Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
→‎Itan: Fixed typo, added content
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
k Added content
Àwọn àlẹ̀mọ́: VisualEditor Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 69:
}}
 
'''Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun''' je okan ninu awon [[Awon Ipinle Naijiria|Ipinle]] ni orile-ede [[Naijiria]]. Ipinle Osun je [[States of Nigeria|ipinle]] arin ile ni apa gusu-iwoorun [[Naijiria]]. Olu-ilu re ni ilu [[Osogbo]]. O ni bodeibode ni ariwa mo [[Ipinle Kwara]], ni ilaorunila-oorun die mo [[Ipinle Ekiti]] ati die mo [[Ipinle Ondo]], ni guusu mo [[Ipinle Ogun]] ati ni iwoorun mo [[Ipinle Oyo]]. Gomina ipinle na lowolowo bayi ni Gomina Gboyega Oyetola.<ref name="Premium Times Nigeria 2019">{{cite web | title=Supreme Court affirms Gboyega Oyetola's election as Osun Governor | website=Premium Times Nigeria | date=2019-07-05 | url=https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/338994-breaking-supreme-court-affirms-gboyega-oyetolas-election-as-osun-governor.html | access-date=2019-09-18}}</ref> Won dibo yan-an wole ni 2018.<ref name="BBC News Pidgin 2019">{{cite web | title=Appeal Court say Oyetola win Osun election | website=BBC News Pidgin | date=2019-05-09 | url=https://www.bbc.com/pidgin/tori-48211765 | access-date=2019-09-18}}</ref> Osun ni ibi ti opo awon landmarkibi meremere to gbajumo wa, lopo mo ogba [[Obafemi Awolowo University|Yunifasiti Obafemi Awolowo]] to wa ni [[Ile-Ife|Ile-Ifẹ]], ibi to se pataki ninu asa Yoruba. Awon ilu tose pataki ni ipinle Osun tun ni [[Oke-Ila|Oke-Ila Orangun]], [[Ila, Nigeria|Ila Orangun]], [[Ede, Nigeria|Ede]], [[Iwo, Nigeria|Iwo]], [[Ejigbo]], [[Esa-Oke]] and [[Ilesa]].
 
==Itan==