Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 2:
==ÀKÙNGBÁ-ÀKÓKÓ==
ÀKÚNMI : ìsèlè tí o mu ìpayà wa sele ní àdúgbò yi ti o mu ki ìpàdé pàjáwìrì wáyé nílé Oba. Nígbà tí onísé yoo jísé fún oba ohun tí o kó so ni pé àkún mi eyi tí o túmò sip e Àkùn ni àdápè Àkùngbá sugbon nígbà tí ìsèlè yi mi gbogbo Àkìngbá ni won fi n so pe Akun mi ti won si waa so adugbo naa ní Akunmi lati ìgbà naa ni won ti n je olóyè ti a n pè ni Alákúnmù.
ÒKELÈ : Àwon jà-nǹ-dù-kú ènìyàn ni won fe àdúgbò yìí dó; Awon alo-kólóhun-kígbe, olè ati ìgára. Ibi ti won si tèdó si je ibi ti o ga sókè. Bi enikeni ba fee lo sí àdúgbò yi won a ni o lo òkè olè. Òkè olè ni won so di òkelè di òní-olónìí.
 
AKÙWÀ: Ìgbàgbó awon ènìyàn nip é awon to wa ni àdúgbò yi je òdàlè, atan-ni-je Àgàbàgebè ènìyàn ni won. Èdè Akungba ni Akuwa eyi ti o túmò sí pe ìwà nikan ni o kù won kù.
 
ÙBÈRÈ: Eni ti o kókó kó ilé ni ilú Àkùngbá Ùbèrè ni o ko o sí. Ibè ni àwon ènìyàn sì gbàgbó pe Àkùngbá ti se wá Ibè ni olóyè àkókó ti je. Idi niyi tí wón fi ń pè é ni Ubere-ibi ti nnkannǹkan ti bèrè tàbí sè.
 
OKÙSÀ: Orúko eni tí o kókó kó ilé ni àdúgbò yí ni a fi n pèé. Òhun ni won n pè ni Okusa. Ìdílé re ni won ti n je oye olókùsà.