Lítíréṣọ̀: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Legobot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 1 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q8242 (translate me)
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 3:
'''Litireso''' tabi '''iṣẹ́ọnàmọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà'''
 
OHUN TÍ LÍTÍRÉSÒLÍTÍRÉṢỌ̀ JÉJẸ́
Eléyìí náà kò sàìṣàì ní orírun tirètirẹ̀ láti inú [[ede Latin|èdè Látìn]] “LITERE” Èyí ni àwonàwọn géésìgẹ́ẹ́sìwowọ inú èdè wonwọnwónwọ́n ń pè ni lete rature”
ÌtumòÌtumọ̀ tí a fún lítírésòlítíréṣọ̀ máa ń yípadà láti òdòọ̀dọ̀ èyàẹ̀yà ènìyàn kan sí èkejì láti ìgbà dé ìgbà. LítírésòLítíréṣọ̀ kò dúró sójú kan.
BabaloláBabalọlá (1986), sàpèjúweṣàpèjúwe lítírésòlítíréṣọ̀ pé:
 
“Àkójopò“Àkójọpọ̀ ìjìnlèìjìnlẹ̀ òròọ̀rọ̀ ní èdè kan tàbí òmíràn tó jásí ewì, ìtàn àlóàlọ́, ìyànjú, eré onítàn, ìròyìn àti eré akónilógbónakọ́nilọ́gbọ́n lórí ìtàgé”
 
Tí a bá wo òde òní, ìtumòìtumọ̀ tí a fún lítírésòlítíréṣọ̀ tún yàtòyàtọ̀, fún àpeereàpẹẹrẹ a máa ń sàkíyèsíṣàkíyèsí ìlò èdè tí wónwọ́n fi kokọ ìwé kan yàtòyàtọ̀ sí èyí, a tún ka lítírésòlítíréṣọ̀ kùn iséiṣẹ́ ònkòwéòǹkọ̀wé alátinúdá tàbí iséiṣẹ́ tó ní í seṣe pèlúpẹ̀lú òròọ̀rọ̀ ìlò ojú inú gégégẹ́gẹ́ bí ewì, ìtàn àròkoàròkọ àti eré oníseoníṣe. A ó sì rí i pe awéawẹ́ tàbí èyàẹ̀yà lítírésòlítíréṣọ̀ tí a mènubàmẹ̀nubà wònyíwọ̀nyípúpòpúpọ̀ nínú ìmòìmọ̀ ìgbé èdáẹ̀dá láwújoláwújọ (folklore) mómọ́ ara, yálà, a kokọ, óọ́ sílèsílẹ̀, a rò ó sosọ tàbí a seṣe é léré yàtòyàtọ̀ fún àwonàwọn àkoóàkọọ́ lèlẹ̀ iséiṣẹ́ owóọwọ́.
LítírésòLítírésọ̀ tún jéjẹ́ irúféirúfẹ́ àkoólèàkọọ́lẹ̀ tó ní àbùdá èmíẹ̀mí gígùn, ó máa ń fi ìsèseìṣẹ̀ṣe àti àsààṣà àgbáríjoàgbáríjọ àwonàwọn èèyàn kan hàn.
ÀwonÀwọn míràn tó tún sòròsọ̀rọ̀ lórí lítírésòlítíréṣọ̀ ni àwonàwọn omoọmọ léyìnlẹ́yìn Mark: ÀwonÀwọn Marxist (1977) yìí gbà pé:
 
“Scrutiny of the literature could not be realize without the society”
Ìlà 19:
Èyí ni pé:
 
“Lítírésò“Lítíréṣọ̀ kò lè seṣe é dá yèwòyẹ̀wò láìwo àwùjoàwùjọ tí a kokọ óọ́ fún”
 
ònkòwéòǹkọ̀wé kan tó lè se iséiṣẹ́ rèrẹ̀àseyanjúàṣeyanjú, irúféirúfẹ́ onkòwéoǹkọ̀wé náà gbódògbọ́dọ̀ ni àtinúdá àtinúdá yìí pèlúpẹ̀lú ohun gan-an tí ó ń selèṣelẹ̀ láwùjoláwùjọ ni yóò wá sosọ di òkanọ̀kan nínú iséiṣẹ́ rèrẹ̀.
Lara àwonàwọn tí ó siséṣiṣẹ́ lórí ìlànà Marx yìí ni: Trosky ara Russia, Lucas àti Goldmann.
Daviguand (1960) ni tíórìtíọ́rì sosọ
 
“Literature enumerate the future thought of an individual (Human being)
Ìlà 29:
Èyí ni pé:
 
“Lítírésò“Lítíréṣọ̀ wà fún láti máa so èrò okànọkàn ènìyàn jáde nípa ojóọjọ́ iwájú”
 
Nípa yíyeyíyẹ lítírésòlítíréṣọ̀ wò, à ní láti wo èhunẹ̀hun ìpìlèìpìlẹ̀ ìtumòìtumọ̀, èyí ni wíwo gbogbo nnkannǹkan tí ó wà láwùjoláwùjọ yenyẹn olápapòolápapọ̀ láì dá òkanọ̀kan sí.
 
==E tun wo==