Fásitì Odùduwà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àfikún àwon ìtóka sí
k corr using AWB
Ìlà 1:
 
{{Infobox University|name=Oduduwa University|native_name=OUI|image_name=|image_size=|caption=Oduduwa University|motto=Learning for human development|established=2009|type=Private|chancellor=Dr. [[Rahmon Adedoyin]]|vice_chancellor=Prof. Chibuzo Nnate Nwoke|faculty=|staff=|students=|city=[[Ipetumodu]]|state=[[Osun State]]|country=[[Nigeria]]|campus=[[Ipetumodu]]|former_names=|website=http://www.oduduwauniversity.edu.ng/}}Fásitì Odùduwà jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ àdáni tí wọ̀n dá sílẹ̀ ní ọdún 2009. Iké-ẹ̀kọ́ náà wà ní Ilé-Ifẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun. Àwọn olùgbé Ilé-Ifẹ̀ tó iye bí ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọọ́ta, ọgọ́rùún méjì ólé mọ́kàndínláàdọ́ta àti àti mọ́kàndínlọ́gọ́eùún ènìyàn (50,000-249,999). Àjọ (NUC) tí ó ń rí sí ìgbòkè-gbodò ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ fásitì nílẹ̀ Nàìjíríà fòntẹ̀ má báṣẹ́ rẹ lọ oẹ̀lú ẹ̀rí tó yanarantí tí wọ́n sì to ilé-ẹ̀kọ́ náà sí ipò kẹrìnlélọ́gọ́rùún (104) láàrín àwọn ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ikẹ̀ Nàìjíríà, nígbà tí ó wà ní ipò ẹgbẹ̀rún kan ólé ọgọ́rùn mẹ́fà àti mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n (10617) ní àwùjọ ilé-ẹ̀kọ́ àgbáyé. Fáfitì Odùduwà ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn ní ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ jákè-jádò àgbọ́ọ̀n-gbẹ ìmọ̀ lóeíṣiríṣi.Oduduwa.
Fásitì Odùduwà fìdí kalẹ̀ sí ìlú [[Ipetumodu|Ìpetumodù]], [[Ilé-Ifẹ̀|Ilé-Ifẹ̀,]], [[ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun]].<ref name="Ranking & Review 2019">{{cite web | title=Oduduwa University | website=Ranking & Review | date=2019-05-08 | url=https://www.4icu.org/reviews/13972.htm | access-date=2019-06-02}}</ref> Wọ́n forí ilé-èkọ́ náà sọ orí baba ńlá àwọn Yorùbá tí ó ń jẹ́ [[Odùduwà]].
 
== Àwọn ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ ibẹ̀ ==