Ifá: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k replacing Unicode code points from the private range (U+E000 to U+F8FF) by the proper combining accents
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 110:
 
Ninu asa [[Yoruba]] '''Ifá''' A ti rí i ni ojú ewé 46 Apa Kini ìwe yi irú ipò pataki ti Orìṣà-nla tabi Ọbàtálá kó laarin awọn òrìṣà ati irúnmalẹ̀ ilẹ Yoruba. A ti gbọ́ pẹlu pe jákè-jádò gbogbo ilẹ̀ Yorùbá ni nwọn maa mbọ́ ọ́, nitoripe oun ni awọn àgbà àtijọ́ gbà ninu ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ wọn pe o jẹ igbákejì Olódùmarè, ti o si nràn an lọ́wọ́ lati tún enia dá nipa fífún un ni ojú, imú, eti, ati gbogbo ẹ̀yà ara miran ti o yẹ ki ẹ̀dá ní ki o fi lè di enia pipe. ...
 
 
== Iwe fun kika ==
Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/wiki/Ifá"