Ilẹ̀ Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 1:
[[ILÈILẸ̀ YORÙBÁ]]
 
[[AKINỌLA ỌLÁNREWAJU]]
[[AKINOLA OLÁNREWAJU]]
Ìtàn ÀkoólèÀkọọ́lẹ̀ Yorùbá
GégéGẹ́gẹ́ bí ìwádìí Àtàndá (1980), bí àwonàwọn Yorùbá seṣeorílèorílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àsìkò tí wónwọ́n tèdótẹ̀dó síbèsíbẹ̀ kíi seṣe ìbéèrè tí enikéniẹnikẹ́ni lè dáhùn ní pàtó nítorí pé àwonàwọn baba nlá wonwọn kò fi àkosílèàkọsílẹ̀ ìseìṣe àti ìtàn wonwọn sílèsílẹ̀ gégégẹ́gẹ́ bí àjogúnbá.
ÀwonÀwọn ìtàn àtenudénuàtẹnudẹ́nu tí a gbógbọ́ nípa ìsèdáìṣẹ̀dá yàtòyàtọ̀ sí ara wonwọn díèdíèdíẹ̀díẹ̀. Ìtàn kan sosọ fún wa pé àwonàwọn Yorùbá ti wà láti ìgbà ìwásèìwáṣẹ̀ àti láti ìgbà ìsèdáìṣẹ̀dá ayé. Ìtàn òrùnọ̀rùn pé kí ó wá sèdáṣẹ̀dá ayé àti àwonàwọn ènìyàn inú rèrẹ̀. Ìtàn náà sosọ fún wa pé Odùduwà sòkalèsọ̀kalẹ̀ sí Ilé-IfèIfẹ̀ láti òrunọ̀run pèlúpẹ̀lú àwonàwọn emèwàẹmẹ̀wà rèrẹ̀. WónWọ́nseṣe iséiṣẹ́ tí Olódùmarè rán wonwọnàsepéàṣepé. NípasèNípasẹ̀ ìtàn yìí, a lè sosọ pé Ilé-IfèIfẹ̀àwonàwọn Yorùbá ti sèṣẹ̀, àti pàápàá gbogbo ènìyàn àgbáyé.
Ìtàn mìíràn tí a tún gbógbọ́ sosọ fún wa pé àwonàwọn Yorùbá wá Ilé-IfèIfẹ̀ láti ilèilẹ̀ MékàMẹ́kà lábélábẹ́ àkóso Odùduwà nígbà tí ìjà kan bébẹ́ sílèsílẹ̀ilèilẹ̀ Arébíà léyìnlẹ́yìnèsìnẹ̀sìn Islam dé sáàrin àwonàwọn ènìyàn agbègbè náà. ÀwonÀwọn onímòonímọ̀ kan nípa ìtàn ti yeyẹ ìtàn yìí wò fínnífínní, wónwọ́n sì gbà wí pé bí ó tilètilẹ̀ jéjẹ́ pé ó seṣe é seṣeàwonàwọn Yorùbá ní ìbásepòìbáṣepọ̀ pèlúpẹ̀lú àwonàwọn ará MékàMẹ́kà àti agbègbè Arébíà mìíràn kí wónwọ́nsíṣí kúrò, ibi tí wónwọ́n ti sèṣẹ̀ wá gan-an ni íjíbítì tàbí Núbíà. ÀwonÀwọn onímòonímọ̀ yìí náà gbà pé Odùduwà ni ó jéjẹ́ olórí fún àwonàwọn ènìyàn yìí.
Kókó pàtàkì kan tí a rí dìmú ni pé Odùduwà ni olùdarí àwonàwọn ènìyàn tí ó wá láti tèdótẹ̀dó sí Ilé-ÌfèÌfẹ̀ gégégẹ́gẹ́ bí ìtàn méjéèjì tí a gbógbọ́ seṣe sosọ. Tí a bá yeyẹ ìtàn méjéèjì wò, a ó rí i pé kò seṣe é seṣe kí Odùduwà méjèèjì jéjẹ́ enìkanẹnìkan náà nítorí pé àsìkò tàbí odúnọdún tí ó wà láàrin ìsèdáìṣẹ̀dá ayé àti àsìkò tí èsìnẹ̀sìn Islam dé jìnna púpòpúpọ̀ sí ara wonwọn. Nítorí ìdí èyí a lè gbà pé nínú ìtàn kejì ni Odùduwà ti kópa. Ìdí mìíràn tí a fi lè fara mómọ́ ìtàn kèjì ni pé léyìnlẹ́yìn àyèwòàyẹ̀wò sí ìtàn ìsèdálèìṣẹ̀dálẹ̀ Yorùbá fínnífínní, ó hàn gbangba pé Odùduwà bá àwonàwọn èdáẹ̀dá OlórunOlọ́run kan ní Ilé-IfèIfẹ̀ nígbà tí ó dé ibèibẹ̀. ÀwonÀwọn ìtàn kan dárúkodárúkọ ÀgbonmìrègúnÀgbọnmìrègún tí Odùduwà bá ní Ilé-IfèIfẹ̀. Èyí fihàn pé kìí seṣe òfìfò ní ó ba Ilé-IfèIfẹ̀, bí kò seṣeàwonàwọn kan wà níbèníbẹ̀ pèlúpẹ̀lú ÀgbonmìrègúnÀgbọnmìrègún. Èyí sì tókatọ́ka sí i pé a ti sèdáṣẹ̀dá àwonàwọ̣n ènìyàn kí òròọ̀rọ̀ Odùduwà tó jejẹ yoyọ, nítorí náà, kò lè jéjẹ́ Odùduwà yìí ni Olódùmarè rán wá láti sèdáṣẹ̀dá ayé gégégẹ́gẹ́ bí a ti gbógbọ́ o nínú ìtàn ìsèdáìṣẹ̀dá.
LónàLọ́nà mìíràn èwèẹ̀wẹ̀, a rí èríẹ̀rí nínú ìtàn pé Odùduwà níláti gbé ìjà ko àwonàwọn òwóọ̀wọ́ ènìyàn kan tí ó bá ní Ilé-IfèIfẹ̀ láti gba ilèilẹ̀, àti pàápáà láti jéjẹ́ olórí níbèníbẹ̀. Ìtàn MóremíMọ́remí àjàsoròàjàṣorò tí ó fi ètànẹ̀tàn àti èmíẹ̀mí omoọmọ rèrẹ̀ okùnrinọkùnrin kan sosoṣoṣo tí ó bí gba àwonàwọn ènìyàn rèrẹ̀ sílèsílẹ̀ lówólọ́wọ́ ìmúnisìn àwonàwọn èyàẹ̀yà Ùgbò lè jèjẹ̀ èríẹ̀rí tí ó fìdí rèrẹ̀ múlèmúlẹ̀ pé Odùduwà àti àwonàwọn ènìyàn rèrẹ̀ ja òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun kí wónwọ́n tó le gba àkóso ilèilẹ̀ náà lówólọ́wọ́ àwonàwọn òwóọ̀wọ́ ènìyàn kan tí wónwọ́n bá ní Ilé-IfèIfẹ̀ gégégẹ́gẹ́ bí ìtàn àbáláyé ti sosọ.
 
OrílèOrílẹ̀-Èdè Yorùbá
orílèorílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àwonàwọn ènìyàn Yorùbá wà káàkiri ìpínlèìpínlẹ̀ bí i mésànmẹ́sàn-án. ÀwonÀwọn ìpínlèìpínlẹ̀ náà ni EdóẸdó, Èkó, Èkìtí, Kogí, Kúwárà, Ògùn, Òndò, ÒsunỌ̀ṣun àti ÒyóỌ̀yọ́.
Lóde òní, Yorùbá wà káàkiri ilèilẹ̀ àwonàwọn aláwòaláwọ̀ dúdú (Áfíríkà), AméríkàAmẹ́ríkà àti káàkiri àwonàwọn erékùsù tí ó yí òkun Àtìlántíìkì ká. Ní ilèilẹ̀ aláwòaláwọ̀ dúdú. A le ríwonríwọn ní Nàìjíríà, Gáná, OrílèOrílẹ̀-Olómìnira BènèBẹ̀nẹ̀, Tógò, Sàró àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ. Ní ilèilẹ̀ AméríkàAmẹ́ríkà àti àwonàwọn erékùsù káàkiri, a lè rí wonwọn ní jàmáíkà, Kúbà, Trínídáádì àti Tòbégò pèlúpẹ̀lú Bùràsíìlì àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ.
YàtòYàtọ̀ sí ètò ìjobaìjọba olósèlú àwarawa tí ó fi gómìnà jejẹ olórí ní ìpínlèìpínlẹ̀ kòòkankọ̀ọ̀kan, a tún ní àwonàwọn obaọba aládé káàkiri àwonàwọn ìlú nlánlá tí ó wà ní ìpínlèìpínlẹ̀ kòòkankọ̀ọ̀kan. DíèDíẹ̀ lára wonwọn ni ObaỌba ìbíní, ObaỌba Èkó, Èwí tí Adó-Èkìtì, Òbáró ti Òkéné, Aláké tí AbéòkútaAbẹ́òkúta, Dèji ti ÀkúréÀkúrẹ́, Olúbàdàn ti Ìbàdàn, Àtá-Ója ti ÒsogboÒṣogbo, SòúnSọ̀ún ti ÒgbòmòsóÒgbòmọ̀ṣọ́ ati Aláàfin ti ÒyóỌ̀yọ́.
BaálèBaálẹ̀tirètirẹ̀ jéjẹ́ olórí ìlú kékeré tàbí abúlé. Ètò ni ó sosọ wónwọ́n di olórí ìlú kéréje nítorí pé Yorùbá gbàgbógbàgbọ́ pé ìlú kìí kéré kí wónwọ́n má nìí àgbà tàbí olórí. Aláàfin ni a kókókọ́kọ́ gbógbọ́ pé ó sosọ àwonàwọn olórí báyìí di olóyè tí a mòmọ̀baálèbaálẹ̀.
LábéLábẹ́ àwonàwọn olórí ìlú wònyíwọ̀nyí ni a tún ti rí àwonàwọn olóyè orísìírísìí tí wónwọ́niséisẹ́wónwọ́n ń se láàrín ìlú, egbéẹgbẹ́, tàbí ìjoìjọ (èsìnẹ̀ṣìn). Lára irú àwonàwọn oyè béèbẹ́ẹ̀ ni a ti rí oyè àjewòàjẹwọ̀, oyè ogun, oyè àfidánilóláàfidánilọ́lá, oyè egbéẹgbẹ́, oyè èsìnẹ̀ṣìn àti oyè ti agboolé bíi Baálé, Ìyáálé, AkéwejèAkéwejẹ̀, Olórí omoọmọ-osú, Ìyá Èwe Améréyá, MógàjíMọ́gàjí àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ.
 
Èdè Yorùbá
Ní báyìí, tí a bá wo èdè Yorùbá, àwonàwọn onímòonímọ̀ pín èdè náà sábésábẹ́ èyàẹ̀yà Kwa nínú ebíẹbí èdè Niger-Congo. WónWọ́n tún fìdí rèrẹ̀ múlèmúlẹ̀èyàẹ̀yà Kwa yìí ló wópòwọ́pọ̀ jùlojùlọsísosísọ, ní ìwòìwọ̀ oòrùn aláwòaláwọ̀ dúdú fún egbeegbèrúnẹgbẹ̣ẹgbẹ̀rún odúnọdún. ÀwonÀwọn onímòonímọ̀ èdè kan tilètilẹ̀ ti fi ìdí òròọ̀rọ̀ múlèmúlẹ̀ pé láti orírun kan náà ni àwonàwọn èdè bí Yorùbá, Kru, Banle, Twi, Ga, Ewe, Fon, Edo, Nupe, Igbo, Idoma, Efik àti Ijaw ti bèrèbẹ̀rẹ̀ sí yapa gégégẹ́gẹ́ èdè òtòòtòọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó dúró láti bí egbèrúnẹgbẹ̀rún métamẹ́ta òdúnọ̀dún séyìnsẹ́yìn.
ÒkanỌ̀kan pàtàkì lára àwonàwọn èdè orílèorílẹ̀ èdè Nàìjíríà ni èdè Yorùbá. ÀwonÀwọn ìpínlèìpínlẹ̀ tí a ti lè rí àwonàwọn tó n sosọ èdè Yorùbá nílènílẹ̀ Nàìjíríà norílènorílẹ̀ èdè Bìní. Tógò àti apá kan ní Gúúsù ilèilẹ̀ AméríkàAmẹ́ríkà bí i Cuba, Brasil, Haiti, àti Trinidad. Ní gbogbo orílèorílẹ̀-èdè tí a dárúkodárúkọ, yàtòyàtọ̀orílèorílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òwò erúẹrú ni ó gbé àwonàwọn èyàẹ̀yà Yorùbá dé ibèibẹ̀.
 
ÀsàÀṣà Yorùbá
Ìràn Yorùbá jéjẹ́ ìran tó ti ní àsààṣà kí Òyìnbó tó mú àsààṣà tiwontiwọn dé. Ètò ìsèlú àti ètò àwùjoàwùjọ wonwọn móyánmọ́yán lórí. WónWọ́nìgbàtbóìgbàtbọ́ nínú OlórunỌlọ́run àti òrìsàòrìṣà, ètò oròọrọ̀ ajé wonwọn múnádóko.
Yorùbá ní ìlànà tí wónwọ́n ń tèlétẹ̀lé láti fi omoọmọ fókofọ́kọ tàbí gbé ìyàwó. WónWọ́n ní ìlànà tó sosọ bí a se n somosọmọ lórúkolórúkọ àti irú orúkoorúkọ tí a le sosọ omoọmọ torí pé ilé là á wò, kí a tó somosọmọ lórúkolórúkọ. Ìlànà àti ètò wà tí wónwọ́n ń tèlétẹ̀lé láti sin ara wonwọn tó papòdà. Oríìsírísìí ni ònàọ̀nà tí Yorùbá máa ń gbá láti ran wonwọn lówólọ́wọ́, èyí sì ni à ń pè àsààṣà ìràn-ara-eniẹni-lówólọ́wọ́. Àáró, ìgbéìgbẹ́ odúnọdún dídedídẹ, ìsingbà tàbí oko olówó, Gbàmí-o-ràmí àti Èésú tàbí Èsúsú jéjẹ́ ònàọ̀nà ìràn-ara-eniẹni-lówólọ́wọ́.
Yorùbá jéjẹ́ ìran tó kónimórakónimọ́ra. Gbogbo nnkannǹkan wonwọn sì ló létò. Gbogbo ìgbésí ayé wonwọn ló wà létòlétò, èyí ló mú kí àwùjoàwùjọ Yorùbá láyé ojóunọjọ́un jéjẹ́ àwùjoàwùjọ ìfòkànbalèìfọ̀kànbalẹ̀, àlàáfíà àti ìtèsíwájúìtẹ̀síwájú. ÀwonÀwọn àsààṣàjejẹ mómọ́ ètò ìbágbépòìbágbépọ̀ láwùjoláwùjọ Yorùbá ní èkóẹ̀kọ́-ilé, ètò-ìdílé, elégbéjegbéẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ tàbí iròsíròirọ̀sírọ̀. ÈkóẸ̀kọ́ abínimóabínimọ́, àwòse, erémodéerémọdé, ìsírò, ìkini, ìwà omolúàbíọmọlúàbí, èèwòèèwọ̀, òwe Yorùbá, ìtàn àti àlóàlọ́ jéjẹ́ èkóẹ̀kọ́-ilé. Nínú ètò mòlébímọ̀lẹ́bí lati rí Baálé, ìyáálé Ilé, OkùnrinỌkùnrin Ilé, Obìnrin Ilé, ObàkanỌbàkan, Iyèkan, ErúbíléẸrúbílé àti Àràbátan.
OrísìírísìíOríṣìíríṣìí oúnjeoúnjẹ tó ń fún ni lókun, èyí tó ń seni lóore àti oúnjeoúnjẹ amúnidàgbà ni ìràn Odùduwà ní ní ìkáwóìkáwọ́. DíèDíẹ̀ lára wonwọn ni iyán, okàọkà, èkoẹ̀kọ móínmóínmọ́ínmọ́ín àti gúgúrú.
ÌWÉ ÌTÓKASÍÌTỌ́KASÍ
 
*Adeoye, C.L. (1979): ÀsàÀṣà àti Ìse Yorùbá, Oxford University Press.
ÈkaẸ̀ka ÈkóẸ̀kọ́ Èdè Yorùbá, Ilé-ÈkóẸ̀kọ́ Gíga ti ÀwonÀwọn OlùkóniOlùkọ́ni Àgbà tí ó jéjẹ́ ti ÌjobaÌjọba ÀpapòÀpapọ̀OsíèlèOsíẹ̀lẹ̀, AbéòkútaAbẹ́òkúta (2005): OgbónỌgbọ́n ÌkóniÌkọ́ni, Ìwádìí àti ÀsàÀṣà Yorùbá.
 
*Olatunji, O.O. (2005): History, Culture and Language, Published fro J.F. OdunjoOdunjọ Memorial Lecture, Series 5.
 
*Opadotun Tunji, ÈkóẸ̀kọ́ Èdè Yorùbá Fún Ilé-ÈkóẸ̀kọ́ OlùkóniOlùkọ́ni Àgbà, ÀkójopòÀkọ́jọpọ̀ ÈkóẸ̀kọ́ Èdè Yorùbá.