Anastasios George Leventis: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Created by translating the page "Anastasios George Leventis"
 
k corr using AWB
 
Ìlà 21:
A lè tọpasẹ̀ ìran rẹ̀ padà sí ọ̀rùndún kejìdínlógún (28th century). Nígbà tí baba ńlá rẹ̀ ṣàtìpó lọ sí Peloponnese gẹ́gẹ́ bí ìtàn 'Olov' ṣe gbe ní 1770. Nígbà tí wọ́n fẹ́ bi, ọ̀pọ̀ àwọn Biṣọ́ọ̀bù tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ lábẹ́  ilé ìjọsìn Othodox ti Jerusálẹ́mù àti  Antioch, àti àwọn alàgbà ilé ìjọsìn as  Cyprus.
 
Wọ́n bi ní oṣù Kejìlá ọdún 1902  ní ìlú Lemythou, ní orílẹ̀ èdè Cyprus . Bàbá àti ìyá rẹ̀ ni : Neoklis/Papaneoklis Leventis àti  Salome Theocharides, ó ní ọ̀pọ̀lọpọ àwọn ẹ̀gbọ́n àti àbúrò lọ́kùnri àti lóbìnri, lára wọn ni: Costas; George, ẹni tí ó kọ́kọ́ lọ sí ilẹ̀ Íjípítì; Kalliopi, tí wọ́n pè oùn náà gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó gbé eré Alki David; Evagoras; Katerina, tí ó sì tún fẹ́ ọ̀gbẹ́ni  Myrianthousis; Charalambos; Anastasios; Christodoulos; àtiDavid.
 
Lẹ́vẹ́ntíìsì fẹ́ Maria Fotini, lẹ́ni tí ó bí ọọmọ kan ṣoṣo fun  ìyẹn Papadopoulos Leventis.
 
Bákan náà ni ó tún jẹ́ àbúrò bàbá fún Constantine (Dino) Leventis (1938–2002), olùṣòwò tí ó jẹ ànfàní lọ́pọọ̀ nínú àwòrán Hellenic art ní (Metropolitan Museum of Art in New York) àti àwọn ilé ìṣura ohun àbáláyé káàkiri àgbáyé. Ní April 2000, ilé ìṣura Metropolitan ṣí àjọ A.G. Leventis ìyẹn (Foundation Gallery) níbi tí ọ̀pọ̀ ihun ìṣura àbáláyé bí ère Cypriot, terracottas, vases, jewelry àti coins tí a lè tọpasẹ̀ rẹ̀ padà sí ọ̀rùndún kẹrin àti ọ̀rùndún karùún ṣájú kí wọ́n tó bí Jésù . Àjọ náà tún ṣèrànwọ́ nípa sísan owó fún àwọn ihun ìṣura ti ó jẹ mọ́ ilẹ̀ Gíríkì , Louvre ní ilẹ̀  Paris àti ilé ìṣura  Fitzwilliam tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ àgbà Cambridge University, àti àwọn mìíràn gẹ́gẹ́ bí ìjábọ̀ ọdọdún wọn ti wí. Ní ilẹ̀ Greece, àjọ náà ti náwó lọ́pọ̀lọpọ̀ sórí iṣẹ́ akíọ́lọ́jì tó pọ̀brẹpẹtẹ. 
 
== Àwọn ìtọ́ka sí ==