Wikipedia:Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): C: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Ahusa
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
 
Ìlà 6:
cab:n; (I came by cab.) ajé ìgboro; okò ìgboro Ajé ìgboro ni mo bá wá.
 
cabbage:n; (Do you like cabbage?) efó òyìnbó-irúfé èfó tí igì rérẹ́ máa n jé àwó ewé tí àwon ewé rè máa n nó àwo pupa résúrésú tàbí
funfun díè díè. A lè jé ní tutu tàbí kí a sè é lobe n jé o fé èfó òyìnbó?
 
Ìlà 65:
pàgó mo pàgó sórí papa ni òru
 
campaign: n; (Today police lunched a campaign to reduce road accident.) ìrtanijí lórí èro wa tàbí ohun tí a féfẹ́. Àwon olópàá se ìtanijí lónìí láti dún ìjànbá móto lójú pópó kù.
 
campaign: v; (They are carmpaigning so as to be voted into power.)se ìtanijí Wón n se ìtanijí kí á bàa lè dìbò fún won
Ìlà 831:
complement:v; (I compliment her on her English.) yìn; pón, mo yìn ní lórí ede Gèésì rè
 
compliments:n; (My compliments to your wife) ìkíní; Bá mi kí ìyàwó rerẹ.
 
compose:v; (I am composing the formal reply
Ìlà 837:
composer: n; (All the misic composers are here.) aláròko; alátòjo.Gbogbo àwon aláròko orin lò wà níbí.
 
compost:n; You need potting compost to grow your plants in.) ìlédú ó nílò ìkòkò ìlèdu láti figin àwon irúgbìn rerẹ.
 
compost: (He composted the vegitable garden.) fì ìlèdú sí; fi òrá sí ó fi ìlèdú sí oko èfó náà.
Ìlà 1,020:
cooker:n; (He bought electrical cooker.) àwon ohun èló ìsàsè ó ra ohun èló ìsasè tí ó n lo èro mònàmónà.
 
cookery:n; (She learnt cookery at school.) ìsàsè; ìse ounje; òna bí a ti n se oúnjeoúnjẹ ó kó èkó ìsàsè ní ilé- èkó
 
cooking oil:n; (She bought cookeing oil.) oróró ìsebè o ra òróró ìsebè.
Ìlà 1,114:
council:n; (The vulage council decided to cut down the vulage trees.) àjò; ìgbìmò. Àjo abúlé pínnu láti gé àwon igi abúlé náà lulè.
 
councilor:n; (My brother is a councillor.) òkan nínú àwon ìgbìmò, olùgbìmò. ÒkanỌ̀kan nínú àwon ìgbìmo ni ègbón mi okùnrin.
 
count: kà; rò; sírò. Edwin lè kà á láti orí oókan títí dé ogórùn-ún.
Ìlà 1,247:
crisis: n; (There was a crisis last Saturday.) ìjòngbòn; wàhàlà; rúkèrúdò wàhálà bé sílè ní ojó Àbáméta tó kojá.
 
crisp:adj; (Leave are crisp during the dry season.) rún were; tí kìí pé rún ÀwonÀwọn ewe máa n rún were nígbà èèrùn.
 
crisp:n; (The potatoes crisp is very sweet.) ànàmó/òdùnkún díndin Ànàmó dúndún náà dùn
Ìlà 1,265:
crooked:adj; (Your glasses are on crooked.) wó. Awò ojúurè.
 
crop:n; (Some main crops of West Africa are rice, cassava and yam.) ohun ògbìn. AwonAwọn ohun ògbìn pàtàki ni ìwò oòrùn. Adúláwò ni : ìresì; èwà àti isu.
 
cross:n; (You must carry the cross.) agbélèbú o ní láti gbé àgbélèbú náà.