Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Orílẹ̀ èdè America"

Kò sí ìsọníṣókí àtúnṣe
No edit summary
No edit summary
'''Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan ilẹ̀ Amẹ́ríkà''' ''(I.A.A)'' tabi '''Àwọn Ìpínlẹ̀ Asokan''' (''I.A'' tabi ni Geesi: ''USA'' tabi ''US''), tàbí '''Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà''' tabi '''Amerika''' ni soki, jẹ́ orílé-èdè ijoba àpapò olominira pèlú [[iwe-ofin ibagbepo]] tí ó ni [[Awon Ipinle Amerika|adota ipinle]], [[agbegbe ijoba-apapo kan]] ati [[agbegbe merinla]], ti o wa ni [[Ariwa Amerika]]. Ilẹ̀ re fe lati [[Pacific Ocean|Òkun Pasifiki]] ni apa iwoorun de [[Òkun Atlántíkì]] ni apa ilaorun. O ni bode pelu ile [[Kanada]] ni apa ariwa ati pelu [[Meksiko]] ni apa guusu. Ipinle [[Alaska]] wa ni ariwaiwoorun, pelu Kanada ni ilaorun re ati [[Russia|Rosia]] ni iwoorun niwaju [[Bering Strait]]. Ipinle [[Hawaii]] je [[archipelago|agbajo erekusu]] ni arin Pasifiki. Orile-ede awon Ipinle Aparapo tun ni [[Territories of the United States|opolopo agbegbe]] ni [[Caribbean|Karibeani]] ati Pasifiki.
 
Pelu 3.79 egbegberun ilopomeji maili (9.83 million km<sup>2</sup>) ati iye to ju 309 egbegberun eniyan lo, awon Ipinle Aparapo je orile-ede totobijulo [[List of countries and outlying territories by total area|keta tabi kerin]] bii apapo iye aala, ati iketa totobijulo bii [[List of countries and outlying territories by land area|aala ile]] ati bi awon [[List of countries by population|olugbe]]. O je kan ninu awon orile-ede agbaye to ni [[Multiethnic society|opolopo eya eniyan]] ati [[multiculturalism|asapupo]], eyi je nitori ikoreokere lati opo awon orile-ede.<ref name="DD">Adams, J. Q., and Pearlie Strother-Adams (2001). ''Dealing with Diversity''. Chicago: Kendall/Hunt. ISBN 0-7872-8145-X.</ref> [[Economy of the United States|Okowo awon Ipinle Aparapo]] ni okowo orile-ede to tobijulo lagbaye, pelu idiye [[Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè|GIO]] 2009 to je $14.3 egbegberunketa (idamerin [[ListÀkójọ ofàwọn countriesorílẹ̀-èdè bybíi GDPGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè (nominalolórúkọ)|GIO oloruko lagbaye]] ati idamarun GIO agbaye fun [[purchasing power parity|ipin agbara iraja]]).<ref>The [[European Union]] has a larger collective economy, but is not a single nation.</ref>
 
Awon eniyan abinibi ti won wa lati [[Asia (orile)|Asia]] ti budo si ori ibi ti orile-ede awon Ipinle Aparapo wa loni fun egberun lopo odun. Awon olugbe [[Native Americans|Abinibi ara Amerika]] din niye gidigidi nitori arun ati igbogunti leyin [[European colonization of the Americas|ibapade awon ara Europe]]. Orile-ede awon Ipinle Aparapo je didasile latowo awon [[Thirteen Colonies|ileamusin metala ti Britani]] to budo si egbe Okun Atlantiki. Ni ojo 4 Osu Keje, 1776, won se [[United States Declaration of Independence|Ifilole Ilominira]], eyi kede eto won fun iko araeni ati idasile isokan alafowosowopo won. Awon ipinle asagun yi bori [[British Empire|Ileobaluaye Britani]] ninu [[American Revolutionary War|Ogun Ijidide Amerika]], eyi ni ogun alamusin fun ilominira akoko to yori si rere.<ref>Dull, Jonathan R. (2003). "Diplomacy of the Revolution, to 1783," p. 352, chap. in ''A Companion to the American Revolution'', ed. Jack P. Greene and J. R. Pole. Maiden, Mass.: Blackwell, pp. 352–361. ISBN 1-4051-1674-9.</ref> [[United States Constitution|Ilana-ibagbepo ile awon Ipinle Aparapo]] lowolowo je gbigba bi ofin ni ojo 17 Osu Kesan, 1787; itowobosi ni odun to tele so awon ipinle di apa orile-ede olominira kan na pelu ijoba apapo to lagbara. Awon [[United States Bill of Rights|Isofin awon Eto]], to ni atunse mewa si ilana-ibagbepo ti won semudaju awon eto ati ainidekun araalu, je titowobosi ni 1791.