Anafilasisi: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
No edit summary
Ìlà 92:
Ninu ẹniti anafilasisi pa, [[iwadi nipa iku]] le fi "ọkan ti o ṣofo" kan han eyiti o waye nipasẹ oro ti o dinku lati ọwọ [[fifẹ awọn ọpa ti o ngbe ẹjẹ kiri ara]] ati ti tun tan kaa kiri omi ti o wa ninu awọn iṣan si awọn apo to wa lerefe.<ref>Anafilasisi, Author: Stephen F Kemp, MD, FACP; Chief Editor: Michael A Kaliner, MD;http://emedicine.medscape.com/article/135065-overview#showall</ref> Awọn aami miiran ni kikorajọpọ omi ninu awọn alafo ara, eosinofilia ninu ẹdọ-foo, ọkan ati awọn tisu, ati ẹri myokadial haipopafusion.<ref name=DaBroi/> Awọn iwadi imọ-ijinlẹ le ṣe awari ipele sẹrọmu ti o pọ si [[tryptase]], pipọsi ni akotan ati ipele sẹrọmu IgE ni pato.<ref name=DaBroi>{{cite journal|last=Da Broi|first=U|coauthors=Moreschi, C|title=Post-mortem diagnosis of anafilasisi: A difficult task in forensic medicine.|journal=Forensic Science International|date=2011 Jan 30|volume=204|issue=1-3|pages=1–5|pmid=20684869|doi=10.1016/j.forsciint.2010.04.039}}</ref>
==Didena==
A gba ni niyanju lati yẹra fun okunfa anafilasisi.<!-- <ref name=World11/> --> Ni awọn ipo ti eyi ko ti ṣee ṣe, didin bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ku tabi mimu kuro le jẹ eyiti a yan.<!-- <ref name=World11/> --> [[Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni]] pẹlu awọn oro [[Hymenoptera]] jẹ eyiti o f’ẹsẹ mulẹ lati dinku tabi mimu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ninu 80–90% awọn agbalagba ati 98% ninu awọn ọmọde l’odi si awọn nkan ti ara korira [[oyin]], [[agbọn]], [[ agbọn]], [[yelojakẹti]], ati [[tana tana]].<!-- <ref name=World11/> --> Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni lati ẹnu le munadoko lati dinku tabi mu kuro bi ara ṣe nṣiṣẹ lodi si nkan ninu awọn eniyan si awọn ounjẹ kan ti o ninu wara-olomi, ẹyin, ẹpa; ṣugbọn awọn nkan ti ko dara si wọpọ.<!-- <ref name=World11/> --> Ọna abojuto to nlo ajẹsara ara ẹni tun ṣee ṣe fun awọn abojuto ti o pọ, ṣugbọn a gba ọpọ eniyan nimọran lati saa yẹra fun nkan ti o nṣe okunfa naa.<!-- <ref name=World11/> --> Fun awon ti ara won nsise l’odi si oje, o le ṣe pataki lati yẹra fun awọn ounjẹ to nfa ṣiṣe iṣẹ lodi bi pia, ọgede, potato laarin ọpọ ounjẹ miiran.<ref name=World11/>
 
==Iṣakoso==