Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Òwò ẹrú (Brasil)"

377 bytes removed ,  13:53, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017
k
replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
k (Poarps ṣeyípòdà ojúewé Owo eru (Brazil)Òwò ẹrú (Brasil))
k (replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents)
 
[[ADEYEMO AKINLOYE STEVE ]]
ÀKÓSÍLÈÀKỌ́SÍLẸ̀ DÍÈDÍẸ̀ LÓRÍ I ÌGBÉ AYÉ OMOỌMỌ YORÙBÁ ILÈILẸ̀ BRAZIL KAN TÍ Ó FI ÌGBÉ AYÉ RÈRẸ̀ TAKO ÒWÒ ERÚẸRÚ (LÁTI OWÓỌWỌ́ : ASA J. DAVIS)
 
Alága, gbogbo èyinẹ̀yin òfòòkùnọ̀fọ̀ọ̀kùn, iyì nláńlá ni fún mi láti wà ní ìjókòó lónìí láti sòròsọ̀rọ̀ lórí ‘Ìlàjú Yorùbá’. Bí ó tilètilẹ̀ jéjẹ́ pé mo siséṣiṣẹ́ rí ni ogbàọgbà Fásitì Ìbàdàn, n kò rò wí pé mo yeyẹ ní emi tí ó lè máa ka àpilèkoàpilẹ̀kọ lórí òròọ̀rọ̀ Ìlàjú Yorùbá, mo lè ti seṣe àwonàwọn ìwádìí tí ó jejẹ mómọ́ àkòrí yìí lóòótólóòótọ́ fún àwonàwọn àkókò kan. Bí a bá fi ojú inú wo òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwa àtòhúnrìnwáàtọ̀húnrìnwá ni a ti nń seṣe ìwádìí orírun wa dé ilèilẹ̀ Yorùbá.
ÒpòỌ̀pọ̀ oníwádìí ìjìnlèìjìnlẹ̀ ni wónwọ́n kokọ ìpàkóìpàkọ́ sí ìwádìí òpin òròọ̀rọ̀ erúẹrúilèilẹ̀ Brazil bí o tilètilẹ̀ jéjẹ́ wí pé gbogbo ogbónọgbọ́n àlùmòkóróyíàlùmọ̀kọ́rọ́yí àti agídí paraku lórí òwò ni ó mú àwonàwọn elénuugbòròẹlẹ́nuugbọ̀rọ̀ dìde láti máa tako òwò erúẹrúilèilẹ̀ Brazil. A gbódògbọ́dọ̀ mòmọ̀ láti ilèilẹ̀ wí pé àti dúdú àti funfun ni wónwọ́n jojọ pa owóọwọ́ pòpọ̀ gbé ogun tí òwò erúẹrú sùgbónṣùgbọ́n òpòọ̀pọ̀ ni kò fi ara mómọ́ àtakò yìí.
ÒkanỌ̀kan nínú àwonàwọn tí ó tako òwò erúẹrú yìí jéjẹ́ omoọmọ Yorùbá ilèilẹ̀ Brazil kan. E jéjẹ́ kí á wo ìsèlèìsẹ̀lẹ̀ yìí:
 
ojóọjọ́ kan erúẹrú aláwòaláwọ̀ dúdú kan jáde ni ilé olówó rèrẹ̀, ó sì lolọòdòọ̀dọ̀ agbejóròagbejọ́rò aláwòaláwọ̀ dúdú kan pèlúpẹ̀lú owóọwọ́agbéjóròagbẹ́jọ́rò yìí yóò lò láti soósọọ́ di òmìnira. Tohùn-tenuètẹnuè ni bàbá olówó erúẹrú wowọ inú OófíìsìỌọ́fíìsì agbejóròagbẹjọ́rò òréọ̀rẹ́ e rèrẹ̀ yìí tí ó sì bèrèbẹ̀rẹ̀ sí í bèèrè lówólọ́wọ́ erúẹrú yìí, ìdí tí ó fi féfẹ́ fi òun sílèsílẹ̀. Ó sosọ síwájú wí pé òun nń tétẹ́ e lórùnlọ́rùn àti wí pé kò yeyẹ kí ó ba inújéinújẹ́ rárá níwònníwọ̀n ìgbà tí oun ti nń seṣe bíi baba fun-un. Ní tòótótòótọ́ erúẹrú yìí nńìtójúìtọ́jú kò sì sí ìdí fún-un láti kùn rárá, ìdí nìyí tí erúẹrú yìí kò fi rí àtakò kankan fún òròọ̀rọ̀ olówó rèrẹ̀ yìí. SùgbónṢùgbọ́n ní ìgbà tí agbejóròagbẹjọ́rò yìí rí i wí pé erúẹrú yìí kò rí ìdáhùn ni ó bá fofọ èsì wí pé : ní tòótótòótọ́ erúẹrú yìí yóò gba ìtúsílèìtúsílẹ̀ nítorí pé kò ní òmìnira láti ba inú jéjẹ́ bí ó seṣe wù ú. Báyìí ni erúẹrú yìí seṣe gba ìtúsílèìtúsílẹ̀.
 
Ó sì ba ni lókànlọ́kàn jéjẹ́ wí pé àwonàwọn erúẹrúowóọwọ́ tètẹ̀ padà léyìnlẹ́yìn ìgbà tí wónwọ́n bá ti sá lolọ ni wónwọ́n nń pa, ìdí nìyí tí ònkòwéòǹkọ̀wé yìí seṣe kokọ óọ́ sílèsílẹ̀ pé:
ÀwonÀwọn ènìyàn dúdú mérinmẹ́rin yìí, tí àwonàwọn ènìyàn nń tì ní ìtìkutì (àbí kí á sosọ wí pé tí àwonàwọn igun nń tì ní ìtìkutì) kìí seṣe ènìyàn lasan o; ìràwòìràwọ̀ mérinmẹ́rin ni wónwọ́n, ìmólèìmọ́lẹ̀ mérínmẹ́rín ni wónwọ́n, béèbẹ́ẹ̀ sì ni ìròrí mérinmẹ́rin ni wonwọn pèlúpẹ̀lú. Láàrin rògbòdìyàn ni a sosọ wónwọ́n di eruku, tí ó bá sì di ojóọjọ́ iwájú àwonàwọn òjògbónọ̀jọ̀gbọ́n yóò kokọ nípa wónwọ́nàwùjoàwùjọ àwonàwọn ìràwòìràwọ̀ àti àwonàwọn oòrùn.
 
ÀwonÀwọn ènìyàn kò sì seṣe béèbẹ́ẹ̀ kokọ àkosílèàkọsílẹ̀ àwonàwọn ènìyàn dúdú tí ó ní owóọwọ́ nínú òwò erúuẹrúu rèrẹ̀, ìwònbaìwọ̀nba èyí tí a sì rí ni ó wá láti òdòọ̀dọ̀ aláwòaláwọ̀ funfun àti wí pé ìwònbaìwọ̀nba péréte ni àwonàwọn aláwòaláwọ̀ dúdú tí a kokọ àkosílèàkọsílẹ̀ wonwọn.
ÀwonÀwọn aláwòaláwọ̀ funfun kò kokọ ibi ara sí òròọ̀rọ̀ Luiz Gama, wonwọn kìí sì sáábà fonfọn rere rerẹ rárá sùgbónṣùgbọ́n ìrìn-àjò rèrẹ̀ láti erúẹrú lásán di olókìkí ènìyàn ni ó yeyẹ kí á kokọ ibi ara sí ju bí a ti seṣe yìí lolọ.
Abala méjì ni ó wú mi lórí jù nínú ìgbé ayé Gama; àkókóàkọ́kọ́ ni dídàgbà rèrẹ̀ nínú òfíì àti òláàọ̀láà. Ní àsìkò yìí ni ó wá ìyá a rèrẹ̀ tì, tí a sì ta òun náà sí oko erúẹrúònàọ̀nà àìtóàìtọ́. Èkejì ni ìlàkàkà rèrẹ̀ láti tako òwò erúẹrú ní àsìkò tí òpòọ̀pọ̀ ènìyàn nń fàdí séyìnsẹ́yìn.
SùgbónṢùgbọ́n ju gbogbo rerẹ lolọ, ìgbé ayé Gama yàtòyàtọ̀ tààrà pèlúpẹ̀lú u bí ó ti jéjẹ́ agbenusoagbẹnusọ fún ènìyàn dúdú àti eniẹni tí ó gba ara rèrẹ̀ là fúnra ara rèrẹ̀.
Ó seṣe ni láàánú wí pé ògbémiọ̀gbẹ́mi yìí kò fi béèbẹ́ẹ̀ sosọ púpòpúpọ̀ nípa ìtàn ìgbésí ayé ara rèrẹ̀, léyìnlẹ́yìn díèdíẹ̀ tí a mòmọ̀ láti ara ìwé kan tí ó kokọ nípa ìtàn ìgbésí ayé e rèrẹ̀.
A bí Gama ní ojóọjọ́ kejìdínlógbònkejìdínlọ́gbọ̀n osù kefàkẹfà odúnọdún 1830 (28/6/1830) ní ìlú Sao Salvador. Luiza Mahin, Ànàgó (Olómìnira) ni ìyá a rèrẹ̀ sùgbónṣùgbọ́n òyìnbó Potogí tí ó ní owó lówólọ́wọ́ ni bàbá rèrẹ̀. Gama kò sosọ orúkoorúkọ bàbá rèrẹ̀ síta sáṣá.
Tí a bá wo àyíká tí a ti bí Gama, a ó rí i wí pé ní tòótótòótọ́ ni, ti àwonàwọn ènìyàn bá pè é ní “àyà koko ni ti Ìnàkí”, “kìí –gbó–gbọ́-kìí-gbà”, “oníròbínúje“oníròbínújẹ okàn”ọkàn” àti béèbéèbẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lolọ. SùgbónṢùgbọ́n Rui Brabosa pè é ní “eni“ẹni tí kìí seṣe ojo rara”. Tí a bá sì fééfẹ́ẹ́ momọ ohun tí ó bí àwonàwọn àpèjeàpèjẹ yìí, a gbódògbọ́dọ̀ kokọ ibi ara sí gbogbo ohun tí ó dìròdìrọ̀ mómọ́ ìbí rèrẹ̀ àti ìdàgbàsókè rèrẹ̀.
àkókóàkọ́kọ́, a bí Gama ní àsìkò tí àwonàwọn àyípadà kan bèrèbẹ̀rẹ̀ sí í dé sí Brazil léyìn tí Brazil yoyọ kúrò ní oko erúẹrú (1840-1889). ÀwonÀwọn àyípadà tí ó bèrèbẹ̀rẹ̀ sí ní dé bá ilèilẹ̀ Europe fúnra rèrẹ̀ nń seṣe àkóbá fún Brazil ní àsìkò yìí. Ní àfikún, ní àárìn àwonàwọn aláwòaláwọ̀ dúdú, àsìkò yìí ni dúkùú nń wáyé láti òdòọ̀dọ̀ àwonàwọn dúdú lórí ìlòdì sí òwò erúẹrú. Àsìkò yìí gan-an tí gbónmigbọ́nmi-síi, omi-ò-tóo nń wáyé ní ìlú rèrẹ̀, Bahia lórí òròọ̀rọ̀ òwò erúẹrú yìí ní pàtàkì. Ibi Gama si papòpapọ̀ mómọ́ rògbòdìyàn tí àwonàwọn omokùnrinọmọkùnrin gbé dìde ní odúnọdún 1835, omoọmọ odúnọdún márùn-ún péré ni Gama ní àsìkò yìí.
ÒkanỌ̀kan nínú àwonàwọn ohun tí ó seṣe okùnfà irú ìgbé ayé tí Gama gbé ni rògbòdìyàn ìlú rèrẹ̀ tí a dà pè ní Incon fidecia da Bahia (rògbòdìyàn ìlú Bahia) eléyìí tí ó ti bèrèbẹ̀rẹ̀ bíi OgbònỌgbọ̀n odúnọdún kí á tó bí Gama. Èyí sì mú àwonàwọn ènìyàn ìlú Brazil ní èmíẹ̀mí ní ìgbà náà.
BéèBẹ́ẹ̀ sì ni a ríi kà wí pé àwonàwọn ènìyàn pàtàkì orílè èdè Brazil kan ti gba èkóẹ̀kọ́ ní orílè èdè Europe níbi tí ìròrí àwonàwọn ènìyàn ti kún fún ìgbòmìnrira. ÈyíẸ̀yí sì ni àwonàwọn ènìyàn mú bòbọ̀ wá sí ilé ní àsìkò yìí.
ÀwonÀwọn nnkannǹkan mìíràn tí ó dá òtèọ̀tẹ̀ sílèsílẹ̀ ni bí àwonàwọn olówó kò seṣe jéjẹ́ kí tálákà ó ní àti bí àwonàwọn omoọmọ Brazil kò seṣe rí ààyè nínú ipò gíga ilé ìjósìnìjọ́sìn. ÀwonÀwọn omoọmọ Brazil gan-an tún nń bá ara wonwọn jà ní àtàrí àwòàwọ̀ dúdú àti àwòàwọ̀ funfun. ÒpòỌ̀pọ̀ ìgbà ni wónwọ́n sì máa nń déyedẹ́yẹ sí dúdú níbi àti dé ipò gíga, èyí sì nń bí dúkùú àti òtèọ̀tẹ̀ ní àsìkò yìí.
Òmíràn nínú ohun tí a fi sàmì ìgbé ayé Gama ni rògbòdìyàn 1835, Ohun tí ó bí òtèọ̀tẹ̀ yìí ni bí àwonàwọn aláwòaláwọ̀ dúdú tí ó jéjẹ́ elésìnẹlẹ́sìn Islam kan seṣe kó ara wonwọn jojọ láti gba ìjobaìjọba lówólọ́wọ́ àwonàwọn ìjobaìjọba ilèilẹ̀ Brazil. Ìjà yìí jéjẹ́ ìjà èsìnẹ̀sìn (Jihad) tààrà. ÌjobaÌjọba ilèilẹ̀ Brazil náà sì gbé ojú agan sí àwonàwọn èèyàn yìí tààrà. Ní àsìkò yìí Gama jéjẹ́ eniẹniodúnọdún mérinmẹ́rin péré. Látàrí rògbòdìyàn yìí, ìjobaìjọba ilèilẹ̀ Brazil fi ohùn seṣe òkanọ̀kan láti wá ini kan ní ilèilẹ̀ Aáfíríkà tí wonwọn yóò kó àwonàwọn aláwòaláwọ̀ dúdú àárín wonwọn lolọ nítorí pé wónwọ́n nń da àlááfíà ìlú rú. EniẸniwónwọ́n bá sì gbá mú ní àtàrí rògbòdìyàn yìí, pípa ni wónwọ́n nń pa wónwọ́n tàbí kí wonwọn fún wonwọnegbaẹgba lópòlopòlọ́pọ̀lọpọ̀, wonwọn a sì tún máa tì wónwọ́n momọ túúbú. Ó sì sòro fún omoọmọ tí kò tíì pé odúnọdún méfàmẹ́fà ní àsìkò yìí láti gbé ojú kúrò ní ìyà àjekúakátáàjẹkúakátá yìí.
Rògbòdìyàn yìí sì fa ikú fún òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ aláwòaláwọ̀ dúdú nípa kíki okùn bòbọ̀ wónwọ́n lórúnlọ́rún. ÀwonÀwọn Obìnrin náà jejẹ nínú ìyà yìí. WónWọ́n fi ìyà jejẹ òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ nítorí pé wónwọ́n jéjẹ́ oreọrẹ àwonàwọn ànàgó lásán, wónwọ́n sì yin àwonàwọn mìíràn ní ìbonìbọn pa.
Kì í seṣe egbaẹgbawónwọ́n nń fún àwonàwọn ènìyàn gan-an ni ó seṣe àkóbá fún Luiz Gama ní ìgbà èwe, sùgbónṣùgbọ́n bí iye egbaẹgba náà seṣe pòpọ̀ tó ní ojúmo kan.
Nítorí wí pé wonwọn a máa na elòmíràn ní egbaẹgba bíi àádòtáàádọ̀tá lójúmólójúmọ́; àwonàwọn ènìyàn tí wónwọ́ndájódájọ́ egbaẹgba fún sì pòpọ̀ gan-an. ÀwonÀwọn erúẹrú tí ó wà láàrin àwonàwọn ènìyàn yìí ni wónwọ́n dá padà fún olówó wonwọn léyìnlẹ́yìn ìjìyà wonwọn. Èyí tí kò bá sì lè siséṣiṣẹ́ dáadáa ni àwonàwọn olówó wonwọn tún tà padà fún elòmíràn.
ÌsèlèÌṣẹ̀lẹ̀ mìíràn òtòòtòọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí ó níí seṣe pèlúpẹ̀lú bí Gama seṣe dàgbà ni ó selèsẹlẹ̀ ní ìgbà tí ó wà ní omoọmọ odúnọdún méje. ÀwonÀwọn kan kó ara wonwọn jojọ, tí wónwọ́nìjobaìjọba gbà tipátipá sùgbónṣùgbọ́npépẹ́ìjobaìjọba fi ségunṣẹ́gun wonwọn pèlúpẹ̀lú ohun èlò ogun. WónWọ́n pe rògbòdìyàn yìí ní Sabinada. Ìdí ni wí pé Sabino ní ó síwájú rògbòdìyàn yìí, ó sì seṣe é seṣe kí bàbá Gama kópa nínú rògbòdìyàn yìí. Ní ìsojú Gama ni ilé jíjó, èèyàn pípa ati béèbéèbẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lolọ seṣe selèsẹlẹ̀ ní àsìkó rògbòdìyàn yìí. Inú n rògbodìyàn yìí ni ó ti wá ìyá rèrẹ̀ tì, tí bàbá rèrẹ̀ náà si báa run. Bí ó tilètilẹ̀ jéjẹ́wónwọ́n séṣé ìrìbomiìrìbọmi onígbàgbóonígbàgbọ́ fún Gama, kò fi èsìnẹ̀sìn Islam àti ìgbàgbóìgbàgbọ́ aláwòaláwọ̀ dúdú ìyá a rèrẹ̀ seréṣeré rára.
ÈkétaẸ̀kẹ́ta gbògíì nínú ohun tí ó seṣe okùnfà irú ìgbé ayé tí Luiz Gama gbé ni títà tí bàbá rèrẹ̀ tàá sí oko erúẹrú. Kékeré ni ojú rerẹ sì ti là sí ìyànjeìyànjẹ tí ìyá rèrẹ̀ máa n takò nígbà ayé rèrẹ̀. SùgbónṢùgbọ́n ó jéjẹ́ eníẹní tí ìyá rèrẹ̀ fi ìféìfẹ́ hàn sí láti kékeré. Títa lérúlẹ́rú rèrẹ̀ jéjẹ́ kí ó ní òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ìrírí tí ó dìròdìrọ̀ mómọ́ òwò erúẹrú. Ìdí ni wí pé òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni ó kòkọ̀ óọ́ sílèsílẹ̀ nítorí pé ìlú Bahama tí rògbòdìyàn pòpọ̀jùlojùlọ láti tako òwò erúẹrú ni Gama ti wá, èyí ni ó sì fàá tí òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn fi nń rà á ní àràtúntà. ÒkanỌ̀kan nínú àwonàwọn tí ó rà á lérúlẹ́rú ni Cardoso jéjẹ́, ní tòótótòótọ́ Cardoso fi ìyà jèjẹ̀ éẹ́ sùgbónṣùgbọ́n òun náà ni ó jéjẹ́ kí Gama ka ìwé.
odúnọdún 1848, Gama gba iséiṣẹ́ ológun léyìnlẹ́yìn ìgbà tí ó ti sa kúrò ní ipò erúẹrú, ó sì gba okùn méjì kí wónwọ́n tó lé e dànù nítorí wí pé ó gbé enuẹnuògáọ̀gá rèrẹ̀ kan. LéyìnLẹ́yìn tí ó kúrò nínú iséiṣẹ́ ológun, ó bá òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn siséṣiṣẹ́ sùgbónṣùgbọ́n àtakò òwò erúẹrú rèrẹ̀ nń jéjẹ́wonwọn ó lé e dànù kí wonwọn sì kà á kún aláìgborànaláìgbọràn àti alágídí ènìyàn.
odúnọdún 1864, òwò erúẹrú bèrèbẹ̀rẹ̀ sí í wá sí òpin díèdíèdíẹ̀díẹ̀ látarí owóọwọ́àwonàwọn ènìyàn àti ìjobaìjọba gbé láti mú kí òwò erúẹrú wá sí òpin. LéyìnLẹ́yìn àsìkò yìí, Gama bèrèbẹ̀rẹ̀ sí ní lówólọ́wọ́ sí títú òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ erúẹrú sílèsílẹ̀ ní Brazil, ó sì gbé òpòlopòọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbésè lórí òròọ̀rọ̀ yìí. Ní odúnọdún 1871, òfin tí ó fi owóọwọ́ìtúsílèìtúsílẹ̀ erúẹrú di gbígbà woléwọlé.
Ni gbogbo ìgbà tí àwonàwọn alásealásẹ bèrèbẹ̀rẹ̀ sí fi ara mómọ́ pípa òwò erúẹrú rérẹ́ díèdíèdíẹ̀díẹ̀, Luiz Gama kò fi ar amóamọ́ èyí, ó nń jà fitafita wí pé kí òwò erúẹrú paréparẹ́ káíkíá ni. Ìdí ni wí pé òpòọ̀pọ̀ ìgbà ni àwonàwọn alásealásẹ nń fi ojú òfin òwò erúẹrú gbo ilèilẹ̀ pèlúpẹ̀lú ogbónọgbọ́n àlùmòkóróyíàlùmọ̀kọ́rọ́yí. Luiz Gama tún mú òròọ̀rọ̀ yìí lolọ sí ilé ìgbìmòìgbìmọ̀ asòfinaṣòfin níbi tí wonwọn kò ti fi ara mómọ́ ìdándèìdáǹdè esèkesèẹsẹ̀kẹsẹ̀ fún gbogbo erúẹrú. Títí tí Gama fi kú ni 1882, àbá yìí kò tí ì di òfin.
Kí ó tó kú, ó tún dara pòpọ̀ mómọ́ ìwé ìròyìn kan tí ó n siséṣiṣẹ́ lákolákolákọlákọ láti tako òwò erúẹrú, orúkoorúkọ ìwé ìròyìn yìí ni Radical Paulistane ó sì siséṣiṣẹ́ kíkan kíkan pèlúpẹ̀lú ìwé ìròyìn yìí láti rí i wí pè òwò erúẹrú di ohun ìgbàgbé kíákíá.
ojóọjọ́ ketàlákẹtàlá, osùoṣù kárùn-ún odúnọdún 1888, tí ó jéjẹ́ odúnọdún kefàkẹfà léyìnlẹ́yìn ikú Luiz Ganzaga Pinto da Gama ni aba tí ó fagi lé òwò erúẹrú di òfin ní ilèilẹ̀ Brazil. SùgbónṢùgbọ́n ìgbéìgbẹ́ ayé Gama gégégẹ́gẹ́ bí amòfin, ònkòwéòǹkọ̀wé àti olósèlúolóṣèlú fi hàn gbangba pé eniẹni tí ó nífèénífẹ̀ẹ́ sí òmìnira terútẹrú-tomotọmọ ni. BéèBẹ́ẹ̀ gégégẹ́gẹ́ ni Frederick Douglass ní ilèilẹ̀ AméríkàAmẹ́ríkà pèlúpẹ̀lú Cugoana, Equiano, àti Antoine Amo seṣeilèilẹ̀ Europe. Gbogbo ìgbìyànjú àwonàwọn wònyíwọ̀nyí ni ó mú àyípadà rere wáyé ní séntúúrìséńtúúrì kokàndínlógúnkọkàndínlógún.
 
==Iwe ti a yewo==
309

edits