'''Ìyá''' ('''màmá''' tabi '''mọ̀nmọ́n''') ni [[òbí]] to je [[obìnrin]] eyan kan. Iya ati [[bàbá]] je obi fun [[son|ọmọ]] tabi eniyan kan. Ni opolopo iya lo bí omo fun ra re, nigba miran o le [[ìgbàlọ́mọ|gba]] omo elomiran bi omo re tabi ki o [[surrogacy|gba]] omo elomiran bí.