Orílẹ̀-Èdè Yorùbá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k Poarps ṣeyípòdà ojúewé Orile-Ede YorubaOrílẹ̀-Èdè Yorùbá
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 1:
[[OrílèOrílẹ̀-Èdè Yorùbá]]
orílèorílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àwonàwọn ènìyàn Yorùbá wà káàkiri ìpínlèìpínlẹ̀ bí i mésànmẹ́sàn-án. ÀwonÀwọn ìpínlèìpínlẹ̀ náà ni EdóẸdó, Èkó, Èkìtí, Kogí, Kúwárà, Ògùn, Òndò, ÒsunỌ̀ṣun àti ÒyóỌ̀yọ́.
Lóde òní, Yorùbá wà káàkiri ilèilẹ̀ àwonàwọn aláwòaláwọ̀ dúdú (Áfíríkà), AméríkàAmẹ́ríkà àti káàkiri àwonàwọn erékùsù tí ó yí òkun Àtìlántíìkì ká. Ní ilèilẹ̀ aláwòaláwọ̀ dúdú. A le ríwonríwọn ní Nàìjíríà, Gáná, OrílèOrílẹ̀-Olómìnira BènèBẹ̀nẹ̀, Tógò, Sàró àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ. Ní ilèilẹ̀ AméríkàAmẹ́ríkà àti àwonàwọn erékùsù káàkiri, a lè rí wonwọn ní jàmáíkà, Kúbà, Trínídáádì àti Tòbégò pèlúpẹ̀lú Bùràsíìlì àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ.
YàtòYàtọ̀ sí ètò ìjobaìjọba olósèlú àwarawa tí ó fi gómìnà jejẹ olórí ní ìpínlèìpínlẹ̀ kòòkankọ̀ọ̀kan, a tún ní àwonàwọn obaọba aládé káàkiri àwonàwọn ìlú nlánlá tí ó wà ní ìpínlèìpínlẹ̀ kòòkankọ̀ọ̀kan. DíèDíẹ̀ lára wonwọn ni ObaỌba ìbíní, ObaỌba Èkó, Èwí tí Adó-Èkìtì, Òbáró ti Òkéné, Aláké tí AbéòkútaAbẹ́òkúta, Dèji ti ÀkúréÀkúrẹ́, Olúbàdàn ti Ìbàdàn, Àtá-Ója ti ÒsogboÒṣogbo, SòúnSọ̀ún ti ÒgbòmòsóÒgbòmọ̀ṣọ́ ati Aláàfin ti ÒyóỌ̀yọ́.
BaálèBaálẹ̀tirètirẹ̀ jéjẹ́ olórí ìlú kékeré tàbí abúlé. Ètò ni ó sosọ wónwọ́n di olórí ìlú kéréje nítorí pé Yorùbá gbàgbógbàgbọ́ pé ìlú kìí kéré kí wónwọ́n má nìí àgbà tàbí olórí. Aláàfin ni a kókókọ́kọ́ gbógbọ́ pé ó sosọ àwonàwọn olórí báyìí di olóyè tí a mòmọ̀baálèbaálẹ̀.
LábéLábẹ́ àwonàwọn olórí ìlú wònyíwọ̀nyí ni a tún ti rí àwonàwọn olóyè orísìírísìí tí wónwọ́niséisẹ́wónwọ́n ń se láàrín ìlú, egbéẹgbẹ́, tàbí ìjoìjọ (èsìnẹ̀ṣìn). Lára irú àwonàwọn oyè béèbẹ́ẹ̀ ni a ti rí oyè àjewòàjẹwọ̀, oyè ogun, oyè àfidánilóláàfidánilọ́lá, oyè egbéẹgbẹ́, oyè èsìnẹ̀ṣìn àti oyè ti agboolé bíi Baálé, Ìyáálé, AkéwejèAkéwejẹ̀, Olórí omoọmọ-osú, Ìyá Èwe Améréyá, MógàjíMọ́gàjí àti béèbẹ́ẹ̀ béèbẹ́ẹ̀ lolọ.