Ìbàdàn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 123:
'''Ìbàdàn''' jẹ́ ilú [[Nàìjíríà]] tí ó tó bí jùlo ni [[Apa Iwóòrùn Afrika|apá ìwọ̀òrùn]] [[Afríkà]], bé ni ó sí jé [[olúìlú]] ìjoba [[ìpínlè Oyo]]. Ibadan' jé ilú àwon jagun jagun. Itumò Ibàdàn ni ebá odàn (Near Savannah).
 
Ibadan budo si guusu-apaiwoorun Naijiria, 128 km sinu lati ariwailaorun ilu [[Lagos|Eko]] ati 530 km lati guusuiwoorun [[Abuja]], oluilu apapo, be sini o je ibi [[Public transport|igunle]] pataki larin agbegbe eba okun ati awon ibi ti won wa ni ariwa Naijiria. Ibadan ti je gbongan ijoba fun [[Western Region, Nigeria|Agbegbe Apaiwoorun]] atijo lati igba ijoba amusin [[British Empire|Britani]], be sini apa die ogiri bode to da abo bo ilu na si wa titi doni. Awon alabugbe to poju ni be ni awon omo [[Yoruba people|Yoruba]] ati opo eniyan lati apa Naijiria yioku.
 
==Ìtàn==
Ibadan je didasile ni odun 1829 nitori awon rogbodiyan to unsele ni [[Yorubaland|Ilẹ̀ Yorùbá]] nigba na. Asiko yi ni awon ilu ti won se pataki ni ile Yoruba nigba na bi [[Ọ̀yọ́ ilé]], [[Ìjàyè]] ati [[Òwu]] je piparun.
{{climate chart|Ìbàdàn
|21|33|8
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ìbàdàn"