In-Young Ahn: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
k corr using AWB
Ìlà 17:
| rr = An Inyeong}}
}}
'''In-Young Ahn''' jẹ́ onímọ̀ ìjínlẹ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè South Korea. Ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Korea tí ó maa kọ́kọ́ dé [[Antárktìkà|Antarctica,]], ó sì jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ Asia tí ó maa ṣe olórí ibùdó Antarctic (King Sejong Station).<ref><cite class="citation web">[http://www.abc.net.au/news/2015-05-05/women-scientists-in-antarctica-report-sexual-harassment/6443570 "Stories of sexual harassment against women in Antarctica highlight issue in science industry"]. </cite></ref><ref name=":0"><cite class="citation web">[https://womeninpolarsciencedotorg.files.wordpress.com/2015/12/womeninpolarscience-issueii.pdf "Newsletter Issue II"] (PDF). ''womeninpolarscience.org''. </cite></ref><ref><cite class="citation web">[http://www.abc.net.au/foreign/content/2015/s4230123.htm "Southern Exposure"]. </cite></ref> Ó jẹ́ onímọ̀ ìbáṣepọ̀ oun ẹlẹ́mì ìsàlẹ̀ omi àti agègbè wọn, ó sì ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bíi ọ̀gá onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ìwádí fún Korea Polar Research Institute.<ref name=":2"><cite class="citation web">[http://www.abc.net.au/foreign/content/2015/s4230123.htm "Antarctica – Southern Exposure"]. ''abc.net.au''. </cite></ref><ref name=":1"><cite class="citation web">[http://eng.kopri.re.kr/www/about/kopri_brochure/annual_report_2015_eng.pdf "Annual Report"] (PDF). ''eng.kopri.re.kr''. </cite></ref>
 
== Ìgbà èwe àti ẹ̀kọ́ ==