Òrìṣà Egúngún: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
File
Ìlà 2:
[[File:Paleopathology; Human femurs from Roman period, Tell Fara Wellcome L0008764.jpg|thumbnail|]]
 
egungun je okan pataki ninu awon Orisa akunlebo ni ile Yoruba. Egungun ni a tun mo si ara orun, awon Yoruba gbagbo pe nigba ti egun ba jade pe oku orun lo wa lati wa ba awon eyan re pejo, lati wa ba araye jiroro. Eegun je Orisa kan to ma n fi aso Bo gbogbo ara, aso yii si la mo si eku tabi agò. Nigbakugba ti egungun ba ma jade, oru ayajo ojo yii ma n je ojo ayeye nla, o ma je ojo idunu ati ojo irawo ebe si awon oku orun tori awon Yoruba gbogbo pe omo ina la n ran si ina leyi to tumo si pe oku la n ran so oku ti yio si le Jise ni kiakia. Awon Yoruba a ma fun egun lebu won a si ma tara rawo ebe si olorun fun ohun rere kan tabi omiran.<ref name="Publishing">{{cite web | last=Publishing | first=Argosy | title=Types of Bones - Learn Skeleton Anatomy | website=Visible Body | url=https://www.visiblebody.com/learn/skeleton/types-of-bones | access-date=2019-06-06}}</ref>won Awo tabi awon ti o ni igbagbo tabi ti won my egungun sise ni okunkundun ni awon ti a no si awon Oloje, awon won yii lo n Se ki Kari ni won so no pupo ni pa asiri eegun.
Awon Awo tabi awon ti o ni igbagbo tabi ti won my egungun sise ni okunkundun ni awon ti a no si awon Oloje, awon won yii lo n Se ki Kari ni won so no pupo ni pa asiri eegun.
Die lara awon oloye eegun ni:
Alaagba