Ìgbéyàwó: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 10:
 
==Àwọn Ìgbésẹ̀ Àṣà Ìgbéyàwó Láyé Àtijọ́==
'''Ìfojúsóde:''' Èyí ni ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ tí àwọn òbí ọmọkùnrin tó bá ti bàlágà máa ń gbé láti ṣe àwárí omidan tó bá yáyì tí wọ́n yóò fi ṣaya fún ọmọ wọn. Láyé àtijó, ọmọkùnrin kì í kọnu sí omidan tó bá wù ú. Lẹ́yìn tí àwọn òbí bá ti fojúsódefojú sóde, tí wọ́n sì ti rí omidan tí wọ́n fẹ́ kí ọmọkùnrin wọn fẹ́ ní ìyàwó, ìgbésẹ̀ tó kàn ní ìwádìí
'''Ìwádìí:''' Èyí ni ìgbésẹ̀ kejì nínú àṣà ìgbéyàwó nílẹ̀ Yorùbá láyé àtijó. Ẹbí ọkùnrin yóò ṣe ìwádìí ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ nípa ọlọ́mọge tí wọ́n tí yàn láàyò láti fẹ́ fún ọmọkùnrin wọn. Wọ́n máa ń ṣe ìwádìí irú ìdílé tí omidan náà tí wá. Ṣé ìdílé tó dára ní tàbí tí kò dára, wọ́n a se
 
== Àwọn Ìtọ́kasí ==