|
|
}}
'''Bahrain''' tabi '''Ile-Oba Bahrain''' Ní odúnọdún 1995, àwonàwọn ènìyàn tí ó ń gbé orílèorílẹ̀-èdè yìí tó egbèrúnẹgbẹ̀rún lónàlọ́nà èédégbètaẹ̀ẹ́dégbẹ̀ta àti ààbòààbọ̀ (555,000). Èdè Lárúbááwá (Arabic) ni èdè ìjobaìjọba ní ibèibẹ̀. ÀwonÀwọn èdè kan tún wà tí wónwọ́n ń sosọ níbèníbẹ̀. ÀwonÀwọn èdè náà ni fáàsì (farsi) tí àwonàwọn tí ó ń sosọ ó egbèrúnẹgbẹ̀rún méjìdínláàádótaméjìdínláàádọ́ta (48, 000); Úúdù (Urdu) tí àwonàwọn tí ó ń sosọ óọ́ tó egbèrúnẹgbẹ̀rún lónàlọ́nà ogún (20,000) àti àwonàwọn èdè fílípíìnì (Phillipine) mìíràn tí àwonàwọn tí ó ń sosọ wónwọ́n tó egbèrúnẹgbẹ̀rún lónàlọ́nà ogún (20,000). Èdè GèésìGẹ̀ẹ́sì ti ń gbayì ní ilèilẹ̀ yìí sí i gégégẹ́gẹ́ bí èdè òwò àti èdè ìseìṣe àbèwòàbẹ̀wò sí ìlú (tourism).
|