Koisaanu: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 26 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q459387 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 10:
==Oju=iwe kiini==
 
OLOFNSAOỌLỌFNSAO OLUKEMI M.
 
ÀWONÀWỌN EBÍẸBÍ ÈDÈ KHOISAN
 
Ìfáàrà
 
EbíẸbí èdè Khoisan yìí ni ó kéré jù lolọ nínú àwonàwọn ebíẹbí èdè gbogbo tí ó wà ní Áfíríkà. GégéGẹ́gẹ́ bí Greenberg (1963a) ti sosọ, ó ní àwonàwọn ni wónwọ́n dúró fún èyí tí ó kéré jù lolọ nínú èdè Áfíríkà.
ÌPÌLÈÌPÌLẸ̀ ORÚKOORÚKỌ ÈDÈ YÌÍ
A mu orúkoorúkọ yìí jáde láti ara orúkoorúkọ egbéẹgbẹ́ Khoi-Khoi ti Gusu ileilẹ Afirikà (South Africa) àti egbéẹgbẹ́ san (Bushmen) ti Namibia. A máa ń lo orúkoorúkọ yìí fún OrísìírísìíOríṣìíríṣìí àwonàwọn èyàẹ̀yàwónwọ́n jéjẹ́àwonàwọn gan-an ni wónwọ́n kókókọ́kọ́ jéjẹ́ olùgbé ilèilẹ̀ south Africa kí awonawọn Bantu tó wá, kí àwonàwọn òyìnbó ilèilẹ̀ GeesiGẹẹsi (Europe) sì tó kó wonwọn lérùlẹ́rù.
OrísìírísìíOríṣìíríṣìí àwonàwọn onímòonímọ̀ ni wonwọn ti sisesiṣẹ lórí orúkoorúkọ yìí – Khoisan.Tan Gùldemann ati Rainer Vossen sàlàyéṣàlàyé nínú iséiṣẹ́ rèrẹ̀ pé Leonardt Schulze 1928 ni o mu orúkoorúkọ yìí jáde láti ara Hottentot’ tí o túmòtúmọ̀ sí Khoi ti o sì tún túmòtúmọ̀ sí ‘person’ (ènìyàn) àti ‘san’ tí ó túmòtúmọ̀ sí ‘forager’. LéyìnLẹ́yìn èyí ni onímòonímọ̀ ìjìnlèìjìnlẹ̀ nípa èdáẹ̀dá àsààṣà, ìgbàgbóìgbàgbọ́ àti ìdàgbàsókè omonìyànọmọnìyàn, anthropologist Schapera (1930) tún wá fèfẹ̀ orúkoorúkọ yìí lòjù séyìnsẹ́yìn nípasènípasẹ̀ ‘Hottentot’àti ‘Bushman’ gégégẹ́gẹ́èyàẹ̀yà, (racia) àsààṣà (cultural) àti ìmòìmọ̀ èdáẹ̀dá èdè. (Linguistic).
ÀwonÀwọn orúmòorúmọ̀ mìíràn tí wónwọ́n jéjẹ́ gégégẹ́gẹ́egbéẹgbẹ́ ketakẹta ti wónwọ́n tún sisésiṣẹ́orúkoorúkọ yìí lórí ni Kolnler (1975, 1981) sands (1998) àti Traill (1980, 1986). WonWọn pinnu láti lo orúkoorúkọ náà Khoisan gégégẹ́gẹ́ bí olúborí fún àwonàwọn èdè tí kìí seṣe ti Bantù tí kì í sì í seṣe èdè Cushitic.
ÀwonÀwọn onímòonímọ̀ akíólójìakíọ́lọ́jì fi han wí pé nnkannǹkanegbèrúnẹgbẹ̀rún lónàlọ́nà ogófaọgọ́fa odúnọdún séyìnsẹ́yìn ni awonawọn ènìyàn Khoisan ti fara hàn. Èyí fi han pé lódòlọ́dọ̀ àwonàwọn àgbà láèláè nìkan ni a ti lè máa gbógbọ́ èdè Khoisan nìkan báyìí.
Bí èdè Khoisan tilètilẹ̀ farajorafarajọra nínú ètò ìró, gírámà tirètirẹ̀ yàtòyàtọ̀ gédégbé. Àìsí àkósìlèàkọ́sìlẹ̀ ìtàn àwonàwọn èdè wònyíwọ̀nyí mú kí o nira díèdíẹ̀ láti sosọ ìfarajoraìfarajọra awonawọn èdè yìí sí ara àti sí àwonàwọn èdè adúláwòadúláwọ̀ tí ó kù.
Lóde àní, IlèIlẹ̀ (South Western Africa) gúsu-ìwòìwọ̀ òòrùn Áfíríkà títí dé àginjù kàlàhárì (Kalaharì Desert), láti Angola de South Africa àti ní apákan ilèilẹ̀ Tanzania nìkan ní wónwọ́n ti ń sosọ èdè Khoisan. Edè Hadza àti Sandawe ní ilèilẹ̀ Tanzania ni a sáábà máa ń pè ní Khoisan súgbònṣúgbọ̀n wónwọ́n yàtòyàtọ̀ nípa ibùgbé àti ìmòìmọ̀ èdáẹ̀dá èdè sí ara wonwọn. A wá lè sosọ pé nínú gbogbo èdè àgbáyé, èdè Khoisan wà lára àwonàwọn èdè tí àwonàwọn onímóonímọ́ èdè kò kobiarakọbiara sí tí a kò sì kókọ́ èkóẹ̀kọ́ nípa rèrẹ̀.
 
ÌPÒ TÍ ÈDÈ YÌÍ WÀ
 
Èdè Khoisan yìí gégégẹ́gẹ́ bí a ti sosọ síwájú ń dín kù síi lójoojúmólójoojúmọ́ ni. BéèBẹ́ẹ̀ ni ó sì ń di ohun ìgbàgbé. Ohun tí ó fa èyí ni pé àwonàwọnwónwọ́n ń sosọ àmúlùmálà èdè Khoisan bèrèbẹ̀rẹ̀ sí í sosọ èdè mìíràn tí ó gbilègbilẹ̀ ní agbègbè wonwọn; wónwọ́ndékundẹ́kun kíkókíkọ́ àwonàwọn omoọmọ wonwọn ní èdè abínibí wonwọn. ÒpòỌ̀pọ̀ àwonàwọn èdè wònyíwọ̀nyí ni kò ní àkósilèàkọ́silẹ̀ kankan tí ó sì fíhàn pé sísonùsísọnùàwonàwọn èdè wònyíwọ̀nyí sonùsọnù, kò lè ní àtúnseàtúnṣe.
Ó jéjẹ́ ohun tí ó nira díèdíẹ̀ láti sosọ pé iye àwonàwọn ènìyàn kan pàtó ni wónwọ́n ń sosọ èdè Khoisan. Bí ó tilètilẹ̀ jéjẹ́ pé a kò momọ ohun tí ó selèṣẹlẹ̀ sáájúṣáájúàwonàwọn Òyìnbó tó gòkè bòbọ̀, a kò sì momọ ohun tí ó selèṣẹlẹ̀ ní gbogbo àkókò tí àwonàwọn Òyìnbó ń sètòṣètò ìjobaìjọba, béèbẹ́ẹ̀ sì tún ni pé ìwònbaìwọ̀nba la lè sosọ momọ nípa ohun ti ó ń seleṣẹlẹlówólówólọ́wọ́lọ́wọ́ yìí pèlúpẹ̀lú. SùgbónṢùgbọ́n àkosílèàkọsílẹ̀ fi hàn pé, ní bíì egbèrúnẹgbẹ̀rún odúnọdún méjì séyìnsẹ́yìn, iye nónbànọ́nbàwónwọ́n kokọ sílèsílẹ̀seéṣeé tèlétẹ̀lé mómọ́; àkosílèàkọsílẹ̀ sosọ wí pé egbèrúnẹgbẹ̀rún lónàlọ́nà ogófàọgọ́fàegbèrúnẹgbẹ̀rún lónàlọ́nà Igba (120,000 – 200,000) ni wonwọn, sùgbónṣùgbọ́n èyí ti di ohun àfìséyìnàfìsẹ́yìn bí eégún fí asoaṣọ. WonWọn kò tó béèbẹ́ẹ̀ mómọ́.
DíèDíẹ̀ lára àwonàwọn èdè khoisan àti iye àwonàwọnwónwọ́n ń sosọ óọ́.
 
 
EDE, IYE ÀWONÀWỌN TI Ń SOSỌ, ILÚ,
 
Sandare, 40, 000, Tanzania
Ìlà 68:
ÈTÒ ÌRÓ
 
ÀwonÀwọn èdè Khoisan kò sàìṣàììfarajoraìfarajọra nínú ètò ìrò. Ó dá yàtòyàtọ̀ gédégbè sí àwonàwọn èdè ilèilẹ̀ Áfíríkà yòókù, ó sì jéjẹ́ òkanọ̀kan lára àwonàwọn èdè tí ó nira.
 
FAWẸLI
FAWELI
ÒpòỌ̀pọ̀ àwonàwọn èdè Khoisan wònyí ni ó ń lo fáwélìfáwẹ́lì márùn ún - /i/, /e/, /a/, /o/, /u/ tí a sì lè pè pèlúpẹ̀lú àwonàwọn orísìíoríṣìí àbùdá wònyìíwọ̀nyìí bíi, ìránmú, (nasalization) ìfi káà-òfunọ̀fun-pè (pharyngealization) ati orísìíoríṣìí àmúyeàmúyẹ ohùn bíi mímí ohun (breathy voice) ati dídún ohùn (Creaky voice) tí yóò sì mú bí i orísìíoríṣìí ìró fáwélìfáwẹ́lì bí i ogójì jáde.
 
KỌ́ŃSÓNÁǸTÌ:-
KÓŃSÓNÁNTÌ:-
 
(Clicks) kílíìkì
 
Kílíìkì ni a ń pe àwonàwọn kóńsónántìkọ́ńsónáǹtì wonwọn; títí kan àwonàwọn àfeyínpè (dential), àfèrìgìpè, (alveolar), afàjàfèrìgìpè (alveo-palatal), afègbéafẹ̀gbẹ́-enuẹnu-pè (lateral) àti kílíìkì afètèpè (bilabial Chick). Sandawe àti àwonàwọn Hadza tí ilèilẹ̀ Tanzania ń lo àfeyínpè (dental ) afèrìgìpè (alveolar) àti kílíìkì afègbéafẹ̀gbé-enuẹnu-pè (lateral clicks). PèlúPẹ̀lú gbogbo àhesoàhesọ òròọ̀rọ̀ títí di àkókò yìí orísun kílíìkì èdè Khoisan kò tíì yéni.
 
Àpẹẹrẹ:-
Àpeere:-
 
- Kiliiki Àfeyínpè – A máa ń pe èyí nípa gbígbé ahónahọ́nèyìnẹ̀yìn eyínẹyín iwájú. “tsk”
 
- Kílíìkì Afèrìgìpè – Ó máa ń dún bí ìgbà tí a bá síṣí ìdérí ìgò nípa gbígbé ahónahọ́nèyìnẹ̀yìn eyín iwájú.
 
- Kílíìkì Afàjàfàrìgìpè – Ó máa ń dún nípa gbígbé ahónahọ́n sílèsílẹ̀ kúrò lára àjà enuẹnu.
 
- Kílíìkì AfègbéAfègbẹ́-enuẹnu-pè – ó máa ń dùn gégégẹ́gẹ́ bí ìró ti à ń lò lédè GèésìGẹ̀ẹ́sì láti mú kí esinẹsin kánjú.
 
- Kílíìkì Afètépè máa ń dún nípa kíkanra ètè méjèèjì, tí a sì tún sí i sílèsílẹ̀ ní kíá, gégégẹ́gẹ́ bí ìró ìfenukonuìfẹnukonu ni èyí seṣe máa ń dún.
 
ÒkòòkanỌ̀kọ̀ọ̀kan àwonàwọn kílíìkì wònyíwọ̀nyí ló lè ní Kíkùnyùn-ùn, (Voicing) ríránmú (nasality), “aspiration” ati “ejection”. Láti le mú kí á ní àgbéjáde orísìírísìíoríṣìíríṣìí kílíìkì. ÀwonÀwọn orísìírísìíorísìíríṣìí kílíìkì wonyiwọnyi ló mú kí èdè Khoisan yàtòyàtọ̀. ÀpeereÀpẹẹrẹ nínú èdè Nama, Ogún ni kílíìkì tí wónwọ́n ń lò nígbà tí wónwọ́n n lo métàlélógórinmẹ́tàlélógọ́rin nínú ède Kxoe tí ó jéjẹ́ òkanọ̀kan lára èdè Khoisan. Ní àfíkún, àádórùnàádọ́rùn-ún ònírúrú kóńsónántìkóńsónáǹtì kílíìkì ni wónwọ́n n lo ni Gwi tí òhun náà jéjẹ́ òkanọ̀kan lára èdè Khosian wònyíwọ̀nyí. ÀpeereÀpẹẹrẹ Kílíìki Nama
 
SÍLÉBÙ
 
Gbogbo àwonàwọn kóńsónántìkóńsónáǹtì Kílíìkì àti èyí tí kìí seṣe kílíìkì ló máa ń fara hàn ní ìbèrèìbẹ̀rẹ̀ òròọ̀rọ̀fáwélìfáwẹ́lì sì máa ń tèlétẹ̀lé e. ÌwònbaÌwọ̀nba kóńsónántìkóńsónáǹtìàpeereàpẹẹrẹ /b/, /m/, /n/, /r/, àti /l/ ló lè jejẹ yoyọ láàrín fáwélìfáwẹ́lì, díèdíẹ̀ sì lè farahàn ní èyìnẹ̀yìn òròọ̀rọ̀.
 
ÌRÓ OHÙN
 
ÀwonÀwọn èdè Khosan máa ń sàfihàn orísìírísìíoríṣìíríṣìí ìró ohùn, bí àpeereàpẹẹrẹ, Jul’hoan ní ipele ohun àárún orísìíoríṣìí mérùnmẹ́rùn, ó sì ní ipele ohun òkè kan.
 
GIRAMA
 
ÒròỌ̀rọ̀ àti ìhun gbólóhùn àwonàwọn èdè Khoisan yàtòyàtọ̀ síra láàrin ara wonwọn.
 
Ọ̀RỌ̀ ORÚKỌ
ÒRÒ ORÚKO
 
ÌsòríÌsọ̀rí métamẹ́ta ni òròọ̀rọ̀ arúkoarúkọ Khoisan pín sí; bí a bá wòó, nípasènípasẹ̀ jendajẹnda, akoakọ, abo àti àjoniàjọni ni ò pín sí. Nínú Kxoe, fún àpeereàpẹẹrẹ, jéńdàjẹ́ńdà nínú òròọ̀rọ̀-orúkoorúkọ aláìlémìíaláìlẹ́mìí tún máa ń ní nnkannǹkan seṣe pèlúpẹ̀lú ìrísíìríṣí, bi àpeereàpẹẹrẹ, akoakọ ní í seṣe pèlúpẹ̀lú gígùn, tí tò si tóbi, nígbà tí abo ní í seṣe pèlúpẹ̀lú nnkennǹken kúkúrú, gbígbòòrò tí kó sì tóbi òrísìírísìíòríṣìíríṣìí mófíímùmọ́fíímù ni wónwọ́n fi ń parí òkòòkanòkọ̀ọ̀kan àwonàwọn jéńdàjẹ́ńdà wònyíwọ̀nyí.
 
ÀpeereÀpẹẹrẹ láti inú èdè Nama.
 
Khoisan , English, Yoruba ,
 
Khoe-b, Man , OkùnrinỌkùnrin ,
 
Khoe-s, Woman, Obinrin ,
 
OrísìírísìíOríṣìíríṣìí nómbànọ́mbà métamẹ́ta ni wónwọ́n ní, àwonàwọneyoẹyọ, oníméjì àti òpòọ̀pọ̀.
 
NỌ́MBÀ
NÓMBÀ
ApeereApẹẹrẹ lati inu èdè Naro
 
Male (AkoAkọ), Female (Abo), Common (Ako/Abo)
 
SG, ba , sa _________
Ìlà 130:
PL llua dzi na
 
Ọ̀RỌ̀-ÌṢE
ÒRÒ-ÌSE
 
Àbùdá gírámà tí ó sáábà máa ń jejẹ yoyọ nínú àwonàwọn èdè Khoisan ni lílo òròọ̀rọ̀-iseiṣe àkànmónúkoàkànmónúkọ (verb compound) nígbà tí èdè GèésìGẹ̀ẹ́sì ń lo òròọ̀rọ̀ atókùnatọ́kùn tàbí òròọ̀rọ̀-iseiṣe kan (single verb) ÀpeereÀpẹẹrẹ
 
English, Khoisan,
Ìlà 139:
Àsìkò (Tense)
 
ÈrúnẸ̀rún ni a máa ń lò láti fi àsìko hàn nínú èdè KhoeKhoe àti nípa lílo àfòrò eyinẹyin nínú ede Kxoe, Buga ati //Ani Ninú àwonàwọn èdè Kalahari East Kxoe, ÀfòmóÀfòmọ́ èyìnẹ̀yìn ló ń fi ìsèlèìṣẹ̀lẹ̀ ti o ti Koja hàn (Past Tense), ohun tó ń selèṣẹlẹ̀ lówólọ́wọ́ tí ó lòdì ati jèróndìjẹ̀rọ́ndì hàn nígbà tí ìsèlèìṣẹ̀lẹ̀ lówólówólọ́wọ́lọ́wọ́ àti ti ojóọjọ́ iwájú ń lo ÈrúnẸ̀rún. BéèBẹ́ẹ̀ náà lomólọmọ́ sorí nínú èdè Naro, G//ana, G/ui àti ‡Haba.
 
IBÁ ÌSÈLÈÌṢẸ̀LẸ̀
 
Mana nìkan ni ó ń lo ibá ìsèlèìṣẹ̀lẹ̀ gégégẹ́gẹ́ònàọ̀nà ìsèdáìṣẹ̀dá (Morphological Category) ó sì ya ibá ìsèlèìṣẹ̀lẹ̀ asetánaṣetán sótòsọ́tọ̀àìsetánàìṣetán
 
 
Ìlà 149:
IYISODI
 
ÈrúnẸ̀rún tàbí àfòmóàfòmọ́ èyìnẹ̀yìn ni wonwọn n lo fún ìyísódì (Khoekhoe tam; G//ana G/ui àti ‡Haba tàmátema) n lò èrúnẹ̀rún fún ìyísódì nígbà tí (kxoe //Am. Buya-bé) n lo afomoafọmọ eyinẹyin, nígbà mìíràn wónwọ́n n lo méjèèjì.
Ètò ÒròỌ̀rọ̀
Ètò òròọ̀rọ̀àwonàwọn èdè Khoisan ti à ń sosọ wònyíwọ̀nyí máa ń lò ni (Svo-Subject-Verb-Object) Olùwà òròọ̀rọ̀-ìseìṣe àti àbòàbọ̀ tàbí (Sov-Suject-Object-verb).
 
ÒròỌ̀rọ̀ Èdè (Vocabulary)
 
Àfihàn ìgbésí ayé àwonàwọn olùsoolùṣọ èdè Khoisan ni òròọ̀rọ̀-èdè (Vocabulary) wonwọn jéjẹ́. Ní ìwònìwọ̀n ìgbà tí àwonàwọn olùsoolùṣọ èdè wònyíwọ̀nyí ń gbé pòpọ̀ pèlúpẹ̀lú àwonàwọn ìsèdáìṣẹ̀dá mìírà, èyí mú kí wónwọ́nàwonàwọn òròọ̀rọ̀-èdè tí ó súnmósúnmọ́ odeọdẹ síseṣíṣe, erankoẹranko, Kóríko àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ.
 
ÀKỌ́SÍLẸ̀
ÀKÓSÍLÈ
ÒpòỌ̀pọ̀ àwonàwọn èdè wònyíwọ̀nyí ni kò ni àkosílèàkọsílẹ̀ sùgbónṣùgbọ́n Nama ati Naro ni àkosílèàkọsílẹ̀ àti ohun èlò ìkóniìkọ́ni. Nama ní pàtàkì ti wà ní àkosílèàkọsílẹ̀ láti ojóọjọ́ pípépípẹ́.
 
 
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Koisaanu"