Genevieve Nnaji: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

k
Mo se atunse otogarafi awon oro kan to ko ba otogarafi ede yoruba ajumolo mu. Bii apeere Filmu si (Sinima-agbelewo), ati awon atunse irufe wonyi
k (Mo se atunse otogarafi awon oro kan to ko ba otogarafi ede yoruba ajumolo mu. Bii apeere Filmu si (Sinima-agbelewo), Interneti (ero ayelujara) ati awon atunse bee)
k (Mo se atunse otogarafi awon oro kan to ko ba otogarafi ede yoruba ajumolo mu. Bii apeere Filmu si (Sinima-agbelewo), ati awon atunse irufe wonyi)
Nnaji bẹ̀rẹ̀ ìṣèré rẹ̀ láti ọmọdé ninu eré tẹlifísọ̀n ''Ripples'' nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 8. Ó tún ṣe ìpolówó ọjà bíi méèló kan nínú èyí tó jẹ́ fún Pronto àti ọṣẹ ìfọsọ Omo. Ní 2004 ó di aṣojú fún ọsẹ ìwẹ̀ Lux<ref>[http://www.unileverghana.com/ourbrands/personalcare/lux.asp Genevieve Nnaji & Lux advertisement]</ref>, ìbáṣe ìgbọ̀wọ́ tọ́ fa èrè ínlá wá fun.<ref name=info1/>
 
Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ sí àwọn olólùfẹ́ filmusinima-agbelewo ni Nàìjíríà pẹ̀lú filmu tó ún jẹ́ ''Most Wanted''. Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn filmusinima-agbelewo bíi ''Last Party, Mark of the Beast'' àti ''Ijele''. Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood.<ref>[http://hollywood.premiere.com/movie_stars/celebrity-filmography-Genevieve+Nnaji Àkójọ àwọn filmu Genevieve Nnaji]</ref>
 
Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tódárajùlọtó dárajùlọ fún 2001 ní City People Awards, ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin-bìnrin tó dára jùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmusinima-agbelewo ilẹ̀ Áfríkà.
 
Ní 2004, ó tọwọ́bọ̀wétọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ àwo-orin ilẹ̀ [[Ghana]], ''EKB Records'' láti gbé àwo-orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde tó ún jẹ́ ''One Logologo Line'',<ref>[http://www.stayaround.com/genevieve-artist-660.html Genevieve at Blue Pie Productions]</ref> àdàlú orin ''R&B'', ''[[Hip-Hop]]'' àti ''Urban''.<ref>[http://www.mtraks.com/artist/genevieve/release/43321-one_logologo_line Genevieve: One Logologo Line]</ref>
 
Ní 2008 ni ó ṣí ilé ìránsọ rẹ̀ tó ún jẹ́ "St. Genevieve", èyí tó ún ṣọrẹ ìdámẹ́ẹ̀wá èrè rẹ̀.<ref>[http://naijashowbiz.com/archives.html Genevieve starts clothing line]</ref><ref>[http://www.talkzimbabwe.com/news/122/ARTICLE/2692/2008-06-15.html Genevieve Nnaji at TalkZimbabwe.com]</ref><ref>[http://niyitabiti.blogspot.com/2008/05/nollywood-star-actressgenevieve-nnaji.html Genevieve Nnaji at Gistmaster.com]</ref>
|}
 
==Awon Ìtọ́kasí==
{{reflist}}
 
3,063

edits