Anafilasisi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
→‎Awọn asopọmọ ode: so we can generate page views
No edit summary
Ìlà 35:
 
===Nipa ọkan===
[[Gbigbọn ọpa to ngbe ẹjẹ kuro lati ọkan]] le ṣẹlẹ pẹlu [[myocardial infarction]], [[iro ọkan ti ko dun deede|aidun deede]]ti o tẹle, tabi[[cardiac arrest]]<!-- paapaa lailo efinifirini -->.<ref name=Review09/><ref name=World11/> Awọn ti o ni aiṣan ti ko han sita ninu ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara wa ninu ewu ti o gaju nipa ọkan lati ọwọ anafilasisi.<ref name=Cardio08/> Gbigbọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara nii fiṣe pẹlu wíwà awọn sẹẹli kan ti njọwọ hisitamini sinu ọkan.<ref name=Cardio08/> Nigbati [[ọkan ti o nyara sáré |ọkan ti o nyara sáré]] ti o waye nipase riru ẹjẹ ti o lọ silẹ jẹ eyiti wọpọ,<ref name=Aus06/> a ti ṣe apejuwe [[Bezold–Jarisch reflex]] ni 10% awọn iṣẹlẹ, nibiti [[ọkan ti o nlọra sáré |ọkan ti o nlọra sáré]] ti ni asopọ pẹlu [[riru ẹjẹ ti o lọ silẹ |riru ẹjẹ ti o lọ silẹ]].<ref name=CEA11/> Lilọ silẹ [[riru ẹjẹ]] tabi [[ijaya (lilo kaakiri ẹjẹ)|ijaya]] (yala [[ ijaya ti o lo kaakiri ara|ti o lo kaakiri ara] tabi [[ijaya ọkan|ti ọkan]) le mu lọwọ imọlara fifuyẹ tabi [[pipadanu òye ìwàláàyè]].<ref name=Cardio08/> Lilọ silẹ riru ẹjẹ kii saba jẹ aami kansoso fun anafilasisi.<ref name=Shock10/>
 
===Omiiran===