Faure Gnassingbé: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k →‎Itokasi: removed deleted template, removed: {{link FA|pl}} using AWB (11720)
Fi kun oju ewe yii.
Ìlà 18:
| party = [[Rally of the Togolese People|RPT]]
}}
'''Faure Essozimna Gnassingbé''' (ojoibi June 6, 1966<ref name=Radio>[http://www.radiolome.tg/template.php?pg=affichenews&idnews=419 "BIOGRAPHIE DU NOUVEAU PRESIDENT"], Radio Lome {{fr icon}}.</ref>) ni [[List of Presidents of Togo|Aare]] ile [[Togo]] lati May 4, 2005. O je omo Aare [[Gnassingbé Eyadéma]], baba re yan si ibise ijoba gege bi Alakoso oro Irinse, Alumoni, Ifiweranse ati [[Telecommunication|Ibanisorolookan]] lati 2003 to 2005. Leyin iku Eyadéma ni 5 February, 2005 Gnassingbé di Aare. Oruko iya re ni Sena Sabine Mensah. o ka ile iwe giga ni lome, o kawe gboye ninu imo eto isuna okowo ni Sorbonne, Paris. O te siwaju lati gba masitasi ni George Washinton Unifasiti ni Amerika.
 
{{ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}