Benito Mussolini: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 104 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q23559 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 31:
| successor3 =
|}}
'''Benito Mussolini''' je oloselu omo orile-ede [[Italia]]. WónWọ́n bí Benito ní 1883. Ó kú ní 1945. Òun ni ó dá Fasisti sílèsílẹ̀ ní Italy. Òun ni ó darí Italy ní 1922 sí 1943. Agbára ni ó fi nń darí ilèilẹ̀ náà (a dictator). It Duce tí ó dúró fún olórí (the leader) ni àwonàwọn èyìn rèrẹ̀ máa nń pè é. Mussolini àti ìgbìmòìgbìmọ̀ Fascist Party ni wonwọn jojọ nń darí Italy. WonWọn kò gba alátakò kankan láyè.
 
GégéGẹ́gẹ́ bí ajàfún-mèkúnnù (socialist) ni Mussohni seṣe wowọ òsèlúòṣèlú. Ó jéjẹ́ olóòtu ìwé-ìróyìn kan tí ó nń jéjẹ́ ní Avanti sùgbónṣùgbọ́n ní 1914, ó dá ìwé-ìroyìn tirètirẹ̀ sílèsílẹ̀. Ó pè é ní IL Popolo d’Italia. Ní odúnọdún 1921 ni ó dá egbéẹgbẹ́ òsèlúòṣèlú Fascist sile. Èrò tí ó ní nípa dídá egbéẹgbẹ́ òsèlúòsẹ̀lú yìí sílèsílẹ̀ ni láti lè tún Italy kókọ́ kí ó sì sosọ óọ́ di ìlú tí ó lágbára. LéyìnLẹ́yìn ìgbà tí àwonàwọn Fascist rìn lolọ sí Róòmù ní 1922 (‘Fascist March on Rome’), ObaỌba Victor Emmanuel III pe Mussoline láti wá gbé ìjobaìjọba tirètirẹ̀ kalèkalẹ̀. Kò pépẹ́àwonàwọn Fascist bèrèbẹ̀rẹ̀ síí darí ilèilẹ̀ Italy.
 
ÀwonÀwọn omoọmọ ogun Mussoline kolukọlu Ethopia ní 1905 wónwọ́nségunṣẹ́gun ibèibẹ̀ léyìnlẹ́yìn òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà tí ó gbóná. Kò pé tí Mussolini ní kí àwonàwọn omoọmọ ogun òun lolọ ran General Franco lówólọ́wọ́ nínú ogun abéléabẹ́lé ilèilẹ̀ Spain. Ní 1940, Italy bèrèbẹ̀rẹ̀ síí kópa nínú ogun àgbáyé kejì. Italy dúró gbá gbá gba ti Germany sùgbónṣùgbọ́n wónwọ́n ségunṣẹ́gun Italy. Won di ebi ifidíremiifidírẹmi Italy yìí ru Mussolini. WónWọ́n gba ìjobaìjọba lówólọ́wọ́ rèrẹ̀ wónwọ́nsosọ óọ́èwònẹ̀wọ̀n. ÀwonÀwọn German gba á sílèsílẹ̀ ó wa di olórí ìjobáìjọbá tí kò fesèfẹsẹ̀ múlèmúlẹ̀ kan. Ní odúnọdún 1945, àwonàwọn tí ó nń jà rí i mú, wónwọ́n sì pa á.
 
{{ekunrere}}