Duke of Wellington. WónWọ́n ségunṣẹ́gun àwonàwọn ìja kan. Ó seṣe, Russia dara pòpọ̀ mómọ́ ilèilẹ̀ GèésìGẹ̀ẹ́sì àti Spain. Napoleon sígunṣígun lolọ sí Russia sùgbónṣùgbọ́n gbogbo omoọmọ ogun rèrẹ̀ ni ó kí sí òhúnọ̀hún. Torí gbogbo ìsègunìṣẹ̀gun wònyíwọ̀nyí, Bsritain, Prussia, Sweden, Russia àti Astria para pòpọ̀ láti bá ilèilẹ̀ Faranse jà. WónWọ́n ségunṣẹ́gun. WónWọ́n wowọ Paris ní 1814. Ní 1815, wónwọ́n lé Napoleon lolọ sí Elba. Ó sá àsálà ó sì wá bá omoọmọ ogun Britain àti Prussia jà ni Waterloo. WónWọ́n ségunṣẹ́gun Napoleon wónwọ́n wá lé e lolọ sí St Helena.