Lawrence Anini: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
k corr using AWB
Ìlà 21:
== BÍ wọ́n ṣe mú Aníní ==
Lẹ́yìn ò rẹ̣yìn Superintendent Káyọ̀dé Uanreroro ló ṣakin, ó sì fi wa egbò dẹ́kun sí ìwà ìṣẹ̀rùbàlú Aníní àti àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀. Ọ̀gá ọlọ́pàá yì mú ògbóntagì ọlọ́ṣ̀a yìí ní December 3, 1986, ní ojúlé kẹrìndínlógún òpópónà Oyemwosa, tí ó dojú kọ ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀r̀ẹ Iguodala, Bìní. Anini ni o wa pelu awon obinrin mefa. Awon olopaa ya wo inu ile ti Anini fi se ibuba naa latari ofofo ti awon aladuugbo se fun awon olopaa. Oga olopaa naa lo mu Anini pelu iko awon olopaa mewa pere.
Oga olopaa naa lo kan ilekun iyara ti Anini wa ti oun naa si si lekun woorowo leni ti o wo pata nikan. Won mu Anini sikun ti oun naa ko si bawon janpata pupo, sugbon ohun ti a gbo ni wipe ore-binrin re kan lowo si bi awon olopaa se ri mu. Obinrin naa ti ba awon ogun ati awon nkan agbara re kan je saaju ki awon olopaa to de. N se ni oro naa dabi ti Samsoni inu bibeli ni. Iyalenu lo je fun Anini fun ra re bi won se ba lojiji, ti oun naa si fe da bi ogbon nigba ti won beere lowo re ibi ti Anini wa, oni: "Ahh, o ti sa pamo si abe ibusun ni iyara keji"  bi o se so bayi tan o gbiyanju lati koja lara oga olopaa naa, sugbon iyen da lowo ko nigba ti o kan oga olopaa naa ni igbo, amo asise nla gbaa ni fun. Uanrenroro sare fi ese te atanpako ese re mole, o fa ibon yo o si ro bajinatu si ni koko-se . Anini gbiyanju lati bo mo won lowo sgbon awon olopaa toku mu so bi eran ti won si n yin ibon fun ni kose-kose debi wipe kokose re ohun fere ja kuro lara re latari ojo ibon ti o baa nibe. Anini kee tirora tirora, awon olopaa tun wa beere lowo re wipe : " Se iwo ni Anini?" oun naa wa fesi wipe : "Wo omo iya mi, mi o ni tan e, mi o si ni paro fun e,emi ni Anini.
 
Lati ibi ni won ti mu lo si ile agbara awon olopaa ni bi ti apase awon olopaa pata pata ti n duro lati fidi ododo re mule pe looto ni won ri Anini mu. fu asiko ti Anini fi wa ni ahamo awon olopaa, ede adamodi geesi ni o fi n soro tori ko lo si ile-iwe kankan. Bayii ni o bere si ni tu awon asiri kan fun awon olopaa nipa awon ise laabi ti oun ati awon iko re ti seyin, o tun fidi re mule wipe igbakeji re Osunbo lo yinbon fun Oga awon olopaa ipinle naa tele iyen Akagbosu
Ìlà 34:
 
== Ìgbẹ́jọ́ àti ìsájọ́ iḱú Aníní ==
Wọ́ln gbe Anini de ile ejo lori aga aro latari ese re ti won ba ge kuro titi won fi pari igbejo re. Ogbeni Iyamu ni tire, o jiyan wipe oun ko mo Annini ri debi wipe oun yoo ba dowo po, amo Anini ko jale wipe iro ni Iyamu n pa o si bu iyamu wipe: 'Opuro alailojuti ni o' . Bee ni Anini jeri takoo niwaju adajo James Omo-Agege ni ile ejo to ga julo ti o wa ni Sapele ni igboro Bini, iyamu ati awon olopaa mwa ti Anini ko ba ni ile ejo naa ran lo soru are-mabo.
 
Sugbon nigba ti won n se idajo yi, adajo Omo-Agege fidi re mule wipe "Anini yoo di eni male gbagbe ti won ba n soro iwa odaran ni orile ede yii, sugbon yoo je iranti to buru julo. Mo si mo wipe perete tabi ki a ma ri eni ti yoo fun omo re ni iru Anini yii. Ojo kokandinlogbon, osu keta odun 1987 (March 29,1987) ni won fi eyin won ti agba.