Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Ìyá"

10 bytes removed ,  18:27, 31 Oṣù Kẹjọ 2018
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
[[Fáìlì:iya.jpg|thumb|right|Ìyá àti [[ọmọ]] rẹ̀]]
'''Ìyá''' ('''màmá''' tabi '''mọ̀nmọ́n''') ni [[òbí]] to je [[obìnrin]] eyan kan. Iya ati [[bàbá]] je obi fun [[ọmọ]] tabi eniyan kan. Ni opolopo iya lo [[ìbí|]] omo fun ra re, nigba miran o le [[ìgbàlọ́mọ|gba]] omo elomiran bi omo re tabi ki o [[surrogacy|gba]] omo elomiran bí.