S.M. Raji àti J.I. Ogunranti: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 1:
[[S.M Raji, J.I. Ogunranti]]
 
[[ÒpèỌ̀pẹ̀ nń fofọ dídùn 1 Orin Ifá]]
 
[[Akojopo orin Ifa ajemodu]]
Ìlà 7:
[[Odu]]
 
==ÀkójòpòÀkójọ̀pọ̀ orin Ifá AjemódùAjẹmọ́dù Ojú-Ìwé 91-110.==
 
 
Ìlà 13:
 
 
ÈlàẸ̀là tutu nini in in.
 
Ilé OlúweriOlúwẹri kì í gbóná
 
Ègbè: Olówó tutu dodo ó ó ó,
 
ÈlàẸ̀là tutu nini in in,
 
Ilé OlúweriOlúwẹri kì í gbóná
 
==Orin Yorùbá Ojú-Ìwé 1-3. ==
 
Orin ni èso àsààṣà ìsènbáyéìsẹ̀ǹbáyé àti ìtàn àwùjoàwùjọ ènìyàn. Káàkiri ilèilẹ̀ adúláwòadúláwọ̀ ni èmíẹ̀mí orin àti ijó ti jéjẹ́ èmíẹ̀mí ìgbésí ayé. SósósóSọ́sọ́sọ́ ni ìrinlèìrinlẹ̀ àti ìmúnilókànìmúnilọ́kàn wonwọn máa nń wowọ gbogbo ìgbésí ayé àwonàwọn ènìyàn gégégẹ́gẹ́enìẹnì kòòkankọ̀ọ̀kan, ní elégbéjegbéẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ àti ní àwùjoàwùjọ. Orin rí bí i díngídíńgí tí a fi nń tún ìwà ènìyàn seṣe.
 
==Orin Ifá Ojú-Ìwé 4-5. ==
 
OrísìírísìíOríṣìíríṣìí ònàọ̀nà ni a le gbà momọ ohun tí à nń pè ní orin Ifá. Orin Ifá ni orin tí ÒrúmìlàỌ̀rúmìlà máa nń kokọ nígbà ayé rèrẹ̀. Bí Baba nń lolọ, bí nń bòbọ̀, enuẹnu rèrẹ̀ kì í dákédákẹ́. Bí ò ki Ifá, yóò máa sun ÌyèrèÌyẹ̀rẹ̀-Ifá. Bí ò sun ìyèrèìyẹ̀rẹ̀-Ifá, yóò máa kokọ orin Ifá.
 
Òrúnmìlà àti orin Ifá 6-7
Kò sí bí a óò ti perí ajá tí a kò ní perí ìkòkò tí a fi sèṣè é. A ò le sòròsọ̀rọ̀ nípa orin-Ifá kí á yoyọ ti ÈdúẸ̀dú sílèsílẹ̀. Bí ObàtáláỌbàtálá; ObàtárìsàỌbàtárìṣà; ObaỌba Tapatapa tí í bá wonwọn gbóde ìrànjé ti ní orin tirètirẹ̀ náà ni Orò: Yínni-yínni gbín-ín-kin; ÒgògòỌ̀gọ̀gọ̀ rumòrumọ̀-rumòrumọ̀rumòrumọ̀ láyé. Ó tún rumòrumọ̀ lórunlọ́run ní orin tí wonwọn fi nń yìn ín.
 
Ìwúlò orin Ifá Ojú-Ìwé 8-9.
Ohùn enuẹnu Yorùbá tó dùn, tó dún, tó sì jinlèjinlẹ̀ ni Orin Ifá. ElòmìírànẸlòmìíràn le gbàgbé ara rèrẹ̀ síbi tí ó bá ti nń wòran eré-Ifá. SíseSíṣe-léré rèrẹ̀ ni kò tó wò ni? ÌwóhùnÌwọ́hùn inú orin ibèibẹ̀ ni ò tó wò ni? Àbí àwonàwọn òròọ̀rọ̀ kànkàǹ-kà tí nń kónikọ́ni lógbónlọ́gbọ́n tí ó kún inú rèrẹ̀ fófófófọ́fọ́fọ́?
 
Àkóónú inú orin Ifá Ojú-Ìwé 10.
Àkóónú orin Ifá kò gbodògbọdọ̀ kojákọjá àwonàwọn nnkannǹkannń bebẹ láàrin àwùjoàwùjọ tí bí i. ÀwonÀwọn nnkannǹkanòròọ̀rọ̀ ìbà jíjú, oríkì, ètò ìsèlúìṣèlú, èto owó àti ohun mìíràn tó jejẹ àwonàwọn ènìyàn lógún, àwonàwọn nnkannǹkanjéjẹ́ bárakú fún wonwọn, ìmòrànìmọ̀ràn àti àwonàwọn ohun tó nń selèṣẹlẹ̀ lówólówólọ́wọ́lọ́wọ́ àti èyí tó ti selèṣẹlẹ̀ séyinsẹ́yin.
 
ÌgbékalèÌgbékalẹ̀ orin Ifá Ojú-Ìwé 11.
ÀwonÀwọnnń fi ojú ààtò wo lítírésòlítírésọ̀ sosọ pé kò sí ohun tó dára tí kò ní ààtò tó dára. Orin náà ní ejéwònẹjẹ́wọ̀n-ónọ́n bí a bá féfẹ́ kó dùn, kó dún, kó sì pépẹ́ lókànlọ́kàn eniẹni. Ènìyàn ò gbodògbọdọ̀ máa to nnkannǹkan lódìlódì. EniẸni tó bá gbé ìyá igbá lé omoríọmọrí igbá tit ò ó lódì.
 
ÈwóÈwọ́ Ojú-Ìwé 12.
Irú èwóẹ̀wọ́ ìlù yìí ni à nń lù sí orin tí a fi seṣe àpereàpẹrẹ lókè yìí. GégéGẹ́gẹ́orúkoorúkọ rèrẹ̀, ìlú yìí gbódògbọ́dọ̀ máa wówọ́ nílènílẹ̀ ni.
 
Jàbàtá Ojú-Ìwé 12.
Irú òrin Ifá ìsàlèìsàlẹ̀ yìí ni a máa nń kokọ sí i pé:-
Lílé: E wáà báni seṣe é é é,
ÈyínẸ̀yín ará òrunọ̀run un un,
E wáà báni seṣe é è e,
EyínẸyín ará òrunọ̀run un un un,
ÈyínẸ̀yín ín aláásekùalááṣekù;
E wá báni seṣe é é.
 
MétamétaMẹ́tamẹ́ta Ojú-Ìwé 13.
Irú orin-Ifá ìsàlèìṣàlẹ̀ yìí ni a máa nń kokọ sí i pé:
Lílé: ÀsèseÀṣẹ̀ṣe o ò o;
La ó bobọ káá wa tó ó bòrìsàbọ̀rìṣà o;
Ikin eniẹni, àsèseàṣẹ̀ṣe
 
ÈsáẸ̀sá Ojú-Ìwé 13-14.
ÈkaẸ̀ka ìlù yìí máa nń le díèdíẹ̀. EniẸninń lu kon-kon-kolo yóò máa sáṣá agogo lolọtirètirẹ̀ ni. Onípapapa náà ò sì ní í dáwódáwọ́ dúró. Ènìyàn le mú irú ìlù yìí le. A sì tún le mú un dèdẹ̀. Ibí yìí gan-an ni òógùn ti nń bóbọ́ kíkan-kíkan lára omoọmọ Awo tó bá le jó ju òkòtó lolọ. Ohùn eniẹninń dárin le pin nígbà tí alágogo bá lé e láré kojákọjá ibi agbára rèrẹ̀ momọ.
 
==Ètò ohùn inú orin Ifá Ojú-Ìwé 15-17. ==
 
Ohun tó máa nń tètè hàn sí ènìyàn tó bá féfẹ́ tú ìfun àti èdòẹ̀dọ̀ iséiṣẹ́ kan wò ni ohun tó jejẹ etí lógún. Dídùn àti dídùn ibèibẹ̀. ÒgbèrìỌ̀gbẹ̀rì akorinakọrin-Ifá ni yóò máa fi orísìíoríṣìí ohùn kan náà gbe ara wonwọn. Bí ohùn òkè bá wà ní orí ìlà àkókóàkọ́kọ́, fún àpereàpẹrẹ, ohùn tí òròọ̀rọ̀ tí ó wá ní ìlà tí a óò fi gbè é gbódògbọ́dọ̀ tako ti àkókóàkọ́kọ́ìbèrèìbẹ̀rẹ̀, ààrin tàbí ní ìparí.
 
==Èto Èrò inú orin Ifá Ojú-Ìwé 18.==
 
Ó ní irú àwonàwọn òròọ̀rọ̀ tí a le tò mómọ́ ara wonwọn nínú orin Ifá.
 
Fún ÀpereÀpẹrẹ:
 
Lílé: Ifá ni n ó ma sìn o o o,
 
Mo forin kokọ o ò o,
 
Ifa ni n ó ma sìn,
 
Mo forin kokọ.
 
ÒpèỌ̀pẹ̀ ni n ó ma sìn o ò o;
 
E má pa mí o ò o;
 
Ifá ni ó ma sìn
 
Mo forin kokọ.
 
 
==Bátànì orin Ifá Ojú-Ìwé 19. ==
 
Kì í seṣe gbogbo ìgbà ni ìlà kan inú orin-Ifá máa nń gbé èrò kan jáde. Ó le jéjẹ́ pé tí a bá ka ìlà orin méjì sí métamẹ́ta ni a óò tó rí èrò tí orin kan gbé jáde. E jéjẹ́ kí á tún wo àpeereàpẹẹrẹ orin òkè yìí wò léèkanlẹ́ẹ̀kan sí i. A kò le momọ èrò òkorinọ̀kọrin yìí tí a bá gbógbọ́ ìlà kìíní orin yìí láìgbóláìgbọ́ ìlà kejì.
 
==Orin Ifá aláàdáákoaláàdáákọ Ojú-Ìwé 20==
 
ÀwonÀwọn orin-Ifá kan wà tí a kì í gbógbọ́ ju ohùn enìẹnì kan lolọ níbèníbẹ̀. ÀpereÀpẹrẹ irú orin béèbẹ́ẹ̀ ni orin tí Babaláwo nń kokọ nígbà tí ó nń dáfá rèrẹ̀òwúròòwúrọ̀ kùtùkùtù. Irú irin-Ifá aládàákoaládàákọ báyìí náà nń fi ipò tí akorinakọrin wà hàn.
 
==Orin Ifá AlájùmòkoAlájùmọ̀kọ (Oní-lílé àti ègbè) Ojú-Ìwé 21-24.==
 
Ó kéré parí, ènìyàn méjì tàbí jù béèbẹ́ẹ̀ lolọ ni wónwọ́n máa nń kokọ irú orin yìí. Bí babaláwo méjì bá pàdé ara wonwọn, wónwọ́n le sun ìyèrèìyẹ̀rẹ̀ Ifá. WónWọ́n sì le korinkọrin ki Ifá. ÀwonÀwọn omoọmọ ìkóséìkọ́ṣẹ́ Ifá náà le kó ara wonwọn jojọ lati máa fi orin-Ifá dá ara wonwọn lára yá. Tí wonwọnnń seṣe ìpàdè Awo tàbí tí wonwọnnń sodúnṣọdún ifá, Irú bátànì orin Ifá yìí ni a sáábà máa nń lò jù.
 
==Ìlànà tí AkorinAkọrin Ifá Máa nń tèlétẹ̀lé Lójú Agbo Eré Ojú-Ìwé 25-30. ==
 
Ó dàbí pé ohun tó seṣe pàtàkì jù lolọ nínú orin Ifá ní kíkokíkọ ni ònàọ̀nà tí à nń gbà gbé e kalèkalẹ̀ lónàlọ́nà eré. Eré àwògbádùn ni eré orin Ifá ní kíkokíkọ. Ó máa nń irú orin tí wonwọn fi nń irú orin tí wonwọn le fí kásèkásẹ̀ eré nílènílẹ̀.
Nígbà tí akorinakọrin Ifá bá nń siséṣiṣẹ́ tó gbà yìí lolọ, ó níláti bèrèbẹ̀rẹ̀ pèlúpẹ̀lú ìyèrèìyẹ̀rẹ̀ Ifá ní sísun pé:
 
==ÌsòwólòÌsọ̀wọ́lò-èdè Inú Orin Ifá Ojú-Ìwé 31. ==
 
Kò sí ohun tí ale pè ní ewì ní ilèilẹ̀ Yorùbá tí a ò ní bá onírúurú onàọnà-èdè níbèníbẹ̀. Ó kàn jéjẹ́àwonàwọn onàọnà-èdè wònyíwọ̀nyí sodoṣodo sínú orin-Ifá ju àwonàwọn ohùn enuẹnu Yorùbá yòókù lolọ. Bí a bá sosọ pé orin kan dára, èdè rèrẹ̀ ló wuyì. Èdè inú orin gbódògbọ́dọ̀ fanimórafanimọ́ra.
 
==ÀkójopòÀkójọpọ̀ Orin Ifá Ojú-Ìwé 32-90.==
 
 
Lílé: Atótó ó ó ó;
 
Atótó Arére, e yáa dákédákẹ́
 
Ifá féfẹ́ fohùnfọhùn;
 
E e dákédákẹ́.
 
 
 
Ègbè: ÒrúnmìlàỌ̀rúnmìlà o ò;
 
Aatótó ó ó ó;
Ìlà 131:
Atótó ó ó Aaarére e e,
 
E yá a dákédákẹ́,
 
Ifá féfẹ́ fohùnfọhùn,
 
E dákédákẹ́.
 
 
==Iwe ti a yewo==
 
[[S.M Raji, J.I. Ogunranti (2004) ÒpèỌ̀pẹ̀ nń fofọ dídùn 1 Orin Ifá Kingson Publishers. ISBN 978-42602-1-8.]]