Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Síńtáàsì Yorùbá"

39 bytes removed ,  13:56, 13 Oṣù Kẹ̀sán 2017
k
replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
k (Poarps ṣeyípòdà ojúewé Sintaasi YorubaSíńtáàsì Yorùbá)
k (replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents)
 
(b) Àwon ti wón lo kò pò
 
Méjèèjì ni ó bófin mu nítorí méjèèjì ni a máa ń so nínú èdè Yorùbá. Ìyen ni pé méjèèjì ni ó wà nínú ìmò wa gégé bí eni tí ó gbó Yorùbá. Nínú ìlò ni àwon kan ti lè so pé òkan jé àtéwógbà, èkejì kò jé àtéwógbà. Èyé kò ni nnkennǹken kan án se pèlú pé bóyá gbólóhùn méjèèjì bófin mu tàbí won kò bófinmu. Ìmò elédè nípa èdè rè ni yóò je wá lógún nínú ìdánilékòó yìí.
Ó ye kí á tún pe àkíyèsí wa sí tip é àbínibí ni èdè o. Ènìkan kì í lo sí ilé-ìwé láti kó o. Ohun tí a ń so ni pé bí ìrìn rinrìn se jé àbìnibì fún omo, béè náà ni èdè jé. Fún àpeere, tí kò bá sí ohun tí ó se omo, tí ó bá tó àkókò láti rìn yóò rìn. Kì í se pé enì kan pe omo gúnlè láti kó o ni èyi. Báyìi gélé náà ni èdè jé. Àbínibí ni gbogbo ohun ti omo nílò fún èdè, ó ti wà lára re. Kò sì si èdè ti kò lè lo èyí fún sùgbón èdè ibi tí a bá bi omo sì ni yóò lo àwon ohun èlò yìí láti so.
 
(2) Òrò àti Àpólà: Òrò ti a bat ò pò ni ó ń di àpólà. Ó seé se kí àpólà jé òrò kansoso. Ìyen tí òrò yìí kò bá ní èyán. Fún àpeere, àpólà-orúko ni a fa igi sí ní ìdi ní (3a) àti (3b).
Sùgbón a kò lè sèdá òkankan nínú (54) nípa lílo òfin (52).
(54) (a) NjéǸjé Olú dé?
(b) Sé Adé ra aso?
(d) Omo tí ó lo dé bí?
 
Síbè a ó se àkíyèsí pé àwon gbólóhùn (53) ní nnkannǹkan se pèlú (54). Gírámà tí a pè ní gírámà ìyídà onídàro yìí ní gbára láti se àlàyé ìbásepò tí ó wà láàrin àwon gbólóhùn wònyí. Sùgbón kí a tó menu ba bí yóò se se àlàyé yìí, e jé kí a wo àwon ohun tí a lè bá pàdé nínú gírámà yìí.
 
10. Gírámà Ìyídà Onídàro:
(i) ìhun Ìsàlè: Gbogbo gbólóhùn ni ó máa ń ní ìhun ìsàlè. Ó wá seé se kí ìhun ìsàlè gbólóhùn kan bá ti òkè mu; ó sì seé se kí ó máà bá a mu. Àwon ohun tí a máa ń pá pàdé nínú ìhun ìsàlè ni aká òrò, òfin òrò, òfin gbólóhùn, àttúnpínsìsòrí, òfin ìsòrí òrò, ìyanra (ìyan ara).
 
(ii) Gbé alfa: Ìtumò gbé alfa ni pé kí á gbé nnkannǹkan kan láti ibì kan lo sí ibòmíràn nínú gbólóhùn.
 
(iii) Ìhun Òkè: Àwon ohun tí a máa ń bá pàdé nínú ìhun òkè ni ìsòrí kòòfo, gbólóhùn tí a ti da ètò rè rú, ìse lámì kanùn (1ise ní àmì kan ùn) asé.
(11) Gbólóhùn Ìbéèrè béè-ni-béè-kó: Àwon ìbéèrè kan wà tí ó jé pé béè ni tàbí béè kó ni ìdáhùn máa ń jé. Fún àpeere, tí a bá so pé:
 
(55) NjéǸjé Olú lo?
 
A lè dáhùn wí pé:
 
 
Ẹ̀ká Fonọ́lọ́jì
Èká Fonólójì
 
ÈkaẸ̀ka àrògún
 
 
(b) Olú lo bí?
 
E ó se àkíyèsí wí pé ń se ni àrótì sáájú gbólóhùn nínú NjéǸjé Olú lo? Sùgbón nínú Olú lo bí? àrótì yóò tèlé gbólóhùn ni.
 
(12) Ìbéèrè tí kì í ní ìdáhùn béè ni béè kó: Àwon ìbéèrè kan wà ti ìdáhùn won kì í se béè ni tàbí béè kó. Àpeere irú ìbéèrè béè ni
(b) Dàda mú Olú, báwo?
 
Ohun tí eléyìí ń fi hàn ni pé (69) náà ni ìpìlè fún (68) sùgbón nnkannǹkan tí ó selè nip é àbé àpólà-ìse kó ni àwon atóka ìbéèrè báwo àti níbo wà. Abé ìsòrí tí wón wà ni a ń pè ní àrótì. Bí àwóràn-atóka igi ti won se rí nì yí.
 
Tí a bá lo atóka ìbéèrè tan i tàbí kí ni láti bèèrè ìbéèrè nípa òrò-orúko olùwà, ààyè olùwà yìí kò ní í jé kòòfo. A ó fi arópò orúko kan sí ààyè yìí. Béè náà nit í a bá bèèrè ìbéèrè nípa òrò-orúko tí ó ń yán òrò-orúko mìíràn. Àpeere.
(14) Òrò-Ìse aláìléni:
 
A ó se àkíyèsí pé gbogbo nnkannǹkan tí a ti ń gbé, apá òtún ni a ti ń gbé won wá sí apa òsì. Ìbéèrè wá nip é sé apá òsì nìkan ni a máa ń gbé nnkannǹkan wa. Ìyen ni pé se apá òsì nìkan ni a máa ń gbé ‘alfa’ wa ni? Kì í se apá òsì nìkan. Àpeere tí a ó fún wa báyìí yóò fi èyí hàn. Àpeere náà ni gbólóhùn tí ó bá ní òrò-ìse aláìléni nínú. Irú gbólóhùn béè ni:
 
(76) Kí á pa àgó méta dára,
 
 
Àyè kòòfo (KF) yìí ni a ó wá fi ó aláìléni sí. Apá òsì ni a ti gbé nnkannǹkan lo sí apá òtún. Àpeere àwon gbólóhùn tí ó se báyìí wáyé ni:
 
(80) (a) (i) Kí á jalè kò dára
(15) Gbólóhùn Àse:
 
Kì í se gbogbo ìyídà ni ó máa ń ní gbé ‘alfa’. Ìyen ni pé kì í se gbogbo ìyídà ni a máa ń gbé nnkannǹkan láti ibì kan lo sí ibòmíràn. Àpeere gbólóhùn tí a sèdá láìgbé nnkannǹkan kan lo sí ibòmíràn ni gbólóhùn àse. Àpeere gbólóhùn àse ni:
 
(18) (i) wá
 
Ìbéèrè yìí fi hàn pé èni kejì eyò ni a ń tóka sí.
(16) Òté tí ó de Gbe ‘alfa’: A ti sàlàyé pé ìtumò gbé ‘alfa’ ni pé ki a gbe nnkannǹkan tí ó bá wù wá láti ibi kan lo sí ibòmíràn. Òté wà tí ó de nnkannǹkan ti a lè gbé.
 
(1) A kò lè gbé òrò kankan láti inú gbólóhùn tí ó bá jé pé APOR tí o ní olórí ni ó je gàba lé e lórí.
(b) *Kí ni Olú se – pé oun yóò fún un ní ìwé?
 
(iii) Tí olùwà gbólóhùn bá jé gbólóhùn, a kò lè gbé nnkannǹkan kan láti inú rè.
 
A kò lè gbé nnkanǹka láti inú gbólóhùn tí a fa igi sí ní ìdí wònyí.
 
(89) (a) (i) Síse ìdáwò mérin ni ojó kan dára
 
(ii) Kí ni kí a pa ¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬¬___ wù mí?
A kò lè gbé nnkannǹkan kan láti inú àpólà tàbí gbólóhùn àso.
 
 
 
 
A kò lè gbé eyo nnkannǹkan láti inú àpólà ti a fi ìlà sí ní ìdí yìí.
 
(91) (i) Mo ri Òjó àti Adé
(iii) * Ta ni mo rí _________ àti Adé?
 
Tí a bá máa gbé nnkannǹkan kan, méjèèjì ni a ó gbé papò.
 
(92) Ta ni mo rí _____________?
309

edits