Ṣalanga oniho: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
No edit summary
k corr using AWB
Ìlà 5:
 
<!-- Construction and emptying-->
Ṣalanga oniho lapapọ ni ipa mẹta Pataki: iho ninu ilẹ, okuta pẹlẹbẹ tabi ilẹ ti o ni iho diẹ, ati ile lori.<ref name="Till2014" /> Iho yii jẹ o kere ni pataki 3&nbsp;mita (10&nbsp;iwọn ẹsẹ) jijin ati 1 m (3.2 iwọn ẹsẹ) nibu.<ref name="Till2014" /> [[Ajọ Ilera Agbaye]] bọwọlu ki wọn kọ ni iwọn ti o jinna diẹ sile ti yoo funni ni irorun ibẹwo ati oorun.<ref name=WHO3.4/> Jijina lati [[omi ilẹ]] ati [[omi orile]] gbọdọ tobi to eyi ti yoo din ewo eeri ku . Iho inu okuta ko gbọdọ tobi ju 25 sẹntimita (9.8 inṣi) lati majẹ ki awọn ọmọde ṣubu sinu rẹ.<!-- <ref name=WHO3.4/> --> Ina ko gbọdọ wọnu rẹ lati din awọn kokoro ku ni wiwọ inu rẹ.<!-- <ref name=WHO3.4/> --> Eyi le nilo lilo ohun kan lati bo ori iho ori ilẹ nigba ti wọn ko balo.<ref name=WHO3.4>{{cite web|title=Ṣalanga oniho to rọrun (iwe ijẹri 3.4)|url=http://helid.digicollection.org/en/d/Js13461e/3.4.html|website=who.int|date=1996|accessdate=15 August 2014}}</ref> Nigba ti ṣalanga ba kun de 0.05 mita (1.6 iwọn ẹsẹ) lori, a gbọdọ ko tabi ki a kọ omiran ki a gbe ile rẹ kuro tabi tunkọ si ibi titun.<ref name="VIP2003">{{cite book|author1=François Brikké|title=Linking technology choice with operation and maintenance in the context of community water supply and sanitation Siso aayo tẹkinọloji pẹlu ilo ati itọju ni akoonu ti ipese omi ilu ati imọtoto|deeti=2003|publisher=Ajọ Ilera Agbaye|isbn=9241562153|page=108|url=http://whqlibdoc.who.int/publications/2003/9241562153.pdf}}</ref> Ibojuto yiyọ [[ohun ibori]] lori ṣalanga lera. Ewu awujọ ati ilera wa bi a kobaṣe daradara.
 
<!-- Improvements -->