Ìbàdàn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Addbot (ọ̀rọ̀ | àfikún)
k Bot: Migrating 42 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q183298 (translate me)
No edit summary
Ìlà 121:
}} <!-- Infobox ends -->
 
'''IbàdànÌbàdàn''' jẹ́ ilú [[Nàìjíríà]] tí ó tó bí jùlo ni [[Apa Iwóòrùn Afrika|apá ìwọ̀òrùn]] [[Afríkà]], bé ni ó sí jé [[olúìlú]] ìjoba [[ìpínlè Oyo]]. Ibadan' jé ilú àwon jagun jagun. Itumò Ibàdàn ni ebá odàn (Near Savannah).
 
Ibadan budo si guusu-apaiwoorun Naijiria, 128&nbsp;km sinu lati ariwailaorun ilu [[Lagos|Eko]] ati 530&nbsp;km lati guusuiwoorun [[Abuja]], oluilu apapo, be sini o je ibi [[Public transport|igunle]] pataki larin agbegbe eba okun ati awon ibi ti won wa ni ariwa Naijiria. Ibadan ti je gbongan ijoba fun [[Western Region, Nigeria|Agbegbe Apaiwoorun]] atijo lati igba ijoba amusin [[British Empire|Britani]], be sini apa die ogiri bode to da abo bo ilu na si wa titi doni. Awon alabugbe to poju ni be ni awon omo [[Yoruba people|Yoruba]].
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ìbàdàn"