Orúkọ Àdúgbò ní Ìjẹ̀bú-Rémo, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 18:
 
Àdùgbò: Ìdómolè
Itumò: Nítorí àgbára àti ìwa ìpànleìpàǹle tàbí ìwà jàgídíjàgan okunrin kan báyìí ti a pe orùko rè ní Ìdó ni àsìkò Ojoun ni a se so oruko adugbo yìí ní Ìdómolè léyìn ikù okunrin yìí ni awon ènìyàn bérè sì fi okunrin yìí júwè adúgbò ré. Won a ní awon n lo sí Ìdó akínkayú nì tàbí okùnrin imolè nì. Báyìí ni a kuku so adúgbà di Ìdómolè.
 
Àdùgbó: Ìròlù
Ìlà 24:
 
Àdugbò: Sáàpàdé
Itumò: Àwon ìlu méta ni ó parapò sí ojú kan. Nígbà tí ó wà di wì pé okan kò yòndayòǹda oruko tirè oún èkèjì ni wón wà yo nínú oruko awon meteeta; làti yo sàaàpàde
Ìsarà – láti ibi ni wón ti yo ‘sá’
Ìparà – láti ibi ni wón ti yo oá’