Ìnáwó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 69 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q43015 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 1:
Sé Yorùbá bòbọ̀ wónwọ́n ní “Se bó o ti momọ eléwààẹlẹ́wàà sàpónsàpọ́n. ÌwònÌwọ̀n eku nìwònnìwọ̀n ìtéìtẹ́.” WonWọn a sì tún máa pa á lówe pé “ìmò“ìmọ̀ ìwònìwọ̀n ara eniẹni ni ìlékè ogbónọgbọ́n nítorí pé ohun owóọwọ́ mi ò tó ma fi gògògọ̀gọ̀ fà á, í í já lu olúwarèolúwarẹ̀ mólèmọ́lẹ̀ ni”
áyé òde òní, àwonàwọn òdóọ̀dọ́ tilètilẹ̀ máa ń dásàdáṣà báyìí pé “dèédèé“dẹ̀ẹ́dẹ̀ẹ́ rerẹ, ìgbéraga ni ìgbérasán lèlẹ̀.” WónWọ́n máa ń sosọ èyí fún eniẹni tí ó bá ń kojákọjá ààyè rèrẹ̀ ni. GégéGẹ́gẹ́òroọ̀rọ ogbónọgbọ́n kan se wí pé “ni àtètékóseàtètékọ́ṣe ni òròọ̀rọ̀ wà,” béèbẹ́ẹ̀ náà ni ètò ti wà fún ohun gbogbo láti ìpilèsèìpilẹ̀sẹ̀ wá. Ètò ní í mú kóhun gbogbo rí rémúrẹ́mú. OlorunỌlọrun ògáọ̀gá ògo to da ayé. Ó fi erankoẹranko sígbó {àwonàwọn olóró}. Ó tún fi ejaẹja síbú. Ó fi àwonàwọn eyeẹyẹ kan sígbó. Ó fi àwonàwọn mìíràn sílé. Àdìmúlà bàbá tó ju bàbá lolọ tún fi ààlà sáààrin ilèilẹ̀, omi òkun, àti sánmòsánmọ̀. Ohun gbogbo ń lolọmèlòmẹ̀lọ̀-mèlomẹ̀lọ.
Bàbá dá àwa omonìyànọmọnìyàn kò fi ojú wa sí ìpàkóìpàkọ́. Kò fi esèẹsẹ̀ wa sórí kí orí wá wà lésèlẹ́sẹ̀. Elétò lOlórunlỌlọ́run gan-an.
 
Kíni ètò? Ètò jéjẹ̣́ ònàọ̀nà tí à ń gbà láti sàgbékalèsàgbékalẹ̀ ohun kan tàbí òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ nnkannǹkan lójúnà àti mú kí ó se é wò tàbí kó se é rí tàbí kó dùn ún gbógbọ́ sétí. A sèdásẹ̀dá orúkoorúkọ yìí gan-an ni. Ohun tí a tò ní í jéjẹ́ ètò.
ÈwèẸ̀wẹ̀, ìnáwó ni ònàọ̀nà tàbí ìwà wa lórí bí a se ń náwó. Ohun pàtàkì ni láti sètòo bí a óò se máa ná àwonàwọn owó tó bá woléwọlé fún wa. Ní àkókóàkọ́kọ́ ná, èyí yóò jéjẹ́ kí á momọ ìsirò oye owó tó ń woléwọlé fún wa yálà lósèlọ́sẹ̀ ni o tàbí lósù, bí ó sì se lódúnlọ́dún gan-an ni.
Bákan náà, yóò tún mú kó rorùnrọrùn fún wa láti momọ àwonàwọn ònàọ̀nà tí owó náà ń bá lolọ. Síwájú síi, ètò yóò ràn wá lówólọ́wọ́ láti le ní ìkóraìkọ́ra-eniẹni-níjàánu lórí bí a se ń náwó wa.
Bí a bá ti mú ìsàkòtúnìsàkọ̀tún tán, tí a tún mú ìsàkòsì náà, ìsàkusà ni yóò kù nilènilẹ̀. Tí a bá yoyọ ti ètò kúrò nínú ojúse ìjobaìjọba pàápàá sí ará ìlú, eré omodéọmọdé ni ìyókù yóò jéjẹ́. Gbogbo àwonàwọn ekaẹka ìjobaìjọba pátá-porongodo ló máa ń ní àgbékalèàgbẹ́kalẹ̀ ìlànà tí wonwọn yóò tèlétẹ̀lé lati momọ oye owó ti wonwọn n reti ati eyi ti wonwọn óò na bóyá fún odidi odúnọdún kan ni o tàbí fún osù díèdíẹ̀. Èyí ni wónwọ́n nǹ pé ní ‘ÈTÒ ÌSÚNÁ’
Ìdí nìyí tó fi se pàtàkì fún gbogbo tolórí-telémùtẹlẹ́mù, tòngatòǹga-tònbèrètòǹbẹ̀rẹ̀ ki kúlukú ní ètò kan gbòógì lónàlọ́nà bí yóò se máa náwó rèrẹ̀. Yorùbá bòbọ̀ wónwọ́n ní, “eku tó bá ti ní òpó nílènílẹ̀, kì í si aré sá. Bí a bá ti se àlàkalèàlàkalẹ̀ bí a óò se náwo wa yóò dín ìnákùùná kù láwùjoláwùjọ wa. Ìnáwó àbàadì pàápàá yóò sì máa gbénúgbẹ́nú ìgbéìgbẹ́ wo wá láwùjoláwùjọ wa.
Mo ti sosọ léèèkanlẹ́ẹ̀ẹ̀kan nípa àwonàwọn ekaẹka ìjobaìjọba métèètàmẹ́tẹ̀ẹ̀tà orílèorílẹ̀ èdè yìí tí wónwọ́n máa ń sètò ìnáwó wonwọn. ÀwonÀwọn wo ló tún yeyẹ kó máa sètò ìnáwó? ÀwonÀwọn náà ni àwonàwọn òsìséòṣìṣẹ́ ìjobaìjọba, àwonàwọn onísòwòoníṣòwò, àwonàwọn omoọmọ ilé-ìwé, níbi àseyeàsẹyẹ.
ÀwonÀwọn òsìséòsìsẹ́ ìjobaìjọba gbodògbọdọ̀ sètò ìnáwó wonwọn kó sì gún régé. Ìdí ni pé, èyí ni yóò jéjẹ́ kí owó osù wonwọn tó í ná. EniẸni tó ń gba egbèrúnẹgbẹ̀rún méwàámẹ́wàá náírà lósù tí kò sì fi òdiwònòdiwọ̀n sí ìnáwó rèrẹ̀ nípa títò wónwọ́n léseeselésẹẹsẹ le máa rówó sohun tó yeyẹ láàákò tó yeyẹ nígbà tí ó bá ti náwó rèrẹ̀àwonàwọn ohun mìíràn tó seése kó nítumònítumọ̀ sùgbónṣùgbọ́n tí kì í se fún àkókò náà.
 
Irú wonwọn á wá má ráhàn owó tósù bá ti dá sí méjì tàbí kí wónwọ́n jejẹ gbèsè de owó osù mìíràn.
Síwájú sí i, àwonàwọn onísòwòoníṣòwò gbódògbọ́dọ̀ máa sètò to jíire lórí ìnáwó wonwọn. Nípa síseṣíṣe èyí, wonwọn óò ni ànfààníàǹfààní láti mòmọ̀ bóyábọ́yá OláńrewájúỌláńrewájú ni iséiṣẹ́ wonwọn tàbí OláńrèyìnỌláńrẹ̀yìn. Níbi tí àtúnseàtúnṣe bá sì ti ponpọn dandan, “a kì í fòdù òyàọ̀yà sùn ká tó í nà án ládàá,” wonwọn kò nì í bèsù bègbàbẹ̀gbà, wonwọn óò sì se àtúnseàtúnṣe ní wéréwéré. ÀwonÀwọn omoọmọ ilé-ìwé gan-an gbodògbọdọ̀ mòmọ̀ pé ká sètò ìnáwó eniẹni kì í sohun tó burúkú bí ti í wù kó momọ. GégéGẹ́gẹ́omoọmọ ilé èkóẹ̀kó gíga, béèyàn bá gbowó fún àwonàwọn orísirísi ìnáwó láti ilé lórí èkóẹ̀kọ́ eniẹni, ó seése kí irú eniẹni béèbẹ́ẹ̀ máa ná ìná-àpà tó bá dé ààrin àwonàwọn elegbéeẹlẹgbẹ́ẹ rèrẹ̀. Irú wonwọn ló máa ń pe òsèọ̀sẹ̀wónwọ́n bá ti ilé lódòlọ́dọ̀ àwonàwọn òbí wonwọn dé ní ‘Ose‘Ọṣẹ ìgbéraga’ Èyí kò yeyẹ omolúàbíọmọlúàbí pàápàá. Ó sì ń pè fún àtúnseàtúnṣe.
SíseṢíṣe ètò tó gúnmógúnmọ́ lórí ònàọ̀nà tí à ń gbà náwó kò pin sí àwonàwọn ònàọ̀nà tí mo sàlàyé rèrẹ̀ sókè yìí. Mo féfẹ́ kó ye wá pé a le sètò ìnáwó wa níbi àwonàwọn orísisi ayeyeayẹyẹìsomolórúkoìsọmọlórúkọ [tàbí ìkómójádeìkọ́mọ́jáde], ìgbéyàwó, oyè jíjejíjẹ, ìsíléìṣílé, àti ìsìnkú àgbà àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ. Yóò ràn wá lówólọ́wọ́ láti fi bí a se tó hàn wá ká le momọ ohun tí a óò dágbá lé níbi irúféirúfẹ́ àseyeàṣeyẹ tí a bá féfẹ́ í seṣe. Nípa béèbẹ́ẹ̀ a ò ní í sí nínú àwonàwọn tó máa ń pa òwe tó máa ń mú kí wonwọn kábàámòkábàámọ̀ nígbèyìnnígbẹ̀yìn òròọ̀rọ̀. Òwe wonwọn ni, “rán asoaṣọ rerẹ bí o bá se ga momọ.” Èyí tí wonwọn ì bá fi wí pé “rán asoaṣọ rerẹ bí o bá se lówóo rèrẹ̀ sí.” Bí eniẹni tó ga bá rán asoaṣọ rèrẹ̀ ní ‘bóńfò’ bó se lówó momọ ni, kò sì féfẹ́ í sàsejù. Irú eniẹni béèbẹ́ẹ̀ le ti mòmọ̀ pé alásejù pérépẹ́rẹ́ ní í tétẹ́.
Bí a bá wá féfẹ́ láti sètò ìnáwó wa, ó yeyẹmòmọ̀ìtòsèìtòṣẹ̀lÒyòólỌ̀yọ̀ọ́, Oníbodè lo làààfin, enìkanẹnìkan kì í fi kèkékẹ̀kẹ́ síwájú esinẹsin. Iwájú lojúgun í gbé. Ìnáwó tó bá seṣe kókó jùlojùlọ tó sì ń bèèrè fún ìdásí ní kíákíá ló yeyẹ ká fi síwájú bí a se ń tò ó ní eseeseẹsẹẹsẹ. Bí a bá wá kíyèsí pé ètò tí a là sílèsílẹ̀ ti ju agbára wa lolọ, e jéjẹ́ ká fura nítorí pé akéwì kan wí pé:
 
“E“Ẹ fura óò!
 
E fura óò!
 
Páńsá ò fura
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ìnáwó"