Genevieve Nnaji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

k
Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
k (Bot: Migrating 23 interwiki links, now provided by Wikidata on d:q463902 (translate me))
kNo edit summary
Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ sí àwọn olólùfẹ́ filmu ni Naijiria pẹ̀lú filmu tó ún jẹ́ ''Most Wanted''. Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn filmu bíi ''Last Party, Mark of the Beast'' àti ''Ijele''. Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood.<ref>[http://hollywood.premiere.com/movie_stars/celebrity-filmography-Genevieve+Nnaji Àkójọ àwọn filmu Genevieve Nnaji]</ref>
 
Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tódárajùlọ fún 2001 ní City People Awards, ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọtó dára jùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà.
 
Ní 2004, ó tọwọ́bọ̀wé pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ àwo-orin ilẹ̀ [[Ghana]], ''EKB Records'' láti gbé àwo-orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde tó ún jẹ́ ''One Logologo Line'',<ref>[http://www.stayaround.com/genevieve-artist-660.html Genevieve at Blue Pie Productions]</ref> àdàlú orin ''R&B'', ''[[Hip-Hop]]'' àti ''Urban''.<ref>[http://www.mtraks.com/artist/genevieve/release/43321-one_logologo_line Genevieve: One Logologo Line]</ref>
3

edits