Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Orin sákárà"

107 bytes removed ,  13:52, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017
k
replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
k (Poarps ṣeyípòdà ojúewé Orin sakaraOrin sákárà)
k (replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents)
 
Ìfáàrà
ÈdáẸ̀dá ìtàn méjì ní a gbógbọ́ tí ó ròrọ̀ mómọ́ bí eré Sákárà seṣe bèrèbẹ̀rẹ̀. OkanỌkan ní pé ni ìlú ÌlorinÌlọrin ní Sákárà tí bèrèbẹ̀rẹ̀ láti owóọwọ́ àwonàwọn Mùsúlùmí kan, kí a to mú un wá sí Ìbàdàn lásìkò BaálèBaálẹ̀ Sítú tí ó jéjẹ́ Olúbàdàn láàrin odúnọdún 1914 sí 1925. ÈdàẸ̀dà ìtàn kejì ní pé eré kerekérè ni ó pilèpilẹ̀ eré Sakárà láti owóọwọ́ Abúdù, tí ó jéjẹ́ omoọmọ Yorùbá kan tí ó ń seṣe àtìpó ní ìlú Bídàá ní ìpínlèìpínlẹ̀ Náíjà. ...
 
[[Agan]]
==Orin Àgan ==
ÀwonÀwọn orin kán wà ni ilèilẹ̀ Yorùbá tí wónwọ́n ń kù lolọ. WónWọ́n ti fi ìgbà kan kári ilèilẹ̀ Yorùbá rí. Ní àsìkò yìí ìlú kòòkankọ̀ọ̀kan ní a ti ń rí wonwọn. WonWọn ò tilètilẹ̀ kárí ekùẹkù kan mómọ́. IrúféIrúfẹ́ àwonàwọn orin náà fara pépẹ́ òrìsàòrìṣà kan pàtó. Ìlú tí èsìnẹ̀sìn òkèrè bá ti gba èsìnẹ̀ṣìn ìbílèìbílẹ̀ lówólọ́wọ́ wonwọn, dandan ni kí irú orin béèbẹ́ẹ̀pèlúpẹ̀lú èsìnẹ̀sìnwónwọ́n gbé jù sílèsílẹ̀....
 
Ìfáàrà
Ìtara àti ìtaníjí nínú èsìnẹ̀sìn Mùsùlùmí ni a gbógbọ́ìpilèsèìpilẹ̀ṣẹ̀ eré ajíwéré, nígbà tí àwonàwọn olúfokànsìnolúfọkànsìn kan máa ń lolọ káàkiri àdúgbò ní ìdájí láti jí àwonàwọn Mùsúlùmí lati kírun àáròàárọ̀. Èyí ni aáyan láti má jéjẹ́àwonàwọn ènìyàn sùn gbàgbera, kí wonwọn sì jí wéré láti sàdúràṣàdúrà òóròòórọ̀....
 
[[Juju]]
==Orin Jùjú ==
 
==ÀwonÀwọn ohun èlò eré Jùjú==
Nígbà ti eré Jùjú bèrèbẹ̀rẹ̀, àwonàwọn ohun èlò tí àwonàwọn òsèréòṣèré n lò ni: báńjò, sèkèrèṣẹ̀kẹ̀rẹ̀, samba àti ‘jùjú’ (àsìkò). Nígbà tí wonwọn kò lo gìtá alápòótí momọwónwọ́n bèrèbẹ̀rẹ̀ síí lo báńjò. ÀwonÀwọn ohun-èlò ìbíléìbílẹ́wónwọ́n tún mú wowọ inú eré Jùjú ni gágan, sákárà tàbí orùn ìsàìṣà, gudugudu, agogo, àgídigbo tàbí móló. ÀwonÀwọn ohun-èlò ìgbàlódé tí a mú wónúwọ́nú eré Jùjú ní gìtá, òpòọ̀pọ̀ ìlú alásopòalásopọ̀enìkansosoẹnìkanṣoṣo máa ń lù, bóńgò, kóńgà, èroẹ̀rọ gbohùngbohùn, míkísà, búsítà, àkódíònùàkọ́díọ̀nù àti dùùrù àfenufonàfẹnufọn, nígbà kan rí. ...
 
[[Igbagbo Yoruba nipa ajodun ibile]]
[[Ero Yoruba nipa ajodun ibile]]
 
==Orin nínú odúnọdún ìbílèìbílẹ̀ ==
 
==Èrò àti ìgbàgbóìgbàgbọ́ Yorùbá nípa àjòdúnàjọ̀dún ìbílèìbílẹ̀==
ÀjòdúnÀjọ̀dún ìbílèìbílẹ̀ jéjẹ́ mómọ́ bíbobíbọ òrìsàòrìṣà kan tí àwonàwọn olùsìn rèrẹ̀ fi ń wájú móramọ́ra tàbí láti fi bèbèbẹ̀bẹ̀ tàbí san èjéẹ̀jẹ́ lódòlọ́dọ̀ rèrẹ̀. Gbogbo ìwònyíìwọ̀nyí wà fún síseṣíṣe ìféìfẹ́ rèrẹ̀. ÀjòdúnÀjọ̀dún ìbílèìbílẹ̀ tún lè wà fún ìrántí asáájuaṣááju tàbí akoniakọni kan, bóyá tí ó tetẹ ìlú kan dó, tàbí tí ó jagun kan láti gba àwonàwọn ènìyàn rèrẹ̀ sílèsílẹ̀ lówólọ́wọ́ òtáọ̀tá tàbí lówólọ́wọ́ ibi tàbí ìjànbáìjàǹbá kan, tàbí tí ó seṣe ohun mánigbàgbé kan tí wonwọn fi ń ránti rèrẹ̀ tàbí tí wónwọ́n fi ń sopéṣọpẹ́ fún un, tí wónwọ́n sì tí ipa béèbẹ́ẹ̀ sosọ óọ́ di òrìsàòrìṣàwonwọn yóò máa bobọ, tí wonwọn yóò sì máa seṣe èyeẹ̀yẹ fún lódoodúnlọ́dọọdún tàbí lóòrèkóòrè. ...
 
[[Agbalogbabo lori orin Yoruba]]
[[Orin Yoruba]]
 
==ÀgbálogbábòÀgbálọgbábọ̀ lori orin==
 
==Ìwúlò orin Yorùbá==
Orin jejẹ ònàọ̀nà kan pàtàkì tí eníẹní tí ó korínkọrín fí ń gbé èrè-okànọkàn rèrẹ̀ jáde lórí ohun tí ń jejẹ éẹ́ lókànlọ́kàn, yálà nípa òròọ̀rọ̀ ara rèrẹ̀, òròọ̀rọ̀ elòmírànẹlòmíràn tàbí nípa òròọ̀rọ̀ kan láwùjoláwùjọ.
ÒkorinỌ̀kọrin lè fi orin mú iwúrí àti ìdùnu bá ara rèrẹ̀ tàbí elòmìírànẹlòmìíràn. GégéGẹ́gẹ́ bí alóre láwùjoláwùjọ, òkorinọ̀kọrin tàbí òsèréòṣèré lè fi orin gbé èdùnẹ̀dùn okànọkàn èrò àwùjoàwùjọ síta, èyí tí ìba máa fún ni ni ìnira tàbí ìtèmólèìtẹ̀mọ́lẹ̀ tàbí ìbánujéìbánujẹ́ abénuabẹ́nu, yálà láti owóọwọ́ ìjobaìjọba tàbí àwonàwọn alásealáṣẹ kan. Orin lè wá fún lílò ara-eniẹni tàbí tí àwùjoàwùjọ lápapòlápapọ̀. Orin lè mú ní sapá seṣe ohun tí ó dàbí eníẹní sòroóṣòroó seṣe fún ní nígbà mìíràn. ...
 
[[Orin apala]]
Ìfáàrà
Orin àpàlà jéjẹ́ òkanọ̀kan lára àwonàwọn orin Yorùbá ti wónwọ́n jéjẹ́ gbájúmògbájúmọ̀ ni agbègbè ègbáẹ̀gbá, ÌjèbúÌjẹ̀bú, ÒyòỌ̀yọ̀, ÒsunỌ̀sun àti Ìgbóminà. Orin ayeyeayẹyẹ ni orin àpàlà, orin ìgbàlóde ni pèlúpẹ̀lú. Orin àpàlà kò ní nnkannǹkan án se pèlúpẹ̀lú èsìnẹ̀sìn, òrìsà tàbí ìboìbọ kan tí a mòmọ̀ ni ilèilẹ̀ Yorùbá. Orin ìgbàféìgbàfẹ́ ni orin àpàlà....
 
==Orin Fújì ==
Ìfáàrà
Orin ìgbàlódé ni orin Fújì. Orin tó gbalágboko ni pèlúpẹ̀lú. ÀwonÀwọn ohun díèdíẹ̀ péréte ni a ó sòròṣọ̀rọ̀ lé lorí nínú orin yìí. A ó fi enuẹnu ba ohun èlò orin Fújì, àwonàwọn òkorinọ̀kọrin Fújì ìsàkósoìṣàkóso àti kókó tí Fújì ń dálé lórí. ...
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}
309

edits