Orúkọ Àdúgbò ní Ìjẹ̀bú-Igbó, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Ìlà 17:
 
6. Àdúgbò: Itún alágbède-itúnlágbède
Ìtumò: Itún ni èdè Ìjèbú je “Agbo ilé”. Ó sì jé ibi ti àwon alágbèdealágbẹ̀dẹ pò sì, bí àwon enìyàn bá sì fé júwe àdúgbò lati agbo ilé yìí, won a ni e lo sí itún alágbède, tí ò sì di itúnlágbède di oni yìí.
 
7. Àdúgbò: Asìsgbìdì
Ìlà 86:
 
27. Àdúgbò: Òkè ìfé
Ìtumò: Orí òkè kan wà ti àwon àlejò ti wón ba sèsè wo inú ìlú ti máa ń lo búra wí pé àwon kò ni se búburú sí Oba ati àwon omo onílùú Orisìrìsi àwon èyà enìyàn ni won máa ń pàdé ni orí oke yìí ni asìko ìbúra náà, Ègbá, ìbàdàn Òyó. Hausa, Ìgbò, abbl. Orò ajé ni ó gbe won wá sí ìlú náà (Ìjèbú Igbó). Ní gbà tí ó se Oba se akiyesi wí pé gbogbo àwon àlejò wònyí ń se bí omo ìyá kan náà, a fi bi eni pe ile kan ni gbogbo won ti wá. Láì fa òrò gùn, àwon àlejò yìí ń pò sí, won ń bí sí i, won ń rè sí, ìlú sì kún to béè géè tì onílé kò mo àlejò mó. Ní ojo kan, Ob ape gbogbo àwon àlejò ìlú jo tèbí tàráawon, Ó sì so fún won wí pé òun ríi pé won ni ìfé ara won, lati òní lo, òun (Oba) yàn-nǹ-da orí òkè tì wón tì bura ni ojósí fún won, ki won ko àwon enìyàn won ki wón lo tèdó sí ibè.
Gbogbo àwon àlejò wònyí sì dupe lówó oba. Won sì se bi Oba ti wí. Lati Igba náà ni won ti so àdúgbò náà di orí òkè ìfé ti o di “Òkè Ìfé” loni yìí.
 
28. Àdúgbò: Atìkòrì
Ìtumò: Ní ayé atijo, ìko tìí wón fi ń hun eni ni ó pò ni àdúgbò yìí. Bàbá kan wà ti o je ògbóntagíògbóǹtagí onísègùn; ìko ni o máa ń fi ríran sí àwon ènìyàn. ohun kohun ti ènìyàn bá bá lo si òdò rè ìko yìí ni ó máa kó kalè ti yóò sì máa ba sòrò bí ènìyàn; sùgbón ohun nìkan ni o máa ń gbo èdè tì ìko náà ń so, òun yóò wa túmò fún eni tí ó wa se àyèwò. Ní ìdí èyí, won so “Baba’yìí ni “Ati ìko ri ohun ti o ń sele si ènìyàn” ti o di “Atìkorí nigba ti awon ènìyàn tèdó si àdúgbò náà. Lónìí Atìkòrì ni àwon ènìyàn ń pè é.
 
29. Àdúgbò: Odòdóoróyè